Timothy Adegoke: Lẹ́yìn oṣù mẹ́ta, ìdájọ́ yìí ń pẹ́ lójú wa- Iya Timothy Adegoke
Leyin isinku oloogbe Timothy Adegoke to waye lọjọ Abamẹta to kọja ni ilu Eruwa ni ipinlẹ Oyo ni BBC ba ebi ati agbejoro oloogbe naa sọrọ.Musulumi àti Kristẹni lo ṣe àdúrà níbi ètò ìsìnkú Timothy Adegoke lónìí
Agbejoro Nahim Adekilekun salaye ibi ti igbejo naa de duro fun BBC pe ọwọ ọlọpaa ti tẹ awọn afurasi mẹfa bayii.
- Osun la fẹ́ kí ìgbẹ́jọ́ ikú Timothy Adegoke ti wáyé, kìí ṣe Abuja - Mọ̀lẹ́bí yarí
- Deji Akure tó lu aya rẹ̀ lójú títì, tí wọn rọ̀ lóyé, ti jáde láyé
- Èèyàn méjì dèrò ọ̀run nínú ìkọlù ọlọ́pàá àtàwọn afurasí akẹ́kọ̀ọ́ ẹlẹ́gbẹ́ òkùnkùn Kwara Poly
- Òkú kú ní ẹ̀ẹ̀kejì nígbà tí òkú 400 jóná ráúráú ní mọ́ṣúárì, ẹbí bú sẹ́kún lẹ́ẹ̀kejì
- Àwọn ọmọbìnrin oníwọ́kuwọ́ ló mú kí ń yẹ̀bá nídìí iṣẹ́ tíátà
- Bí ayẹyẹ ìsìnkú Alao Akala yóò ṣe lọ rèé
- Àwùjọ àgbáyé, ẹ ṣèrànwọ́ fún Burkina Faso kó le borí ìṣòro - Olórí ìjọba ológun
Agbejoro Nahim salaye idi to fi dabi pe igbẹjọ naa n falẹ nitori iru iku to pa oloogbe Timothy.
O ni ipinlẹ Osun ti iṣẹlẹ naa ti ṣẹlẹ naa ni igbejo ye ko ti waye gẹgẹ bi ofin Naijiria ṣe laa kalẹ.
Aya, Iya, ẹgbọn, aburo ati ara oloogbe Timothy Adegoke naa ba BBC sọrọ lori ohun ti wọn n fẹ bayii lẹyin isinku Timothy Adegoke ni Eruwa.
- Èèyàn méjì dèrò ọ̀run nínú ìkọlù ọlọ́pàá àtàwọn afurasí akẹ́kọ̀ọ́ ẹlẹ́gbẹ́ òkùnkùn Kwara Poly
- Àwọn ọmọbìnrin oníwọ́kuwọ́ ló mú kí ń yẹ̀bá nídìí iṣẹ́ tíátà
- "Á lọ yíká gbogbo ilẹ̀ Yorùbá láti bèèrè fún ìdáǹdè Sunday Igboho"
- Tiyín lẹ ṣe o, àwa kò gbà èsì ìdìbò abẹ́nú PDP l‘Ekiti - Segun Oni
- Àlàyé rèé lórí ìròyìn tó ní Buhari ti kú, Jubril Sudan ló ń darí Nàíjíríà
- Iléeṣẹ́ ìròyìn BBC ṣe ìfilọ́lẹ̀ àmì ẹ̀yẹ Komla Dumor
- Afenifere ń gbèrò láti dá ẹgbẹ́ òṣèlú sílẹ̀, àgbà Yoòbá kan ní àbùkù ni yóò gbẹ̀yìn rẹ̀