Global University Ranking:: Wo àwọn Fasiti Nàìjíríà tó gbégbá orókè lágbàyé

Global University Ranking:

Oríṣun àwòrán, others

Ile ẹkọ fasiti ilu Ibadan,UI,Covenant University ati fasiti Obafemi Awolowo ni ile Ife,OAU ni wọn ti kede gẹgẹ bi awọn fasiti to munadoko julọ ni Naijiria.

Ninu atupalẹ akasọ awọn ile ẹkọ fasiti ti Webometrics gbe jade ni a ti ri bawọn fasiti wọn yi ati awọn mii ti ṣe pegede si ni Naijiria ati lagbaye.

Atupalẹ taa n wi yi, ko safihan fasiti Naijiria kankan ninu awọn fasiti ẹgbẹrun kan akọkọ to pegede julọ lagbaye.

Fasiti UI to le tente ni Naijiria la gbọ pe o wa ni ipo 1,196 labaye.

Fasiti aladani Covenant Univerity to se ipo keji ni Naijiria wa ni ipo 1,314 nigba ti OAU to se ipo kẹta ni Naijiria wa ni ipo 1,503 lagbaye.

Fawọn akẹkọọ fasiti Naijiria ta mọ si University of Nigeria ati fasiti ilu Eko,UNILAG wọn wa ni ipo kẹrin ati ikarun ni Naijiria.

Àkọlé fídíò, Thyroid foundation: eéwo ni mo kọ́ka pè é àṣé gẹ̀gẹ̀ ọrùn tó lé ẹbí, ará àti ọ̀rẹ́ ni mo n

Akasọ igbelewọn awọn fasiti lagbaye taa mọ si Ranking Web tabi Webometrics yi ni o tobi julọ lagbaye nipa lilo awọn asunwọn kan lati fi sọ ipo ti fasiti wa lagbaye.

Lopju opo ayelujara wọn, ohun ti wọn sọ ni pe ''awọn gbe igbelewọn ati akasọ fasiti lelẹ lagbaye lati le jẹ ki awọn fasiti ṣe paṣiparọ imọ sayẹnsi ati aṣa jakejado agbaye.''

Lati le fi se aṣeyọri pẹlu afojusun yi, gbigbe orukọ awọn fasiti to le tente yi jẹ irinṣẹ lati le fi mu iyipada ba kikẹkọ lawọn fasiti ti eyi yoo si mualekun ba ifarajin awọn olukọni''

Àkọlé fídíò, Badagry: Ojú ọ̀nà àrèmabọ̀ fáwọn ẹrú tó ń lọ sókè òkun

Ni meni meji, atupalẹ awọn fasiti Naijiria ati ipo ti onikaluku wa ree labẹ yi:

Ipo fasiti lagbaye; Ipo ti fasiti naa ti ko ipa to pọju, Bí awọn eeyan ṣe tẹwọ gba fasiti kọọkan si

Fasiti alakọkọ ni:

11,196

University of Ibadan

2628

837

1364

21314

Covenant University Ota

3823

1109

1192

31503

Obafemi Awolowo University

2228

1326

2020

Àkọlé fídíò, Senato francis Fadahunsi: Ká ni wọ́n fún Buhari ladún mẹ́wàá sẹ́ypin ní, bóyá kò bá rí i ṣ

41554

University of Nigeria

3816

881

1839

5

1711

University of Lagos

3873

1204

2053

62102

University of Port Harcourt

1886

1626

3615

72127

Ahmadu Bello University

6296

1486

2182

82172

Federal University of Technology Akure

7979

1355

1989

92298

Landmark University

4420

2070

2807

10

2748

Àkọlé fídíò, Eegunjobi Omotanbaje Ajobiewe- Èébú ní wọ́n kọ́kọ́ ń bù mí nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ ẹ̀ṣà pípé ní

Federal University of Technology Minna

7597

1573

3173

11

2805

Bayero University Kano

9658

1891

2690

12

2848

Ladoke Akintola University of Technology

9466

1430

3054

13

2878

University of Calabar

8908

1184

3416

14

2919

University of Benin

7428

1456

3694

15

2947

Adekunle Ajasin University

2223

3276

4559

16

3018

Àkọlé fídíò, Ohun ti Yorùbá ń pè ní Èṣù yàtọ̀ sí Sátánì nítorí Èṣù ní iṣẹ́ rere lọ́wọ́

Ekiti State University Ado Ekiti (University of Ado Ekiti)

4305

2209

4391

17

3149

Olabisi Onabanjo University (Ogun State University)

5670

2550

4075

18

3167

University of Uyo

9937

1982

3331

19

3226

Àkọlé fídíò, Oba Ogboni Abalaye n fẹ́ kí wọ́n o má a fi ẹ̀sìn àbáláyé búra fún àwọn olóṣèlé Naijiria

Nnamdi Azikiwe University

9230

1350

3980

20

3331

Federal University of Technology Owerri

7375

1827

4341

21

3374

Lagos State University

9029

2281

3860

22

3438

University of Abuja

8874

2211

4041

23

3447

University of Jos

7785

2471

4187

24

3663

Redeemer's University

10772

2853

3764

25

3714

Àkọlé fídíò, Yoruba Nation: Mo faramọ́ àtúntò 'Restructuring' tí kò lọ́wọ́ ìṣèlú nínú- Oba Ahmed Adeku

Federal University Oye Ekiti Ekiti State

7702

2303

4700

26

3774

Federal University Dutse Jigawa State

13566

3506

3038

27

3902

University of Ilorin

5915

6492

2498

28

4104

Ebonyi State University

13377

3427

3801

29

4241

Osun State University

11381

2869

4700

30

4257

Federal University of Petroleum Resources Effurun

9047

4008

4700

31

4283

Delta State University Nigeria

11297

1810

5118

32

4334

University of Agriculture Abeokuta

6878

6492

3089

33

4368

Rivers State University of Science & Technology

1230

6492

5118

34

4911

Modibbo Adama University of Technology Yola (Federal University of Technology)

14377

3156

5051

35

5024

Federal University Lokoja Kogi State

3139

3506

6650

36

5054

Niger Delta University

13180

3816

5180

37

5189

Benue State University

11750

3792

5519

38

5244

Usmanu Danfodiyo University

11783

6492

3764

39

5274

University of Maiduguri

11091

6492

3980

40

5284

Imo State University Owerri

12215

5093

5118

41

5365

Abubakar Tafawa Balewa University

8223

6492

4700

42

5425

American University of Nigeria

9623

4573

5782

43

5439

African University of Science & Technology Abuja

13672

5327

4984

44

5561

Cross River State University of Science & Technology Calabar

13610

4290

5519

45

5671

Babcock University

9993

1866

6650

46

5772

Àkọlé fídíò, Nítorí kí aafa lè máa rí iṣẹ́ ṣe ní wọ́n kò ṣe kó Alumaajiri nílẹ̀ tó fi di ohun tó dà yìí

Kogi State University

14929

4385

5519

47

5791

Kwara State University

11109

6492

4762

485819

Federal University of Agriculture Makurdi

12677

3904

5973

49

5957

Enugu State University of Science & Technology

10861

4134

6216

50

6006

Federal University Ndufu Alike Ikwo FUNAI

11062

2438

6650

51

6095

Ambrose Alli University Ekpoma

10601

6492

5118

52

6179

National Open University of Nigeria

7812

6492

5519

53

6247

Federal University Kashere Gombe State

7750

4502

6650

54

6427

Nigerian Defence Academy Kaduna

10756

3573

6650

55

6443

Àkọlé fídíò, Unijos students victims: Àwọn Fulani yabo 'hostel' wa, ọpẹ́lọpẹ́ àwọn Sọ́jà tí gómìnà ìpí

Nasarawa State University

12596

4378

6216

56

6565

Federal University Dutsin Ma

12334

3031

6650

57

6597

Umaru Musa Yar'Adua University (Katsina State University)

10756

3844

6650

58

6850

Skyline University Nigeria

2711

6492

6650

59

7035

Southwestern University Oku Owa

3010

6492

6650

60

7095

Akwa Ibom State University of Technology

13316

3319

6650

61

7130

Kaduna State University

13121

3455

6650

62

7158

Edo University Iyamho

12930

3577

6650

63

7216

Chukwuemeka Odumegwu Ojukwu University (Anambra State University of Science & Technology Uli)

14287

2975

6650

64

7258

Igbinedion University Okada

10949

4527

6650

65

7306

University of Medical Sciences Ondo

13762

3363

6650

66

7451

Abia State University Uturu

13316

5093

6216

67

7468

Nile University of Nigeria (Nigerian Turkish Nile University Abuja)

13566

3632

6650

68

7503

Àkọlé fídíò, Ọlatunji, akẹ́kọ̀ọ́gboyè 'graduate' tó ń ta àkàrà 'Ó ta lẹ́nu' nílùú Osogbo

(3) Lagos State University College of Medicine

15414

2779

6650

69

7503

Bowen University

14618

3159

6650

70

7805

Baze University Kuchigoro

13030

4192

6650

71

7934

Federal University Otuoke Bayelsa

13061

4333

6650

72

8084

Ibrahim Badamasi Babangida University Lapai

14522

3856

6650

73

8162

Mountain Top University

13121

4498

6650

74

8310

Tai Solarin University of Education

12615

4771

6650

75

8399

Elizade University Ilara Mokin

14883

3985

6650

76

8474

Bells University of Technology Otta

14711

4109

6650

77

8593

Adeleke University Ede

14522

4282

6650

78

8739

(1) Kebbi State University of Science and Technology KSUSTA

17765

6492

5118

79

8764

Kano University of Science & Technology Wudil

13523

4754

6650

80

8792

Lead City University Ibadan

14452

4466

6650

81

8827

Lagos Business School Pan Atlantic University

8940

6030

6650

82

8921

Àkọlé fídíò, Babatunde Gbadamosi: Mo ta gbogbo dúkìá mi lásìkò kan kí ń tó padà di eèyàn lónìí

Federal University Lafia Nasarawa State

14496

4516

6650

83

8933

Pan African University Lagos

9039

6055

6650

84

9023

Federal University Wukari Taraba State

16758

3635

6650

85

10146

Benson Idahosa University

14252

5219

6650

86

10187

Technical University Ibadan

12539

5701

6650

87

10199

Gombe State University Gombe

16758

4414

6650

88

10686

Ajayi Crowther University Oyo

13163

5693

6650

89

10761

Edwin Clark University Kiagbodo

8187

6492

6650

90

10886

Bauchi State University Gadau

14618

5399

6650

91

10886

Godfrey Okoye University

12697

5891

6650

92

11135

Joseph Ayo Babalola University

14452

6492

5973

93

11927

Taraba State University Jalingo

14313

5814

6650

94

11987

Bingham University New Karu

13647

5990

6650

95

12182

Federal University Birnin Kebbi

15579

5598

6650

96

13095

Anchor University Lagos

16576

5632

6650

97

13239

Àkọlé fídíò, Ondo Jos clash: Èmi nìkan ló padà dé nínú àwa márùn ún tí a jọ lọ ìpàdé àdúrà ní Jos- Bell

Yobe State University (Bukar Abba Ibrahim University Damaturu)

15521

5943

6650

98

13588

Sule Lamido University

17004

5670

6650

99

14422

Caleb University

14496

6354

6650

100

14609

Augustine University Ilara Epe

18077

5756