Timothy Adegoke court case: Raheem, ọmọ Adedoyin ló pàṣẹ pé kí ń tún ìwé mii kọ- Adeniyi

Aderogba, ẹni ọdun marundilogoji ní ọmọ oloye Ramon Adedoyin ti o jẹ Roheem Adedoyin ni o pa a lase fun oun lati tun iwe account miiran ko.
O tesiwaju lati sọ fun Adajo Adepele Ojo pe awọn olopaa ipinlẹ Osun fi agidi mo oun lati gba ohun lenu oun ati pe pẹlu agídí ni oun fi ti owo bo iwe àkọsílẹ̀ fun Ile ise olopaa.
Aderogba tun so fun Ile ejo giga ipinle Osun pe oun pẹlu Oyetunde Kazeem ati Roheem Adedoyin lati gbe oku Timothy Adegoke lọ sí Ede road pẹlu oko funfun Lilux.Mi ò mọ nǹkan kan nípa 'receipt' ṣùgbọ́n èmi ní mó kó Ẹ̀dá ìwé account- Adeniyi Aderogba, ẹlẹ́rìí ẹjọ́ ikú Timothy Adegoke
"Magdalene Chiefuna ni o pe mi lẹyin tí ati gbinyanju lati pe alejo to wa ninu yara 305 tí ko si da wa lohun.
- Àwa mẹ́ta la gbé òkú Timothy Adegoke lọ sí Ede road- Ẹlẹ́rìí Oyetunde Kazeem
- Ọmọ ọdún 19 tí wọ́n sọ sí ẹ̀wọ̀n nitorí ọ̀kadà tó sọnù ti kú
- Gbajúmọ̀ Olórin Banky W ti rí tíkẹ̀ẹ̀tì ẹgbẹ́ òṣèlú PDP gbà láti díje dupò aṣòfin
- Ìjọba kéde òfin kónílé-ó-gbélé ní ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́sàn-án ní ìpínlẹ̀ Anambra
- Ọmọdé 19 ló pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ìṣekúpani ní iléẹ̀kọ́ alákọ̀bẹ́rẹ̀ Texas
- Mà á dá fijilanté sílẹ̀, òmìnira á wà fún ìjọba ìbílẹ̀ láti ná owó wọn- Oluwole Oluyede
- Gómìnà Anambra, Àjọ CAN, Àjọ Arewa bu ẹnu àtẹ́ lu obìnrin àti àwọn ọmọ rẹ̀ tí wọ́n ṣekúpa
O tun so pe: "Chiefuna ni oun ti rí eda kọkọrọ fun yara 305 tí òun si ba oku Timothy Adegoke ni o ri bedi to sun si, mo gbera lati lọ si ile ìtura naa lati woo nkan ti o sele.
"Emi pẹlu Magdalene Chiefuna lọ sí inu yara naa lati woo nkan ti o sele, orun naa poo gan tí mo si fi owo bo imu mi.
Ọkan lara awọn afurasi to jẹjọ lori iku Timothy Adegoke, Magdalene Chiefuna sọ fun Ile ẹjọ giga ipinlẹ Ọṣun pe otitọ ni awọn mulẹ lati maṣe sọ ọrọ lori iku Timothy Adegoke fun ẹnikẹni lẹyin iṣẹlẹ
naa.
Chiefuna, ẹni ọdun mẹ́rìnlélógún, akẹkọọ fasiti Ọbafẹmi Awolọwọ to tun jẹ ọkan lara awọn òṣìṣẹ́ ìle itura Hilton Hotel ni ilu Ile-Ifẹ lo fi idi ọrọ náà mulẹ nigbati o dahun ibere lati ọwọ agbejoro Fẹmi Falana.
Ó ni idi ti awọn fi múlẹ lati ma sọ fún ẹni kankan ni làti dabo bo ilé itura Hilton hotel.
Òtítọ́ ni pé a mùlẹ̀ láti má sọ fún ẹnì kankan- Magdalene Chiefuna, òṣìṣẹ́ Hilton Hotel jẹ́wọ́ nílé ẹjọ́
"Ojo keje osu konkanla ọdún 2021 ni a mùlẹ̀ láti má sọ̀rọ̀ lori iku Timothy Adegoke fun eni kankan
Òtítọ́ ni pé a mùlẹ̀ láti má sọ fún ẹnì kankan- Magdalene Chiefuna, òṣìṣẹ́ Hilton Hotel jẹ́wọ́ nílé ẹjọ́
"ìdi tí a fi mulẹ naa ni lati dabo bo eto ọrọ aje Hilton Hotel sugbon kin ṣe láti ma ba ọlọpa sọ̀rọ̀.
"Ọjọ́ konkanla oṣù kọkànlá ọdún 2021, wọn pé fun ipade nile Alamojuto ilé itura tí ó sì gbe iwe pe wọn tí gbe wa kuro ni lle itura lọ sí ọgbà fasiti alaga fun Ile ìtura naa."
Ipàdé wáyé láàárín àwa àti Aláṣẹ Hilton Hotel
Síwájú, Chiefuna salaye bi o se gba isẹ lọwọ Arábìnrin Adesola Adedeji àti bí o ṣe s'alabapade oku Timothy Adegoke nínu yara.
O ni oun Arabinrin Adesola Adedeji sọ fun oun pe awọn alejo meji sì wa ninu ilé itura naa ti o si fun oun ni kọkọrọ awon yara naa.
O ni oun gbiyanju lati kan yara 305, tí oun si kan ilẹkun sugbọn alejo naa kọ lati sì ilẹkun náà
"Ọjọ́ kẹfà oṣù konkanla ọdún 2021 ni mo wọ iṣẹ tí Adesola Adedeji si fun mi ni àwọn kọkọrọ àti pe awọn alejo kan si wa ninu yara méjì.
"Mo gbìyànjú lati kan sì yara naa sugbọn ẹni kankan o ja simi, mo ranse pe ọ̀gá wa to wa pẹlu mi ni ẹnu iṣẹ, Adeniyi Aderogba pe mo ri alejo to wa ninu yara 305.
"Aderogba gbera lọ sí be sugbon ko si iyato.
"Ọjọ́ keji to jẹ ọjọ́ keje oṣù konkanla ọdún 2021, mo ransẹ pe ẹni tọ mojuto spare house wá pe ṣe kọkọrọ mìíran tí a le fi sì ilẹkun yara 305 torí pe amọ boya alejo wa ninu yara ati pe wọn fẹ ṣe itoju sì ninu yara
naa.

"Ko pẹ ni ẹni tó ń mojuto spare house naa mu kọkọrọ de tí mo si kọja sì oke níbi tí yara naa wa ti mo sì fi kọkọrọ tí mo gba lọwọ alamojuto spare house si ilẹkun"
"Bí mo ṣe wọlé ní oorun bi ẹja pademi, lẹyin naa ni mo rí laptop ati ọwọ lori tabili.
"Mo ri òkú Timothy Adegoke pẹlu asọ duvet tí o bo lati ọrun si ẹsẹ rẹ. Mo gba l'ẹsẹ ṣùgbọ́n kò dami lohun.
"Mo ransẹ pe manager mi Adeniyi Aderogba pe ki wọn wa wo alejo ti o wa ni yara 305."
Agbejoro Femi Falana wa bere lọwọ arabinrin naa boya o fi ọrọ naa to awọn tó n sọ ilé itura létí, tí o sì ni rara".
Agbẹjọro Fẹmi Falana wa ni ẹjọ naa yi o tẹsiwaju.
Adajọ Adepele Ojo wa sun ipẹjọ naa si ọjo kerindinlọgbọn oṣù karùn-ún ọdun 2022.
Irọ ni pé ẹ̀jẹ̀ n da ninu Timothy Adegoke - Ẹlẹ́rìí

Oríṣun àwòrán, others
Mo kọ lati gba nnkan ti awọn akẹgbẹ mi sọ, ko si nnkan to jọ pe ẹjẹ n da lati inu wa
Ojogbon Olusegun Ojo, onimọ nipa ẹyẹ ara lati ile eko giga fasiti Obafemi Awolowo University teaching hospital ni esi ayẹwo ara ti wọn akẹgbẹ oun se lori iku Timothy Adegoke ni ko waye laito, ti oun si
keyin si oun ti wọn gbẹ jade ati pe ko si nnkan to jọ pe ẹjẹ n da lati inu wa.
Ojogbon Ojo naa pẹlu Dokita Akin Komolafe ni ayẹwo wọn yato esi ayẹwo awọn dokita mẹfa to ṣe ayẹwo ara Timothy Adegoke lẹyin tí wọn gbẹ oku rẹ ni Ede road niluu ile ife.
- Inú ọ̀sẹ̀ yìí ló yẹ kí ìyàwó mi bímọ kí wọ́n tó dá ẹ̀mí rẹ̀ légbodò - àlàyé rèé lẹ́nu ọkọ aláboyún tí àwọn agbébọn ṣekúpa ní Anambra
- Wọ́n lẹ̀dí àpòpọ̀ mọ́ mi ni mo ṣe fìdí rẹmi níbi ètò ìdìbò abẹ́nú – Dino Melaye
- EFCC ṣàlàyé ìdí tó fi fípa wọ́lé mú Rochas Okorocha lẹ́yìn tí wọ́n rọ̀jò ìbọn nílé rẹ̀ l'Abuja
- Lẹ́yìn idojúkọ ASUU, LAUTECH kéde pé kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọlé wa parí sáà ètò ẹ̀kọ́ tó bẹ̀rẹ̀ tẹ́lẹ̀
- MC Oluomo, òpin ti débá gbígba owó orí lọ́wọ́ àwọn awakọ̀ ní Eko - Iléẹjọ́
- Afurasí 4,000 la fi ṣìkùn òfin mú láàrín ọṣù márùn ún- Amotekun Ondo
Esi ayẹwo tí Dokita Wa Oluogun pẹlu Ojogbon E.A.O Afolayan fi sita pẹlu awọn dokita mẹrin miiran ni o fi han pe ẹjẹ da lati inu wa ati ọpọlọpọ egungun tí ó kàn tí ó le fa ikú Timothy Adegoke.
Ojogbon Ojo so fun Ile ejo pe oun sin bere lọwọ Egbon Ologbe Olùgbàde Adegoke bi ó sele fi ẹsẹ da oku Timothy mọ níbi tí wọn tí wù òkú naa síta nítorí ese lasan o idanomo.
"Ko si nnkan to jọ pe ẹjẹ n da lati inu wa niluu iwadi wa ti mio o sì pẹlu awọn dokita akẹgbẹ mi."
"Koda gbogbo awon eye ara ologbe Timothy Adegoke ti o pe ṣùgbọ́n a kẹfin pe awọn ẹyẹ ara naa ti ni ilera olojopipe ti o ologbe tọ kú.
Agbẹjọ́rò Agba Femi Falana wa bere lọwọ Ojogbon Olusegun Ojo boya esi ayẹwo rẹ pẹlu Akin Komolafe sọ nnkan to sọ okúnfa iku Timothy Adegoke.
Ojogbon Ojo ni ayẹwo naa o fi han iru iku to pa ologbe Timothy Adegoke sugbon opo lára àwọn iwadi awọn akẹgbẹ ohun ni o kẹyin sì.
"Òkú Timothy Adegoke ni ko ni àpẹẹrẹ pe wọn fi ọwọ ìjà kan ṣùgbọ́n ikú tio le pa arákùnrin Timothy Adégòkè ni ó le jẹ́ ikú àìsàn.
- Kò sí ààyè fawọn ọdaràn tó ń ṣiṣẹ́ ibi mọ́ ní ìpínlẹ̀ Anambra- Gómìnà Soludo
- Ta ni Anamekwe Nwabuoku tí ìjọba yàn láti delé sí ipò olùṣirò owó àgbà ní Nàìjíríà (AGF)?
- Wo ohun tó yẹ kóò mọ̀ nípa aàrùn 'Monkeypox' tó gbòde kàn ní àgbáyé
- Ẹgbé òsèlú méje darapọ̀ mọ́ ẹgbé òṣèlú Labour Party fún Ètò ìdìbò Ààrẹ
- Àwọn ọmọ bíbí Arewa ní àwọn ọlọ́kada láti orílẹ̀-èdè míràn ló ń dáràn nípínlẹ̀ Eko
- A kò ní sinmi títí tí àlááfíà yóò fi padà sí Naìjíríà- Buhari
- Ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn Aiye méjìdínlógún kò sí pámpẹ́ ọlópàá Ekiti lórí ikú èèyàn méjì
Wo awon ohun to n ṣẹlẹ ni ìgbẹ́jọ́ lórí ikú Timothy Adegoke ń tẹ̀síwájú nílùú Osogbo
Agbejoro Femi Falana yóò léwájú àwọn agbẹjọ́rò ìjọba àti mọ̀lẹ́bí Adegoke
Awon Agbejoro Olùpẹ̀jọ́ Femi Falana M.O Omashun A.A Adegoke Fatima Adeshina Femi Akinyemi
Awon Agbẹjọ́rò olùjẹ̀jọ́ First Defendant
K.K Eleja Williams Ajayi Adewole ọlá irẹIbrahim AlabidunA.O Olajide
Kunle Adegoke 2nd 4th 5th defendants
Ipoola binuyo Odunayo Henry Muideen Adeoye GO OludayoHasana AbdullahiRoland Otaoo 3rd 6th
OO Olabode Okon Edet itah 7th
Agbejoro Femi Falana yóò léwájú àwọn agbẹjọ́rò ìjọba àti mọ̀lẹ́bí Adegoke
Igbejo lori iku arakunrin Timothy Adegoke, akẹkọọ fasiti Obafemi Awolowo ni o tesiwaju ni oni ojo kẹẹdọgbọn oṣu karun-un leyin ti agbejoro agba Femi Falana ni siwaju fun awọn agbejoro fun ijọba ati
Molebi Adegoke.
Adajo Adepele Ojo sun ojo naa ni ojo kẹẹdọgbọn oṣu kẹrin nitori àìlera oókan lara awon afurasi naa.Agbejoro Agba Rasheed Murtala ni o be ile ejo lati fun ọkan lara awon afurasi naa ni anfani lati lọ gba itoju lẹyin tio ni ipenija ilera nínú ilé ejò.
- Wo ohun tó yẹ kóò mọ̀ nípa aàrùn 'Monkeypox' tó gbòde kàn ní àgbáyé
- Gbajúmọ̀ Olórin Banky W ti rí tíkẹ̀ẹ̀tì ẹgbẹ́ òṣèlú PDP gbà láti díje dupò aṣòfin
- Ta ni Anamekwe Nwabuoku tí ìjọba yàn láti delé sí ipò olùṣirò owó àgbà ní Nàìjíríà (AGF)?
- Ẹgbé òsèlú méje darapọ̀ mọ́ ẹgbé òṣèlú Labour Party fún Ètò ìdìbò Ààrẹ
- Kò sí ààyè fawọn ọdaràn tó ń ṣiṣẹ́ ibi mọ́ ní ìpínlẹ̀ Anambra- Gómìnà Soludo
- EFCC ká Rochas Okorocha mọ́lé, wọ́n ní kó sẹ́bí rẹ̀ tí yóò jáde bí àwọn kò bá mú u
- Gbajúmọ̀ Olórin Banky W ti rí tíkẹ̀ẹ̀tì ẹgbẹ́ òṣèlú PDP gbà láti díje dupò aṣòfin
- Kò sí ààyè fawọn ọdaràn alaburu ní ìpínlẹ̀ Anambra- Gómìnà Soludo
Lẹyin ẹbẹ naa ni awọn agbejoro fun awọn afurasi méjèèje so fun Adajo Adepele Ojo pe awon lílọ asiko lati se iwadi pẹlu awọn olubara wọn
Adajo Adepele Ojo wa sun ipejo naa si oni, ti o si ro awọn agbejoro naa lati fi asiko sofo ninu igbinyanju ile ejo lati fi otito han awọn ọmọ orile-ede Naijiria.
Ninu ifiorowero BBC News Yoruba pelu Agbejoro Agba Femi Falana, ni ile ejo giga ipinle Osun nio ni igbagbọ pe owa fun idajo ododo labe isakoso Adajo Adepele Ojo."Adajo Adepele Ojo ni mo mọ pe a ṣẹ ejo naa dáadáa, tí a si ri idajo ododo naa mu jade."
- Wo nkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa 'BBC Yoruba Ekiti Governorship Debate' tí yóò wáyé lọ̀sẹ̀ yìí
- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní iṣẹ ti bẹ̀rẹ̀ láti dóòlà ẹ̀mí Alùfáà tí wọ́n jígbé ní Ondo
- EFCC ká Rochas Okorocha mọ́lé, wọ́n ní kó sẹ́bí rẹ̀ tí yóò jáde bí àwọn kò bá mú u
- Àwọn Jàǹdùkú kọlù alága àjọ tó ń ṣètò eré ìdárayá ní ìpínlẹ̀ Oyo
- Jurgen Klopp tọwọ́ bọ̀wé àdéhùn tuntun pẹ̀lú Liverpool di 2026
- A kò fi ti gbèdéke June 1 ṣe, a ti fòfin de ọ̀kadà, kèké ní Eko
- "₦20,000 ló kàn mí lẹ́yìn tí a ja Iléeṣẹ́ rédíò Yinka Ayefele lólè ní Ibadan"
- Mo ti ṣetán láti gba ìjọba lọ́wọ́ Makinde lọ́dún 2023 - Adebayo Adelabu
Ti aba gbagbe, Arákùnrin Timothy Adegoke ni o jẹ akẹkọọ oípò kejì ní ile ẹkọ giga fasiti Obafemi Awolowo, Ile Ifẹ to ku sí ile ìtura Hilton.
Ramon Adedoyin tó ni ile ìtura Hilton, Ilé Ifẹ̀ àti àwọn afurasí mẹfa miiran n lo n ò Júù ẹsùn sínsin òkú Timothy Adegoke lọ́nà àìtọ́.Orúkọ àwọn afurasi yioku ni Adedeji Adesola, Magdalene Chiefuna, Adeniyi Aderogba, Oluwale Lawrence, Oyetunde Kazeem àti Adebayo Kunle.

Oríṣun àwòrán, others
























