Ekiti Bishop: Ìjọ Anglican pàṣẹ lọ rọọ́kún nílé fún Bíṣọ́ọ̀bù tó ń bá ìyàwó àlùfáà abẹ́ rẹ̀ sùn l'Ekiti

Oríṣun àwòrán, Newsdayng.com
Ijọ Anglican ni ipinlẹ Ekiti ti kọwe lọ ree gbe ile rẹ si Biṣọbu ijọ naa kan, Victor Adepoju lori ẹsun pe o ni ibalopọ pẹlu iyawo alufaa ẹgbẹ rẹ kan ninu agbegbe kan naa.
Biṣọbu Adepọju lo n ṣakoso daosisi ijọ naa to wa lẹkun Iwọ oorun Ekiti ni ipinlẹ naa.
- Wo ìjìyà tó wà fún àwọn ọmọ Naijiria tí kò bá fi nọ́mbà NIN kún ìforúkọsílẹ̀ Siimu wọn láàrin ọ̀sẹ̀ méjì
- Ìyàwó mi fi mí sílẹ̀ kó lọ sílé ọkùnrin míì nínú báráàkì kan náà, àmọ́ mò sí tún fẹ́ràn rẹ̀- Sọ́jà
- Ààrẹ àná, Goodluck Jonathan ló fún mi ní 'oògùn' tí mo fi yọ Sanusi nípò Emir Kano- Ganduje
- Wo àwọn ìṣesí ojoojúmọ́ mẹ́wàá tó le ṣàkóbá fún ọpọlọ rẹ
Gẹgẹ bi lẹta ti awọn ileeṣẹ iroyin abẹle kan ni wọn kọ ṣọwọ si Biṣọọbu naa lati fi pe ko lọ rọọkun nile,
Wọn ni Biṣọọbu Adepọju "jẹwọ pe lootọ loun ba iyawo alufaa to wa labẹ oun sun"
Bisọọbu yii lo n dari ijọ Anglican to wa ni Iwọ oorun Ekiti ni
Amọṣa, Biṣọbu Adepọju ko tii sọrọ kankan lori iṣẹlẹ yii.
- Coronavirus: ''Ìjọba kò tíì pàṣẹ ìlànà ìtakété-síra-ẹni padà nínú BRT la ò ṣe máa tẹ̀le''
- Ìjọba gbé ilé ijó oníhòhò tì pa lórí ẹ̀sùn títàpá sí ìlànà àti dẹ́kun coronavirus
- Ogun abẹ́lé tó ń ja Akeredolu l'Ondo, òní la ó mọ̀ bóyá yó borí rẹ̀
- Èyí ni bí èèyàn 538 ṣe ń yan ààrẹ lé èèyàn mílíọ̀nù 331 ní Amẹ́ríkà















