Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, KO ṢEE MA GBỌ Ọ
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Published

Ki lo de ti awọn ọlọpaa tun fẹ fi tipa tikuuku gbe gbajumọ ẹlẹsin abalaye ni, Tani Olohun niluu Ibadan?

Ẹmi o mọ o, lọjọ wo niyẹn?

Awọn ọlọpaa kan ni wọn yawọ ile ọkunrin naa laarọ oni, ti wọn si lawọn yoo gbe e lọ si agọ awọn.

Wọn ni Tani Olohun ni ẹjọ lati jẹ nipinlẹ Kwara lori bo ṣe n tako ẹsin Islam ni gbogbo igba

Ki lo wa ṣẹlẹ?

****************************************************************************************

Awọn mọlẹbi Fusengbuwa ti ipo ọba Awujale kan nilẹ Ijebu gbe ijọba ipinlẹ Ogun lọ silẹ ẹjọ.

Ẹbi Fuengbuwa lawọn fẹ ki ile-ẹjọ paṣẹ lati jẹ kawọn Afọbajẹ bẹrẹ eto yiyan ọba pada

Bẹẹ ni wọn sọ pe ijọba ipinlẹ Ogun ko lẹtọọ labẹ ofin lati da eto yiyan ọba duro

Awọn wo lo tun wa ninu iwe ipẹjọ naa?

Sare lọ soju opo BBC.COM/Yoruba ni bayii.

*****************************************************************************************

O ma ṣe o!

Gbajugbaja agba akewi asunjala nni, Oloye Alabi Ogundepo jade laye

Alabi Ogundepo jade laye lẹyin aisan ranpẹ lẹni ọdun mẹrinlelọgọrin

Bi o ba fẹẹ mọ ẹkunrẹrẹ