LAUTECH calls off strike for resumption: Fásitì LAUTECH ṣétan láti ṣe ìpàdé pẹ̀lú ASUU- Agbẹnusọ Lekan Fadeyi

Oríṣun àwòrán, others
Ile eko giga Fasiti Ladoke Akintola nio kede ìwọle ṣaa tuntun fun awọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olukọ tí ó bẹrẹ ni ojobo, ojo kerindinlogbon ọdun 2022.
Akowe Agba ilé eko naa, Kayode Ogunleye ni o fi oro naa síta fun awọn akoroyin ti o si awọn akẹkọọ àti olukọ ni iyanju lati wọle saa tuntun naa.
Ṣugbọn, ẹgbẹ olukọ ile ẹkọ giga fasiti, ASUU ti Ile eko giga naa ti ni awon ọmọ ẹgbẹ naa o setan lati wọle fun saa tuntun naa.
- EFCC ká Rochas Okorocha mọ́lé, wọ́n ní kó sẹ́bí rẹ̀ tí yóò jáde bí àwọn kò bá mú u
- Afurasí 4,000 la fi ṣìkùn òfin mú láàrín ọṣù márùn ún- Amotekun Ondo
- Kò sí ààyè fawọn ọdaràn alaburu ní ìpínlẹ̀ Anambra- Gómìnà Soludo
- Ta ni Anamekwe Nwabuoku tí ìjọba yàn láti delé sí ipò olùṣirò owó àgbà ní Nàìjíríà (AGF)?
- Gbajúmọ̀ Olórin Banky W ti rí tíkẹ̀ẹ̀tì ẹgbẹ́ òṣèlú PDP gbà láti díje dupò aṣòfin
- Wo ohun tó yẹ kóò mọ̀ nípa aàrùn 'Monkeypox' tó gbòde kàn ní àgbáyé

Oríṣun àwòrán, others
Alaga ẹgbẹ olukọ ile ẹkọ giga fasiti, ASUU ni lautech, Ojogbon Biodun Olaniran nio fèsì sì oro naa ni atesita kan.
Olaniyan ni ase lati òkè ni iyanselodi tí awọn oluko jule tí awọn ọmọ ẹgbẹ naa o sì setan ìwọle.
- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní iṣẹ ti bẹ̀rẹ̀ láti dóòlà ẹ̀mí Alùfáà tí wọ́n jígbé ní Ondo
- Ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn Aiye méjìdínlógún kò sí pámpẹ́ ọlópàá Ekiti lórí ikú èèyàn méjì
- Ọlọ́pàá ìpínlẹ Ogun mú olùkọ́ tó fipá bá akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ ọdún mẹ́sàn-án lòpọ̀
- Buhari yọ ikọ̀ D'Tiger, D'Tigress kúrò nídíje bọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ lágbáyé fún ọdún méjì, ohun tó fàá nìyí
- Afurasí 4,000 la fi ṣìkùn òfin mú láàrín ọṣù márùn ún- Amotekun Ondo
- Kò sí ààyè fawọn ọdaràn tó ń ṣiṣẹ́ ibi mọ́ ní ìpínlẹ̀ Anambra- Gómìnà Soludo
Nígbà ti ilé iṣẹ BBC NEWS YORUBA kan sí alukoro Fasiti naa Lekan Fadeyi lori ase fasiti naa, o ni ase naa o yí padà.
Fadeyi ni ile eko giga Fasiti naa ti ṣétan lati se Ipadẹ pẹlu awọn ẹgbẹ olukọ ile ẹkọ giga Fasiti, ASUU lati mọ ọna abayo lori eto iyanselodi naa.
"Ile eko giga Fasiti Ladoke Akintola o koyan ẹgbẹ olukọ ile ẹkọ giga fasiti, ASUU kere ní a fi ṣe tan lati ba wọn ṣe Ipadẹ lo













