PDP Primaries 2023: Banky Wellington jáwé olúborí láti díje ṣojú Eti Osa nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin ni Eko

Oríṣun àwòrán, @BankyW
Gbajúmò Ọlọ́rin Banky W Gbà Ticket Ègbé òsèlú PDP nínú ètò ìdìbò abele
Ilumoọka olorin ni, Olubankole Wellington, tí aye mo gege bí Banky W ni ẹgbẹ oselu PDP ti kede pẹ o jawe olubori ninu eto ìdibo abele to kọja.
O ti gab tikẹẹti lati soju ijọba ibile Eti Osa ni ile igbimo asofin kekere orile-ede Naijiria ninu eto ìdibo ọdún 2023.
Banky W ni borí pelu ibo mejidinlogbon ninu ibo mokanlelogbon ti wọn di ni ijoba ibile Eti Osa ni Ipinlẹ Eko.
Alamojuto eto ìdibo abele naa, Ayodele Kazeem ẹni to kede esi ìdibo abele naa, ni eto ìdibo naa lọ ni alafia pẹlu suuru.
- Ta ni Anamekwe Nwabuoku tí ìjọba yàn láti delé sí ipò olùṣirò owó àgbà ní Nàìjíríà (AGF)?
- Ẹgbé òṣèlú PDP kédé èsÌ ètò ìdìbò abẹ́lé tó wáyé ni ìpínlè Ọ̀yọ́
- Wo ohun tó yẹ kóò mọ̀ nípa aàrùn 'Monkeypox' tó gbòde kàn ní àgbáyé
- Ẹgbé òsèlú méje darapọ̀ mọ́ ẹgbé òṣèlú Labour Party fún Ètò ìdìbò Ààrẹ
- Wo nkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa 'BBC Yoruba Ekiti Governorship Debate' tí yóò wáyé lọ̀sẹ̀ yìí
- Àwọn ọmọ bíbí Arewa ní àwọn ọlọ́kada láti orílẹ̀-èdè míràn ló ń dáràn nípínlẹ̀ Eko
- A kò ní sinmi títí tí àlááfíà yóò fi padà sí Naìjíríà- Buhari
- Àwọn Jàǹdùkú kọlù alága àjọ tó ń ṣètò eré ìdárayá ní ìpínlẹ̀ Oyo
Kini ọrọ Banky W lẹyin to jawe olubori?
Banky W wa ni bi oun se bori ninu eto ìdibo abele naa je nkan ti olorun ati awọn eeyan ìjọba etí osa nife si pupo ti inu oun si dun lati soju ẹgbẹ oselu PDP ninu ìdíbo ọdun 2023.
"Inu mi dun pupo si awọn ọmọ ẹgbẹ oselu PDP àti gbogbo ijọba Eti Osa ṣe gbaruku timi ninu eto ìdibo abele PDP."
Banky W, ni afikun ni irinajo oun lati ṣe ohun gidi fun ijọba Eti Osa ṣẹṣẹ bere ni, ti oun o si ifowosowopo pelu awon ara agbegbe naa lati je isẹ naa.
O ni pe: "Eto ìdibo abele ní oun akoko sugbon ìṣe wa si tesiwaju pẹlu Ase Edumare "
Ogbeni Olubankole Wellington ni yoo koju ọmọ minisita fun eto aabo nigba kan rí, Babajide Obanikoro ti ẹgbẹ oselu APC ba yan bi ọmọ oye ẹgbẹ naa fun ìdibo ọdún 2023.

Oríṣun àwòrán, others
Ẹgbẹ oselu PDP ti kede awọn to jeweelubori ninu eto ìdibo abele fun ilẹ igbimọ asọfin agba, kekerẹ ati awọn asoju fún ilẹ̀ igbimọ ìjọba ibile.
Ẹgbé òṣèlú PDP kédé èsÌ ètò ìdìbò abẹ́lé tó wáyé ni ìpínlè Ọ̀yọ́
Ẹgbẹ́ òṣèlú PDP yàn Aṣojú fún ilẹ̀ ìgbìmọ̀ aṣòfin àgba, kékeré àti aṣòfin ìpínlè
Eto ìdibo abele naa waye ni ojo kejilelogun ati ojo ketalelogun oṣu karùn-ún ọdun 2023 nibi ti awọn ọmọ ẹgbẹ oselu naa ti ni afani lati yan ẹni tí aṣoju fun ẹgbẹ oselu naa ninu eto ìdibo ọdun 2023.
Ọpọlọpọ awọn amugbalegbe Gomina Ipinle Oyo lọ borí ninu eto ìdibo abele naa.
Abẹnusọ fun ilẹ igbimọ aṣọfin ipinlẹ Oyo, Rt Debo Ogundoyin, ninu ọrọ ti sọ síta fun awọn ololufẹ ẹgbẹ oselu PDP ni oun dupẹ lọwọ gomina Seyi Makinde fun bi eto ìdibo abele naa se lọ ní alafia.
"Awọn ọmọ ẹgbẹ oselu PDP dupẹ lọwọ gomina Seyi Makinde ati awon agba ẹgbẹ oselu PDP fun bi eto ìdibo abele ṣe lọ ní afani."
- Wo ohun tó yẹ kóò mọ̀ nípa aàrùn 'Monkeypox' tó gbòde kàn ní àgbáyé
- Inú Nnamdi Kanu kò dùn sí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìṣekúpani tó ń wáyé ní Anambra - Agbẹjọ́rò Kanu
- Ẹgbé òsèlú méje darapọ̀ mọ́ ẹgbé òṣèlú Labour Party fún Ètò ìdìbò Ààrẹ
- Wo nkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa 'BBC Yoruba Ekiti Governorship Debate' tí yóò wáyé lọ̀sẹ̀ yìí
- Àwọn ọmọ bíbí Arewa ní àwọn ọlọ́kada láti orílẹ̀-èdè míràn ló ń dáràn nípínlẹ̀ Eko
- 'Panel Beater' méjì ya odi òjijì lẹ́yìn tí alága ẹgbẹ́ mọkáláìkì tẹ́lẹ̀ gbá wọn l'étí ní Eko
- Èmi ò lọ́wọ́ sí ẹ̀sùn ìkówójẹ N80 bílíọ̀nù tí Idris Ahmed olùṣírò owó àgbà kó jẹ o- Zainab Ahmed mínísítà ìṣúná Nàìjíríà
- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní iṣẹ ti bẹ̀rẹ̀ láti dóòlà ẹ̀mí Alùfáà tí wọ́n jígbé ní Ondo
Wọ awọn olujide fun ẹgbẹ oselu PDP fun eto ìdibo ọdun 2023
Ile Igbimo Asofin Agba
Akinwale Solomon Akinwole, ilẹ igbimọ aṣọfin agba fun Ariwa ipinle Oyo
Oloye Luqman Oyebisi Ilaka, ilẹ igbimọ aṣọfin agba fun aarin gbogbo ipinlẹ Oyo
Mogaji Olasunkanmi Joseph Tegbe, ilẹ igbimọ aṣọfin agba fun guusu ipinlẹ Oyo
Ile Igbimo Asofin kekere
Guusu ibadan Federal Constituency - Lanre Sarumi
Oluyole Federal Constituency - Majeed Mogbojunbola
Akinyele Lagelu Federal Constituency - Abideen Adeaga
Irepo, Oorelope, Olorunsogo Federal Constituency - Hussaini Yusuf Ijabah
Ila- Oorun Saki àti ila -Oorun, Atisbo Federal Constituency - Dr Lukman Adisa Salami
Guusu Orun ati Ariwa Orun Ibadan- Hon Abass Adigun Agboworin
- Taliban gbé òfin kalẹ̀ lórí àwọn Obìnrin atọ́kùn ètò, bó ojú rẹ tóo bá fẹ́ ka ìròyìn bí bẹ́ẹ̀ kọ́.....
- Ẹran màálù N328 bilionu ni àwọn ará Eko ń jẹ ní àárín ọdún kan- ìjọba
- 'Panel Beater' méjì ya odi òjijì lẹ́yìn tí alága ẹgbẹ́ mọkáláìkì tẹ́lẹ̀ gbá wọn l'étí ní Eko
- Ìwà aṣemáṣe gbaṣẹ́ lọ́wọ́ dókítà àti nọ́ọ̀sì ní ìpínlẹ̀ Oyo
- Anthony Albanese di olóòtú ìjọba Australia, ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa rẹ̀ rèé
- Ta ló gbé òkú ènìyàn sí pápákọ̀ òfurufú Muritala Muhammed l'Ekoo? FAAN bẹ̀rẹ̀ ìwádìí
- Àwọn alákatakítí ẹ̀sìn dáná sun ilé mẹ́fà, ṣọ́ọ̀bù méje ní Bauchi lórí ẹ̀sùn sísọ̀rọ̀ òdì sí Islam
- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá nawọ́ gán afurasí mẹ́fà lórí ikú "Sound Engineer"
Iseyin, Itesiwaju, Kajola, Iwajowa Federal Constituency - Oyejide Oyesina
Ariwa ìwọ oorun ati Guusu ìwọ oorun Ibadan Federal Constituency - Hon Stanley Olajide Odidi Omo
Ariwa, Guusu ati Oriire Ogbomoso Federal Constituency - Olufemi Onireti
Ido, ila oorun IbarapaFederal Constituency - Hon Yemi Taiwo
Egbada, Ona Ara Federal Constituency - Hon Busari Olayemi
Ariwa, Aarin gbogbo Ibarapa Federal Constituency - Dr Adepoju Anthony
Ogo Oluwa, Surulere Federal Constituency - Ojo Sunday Makanjuola
Ila Oorun, ìwọ oorun Oyo ati Atiba Federal Constituency - Mudashiru Kamil Akinlabi




















