Nigeria government: Àpò òfìfo ni a bá nígbà tí a gbàjọba lọ́dún 2015, ṣùgbọ́n a ti ṣiṣẹ́ ribiribi- Ahmed Lawan

Oríṣun àwòrán, @Ahmed
Àpò òfo ni ìjọba àná fi sílẹ̀ kó tó kúrò lórí àléfà - Ìjọba àpapọ̀
Lẹyin ọdun marun un ti ẹgbẹ oṣelu PDP ti kuro lori alefa ijọba Najiria, sibẹ ẹgbẹ oṣelu APC ṣi n di ẹru bi bi eto ọrọ aje ṣe dẹnu kọlẹ le ẹgbẹ naa lori.
Nigba to n sọrọ ni ọọfisi ẹgbẹ naa niluu Abuja, Aarẹ ile igbimọ asofin agba, Ahmad Lawan sọ pe apo ofo ni ijọba ana, labẹ Ọmọwe Goodluck Ebele Jonathan fi silẹ fun ijọba to wa lode.
- Kílódé tí Ọọni Ife, Oba Ogunwusi kò fi gbọdọ̀ rí ọmọ rẹ̀ tuntun ti Olorì Naomi bí títí di bíi ẹ̀yìn oṣù mẹ́fà?
- Omotara kan ìdin nínú iyọ̀, àwọn ọmọ ilẹ̀ Faranse náà bínú síi nítorí alágbe tó fi ṣe yẹ̀yẹ́.
- Ọ̀rọ̀ àsọkẹ́yìn Diego Maradona ìlúmọọká agbábọ́ọ̀lù rèé kó tó dágbére f'áyé
- Nàìjíríà fohùn ránṣẹ́ padà sílé aṣofin UK pé ọ̀rọ̀ EndSars kò sí lẹ́nú wọn láìgbọ́ ìwádìí tán!
Lawan nni Aarẹ Muhammadu Buhari n gbiyanju lati sọ eto ọrọ aje to ti n dẹnu kọlẹ ji, ṣugbon yoo gba akoko diẹ.
O ni "nigba ti gba ijọba lọdun 2015, lara ohun ti a jogun ba ni apo ofo ti ijọba ana fi silẹ fun wa."
"Ṣugbọn a dupẹ lọwọ Ọlorun pe Aarẹ Buhari jẹ ọlọpọlọ pipe ati ẹni to ni afojusun lati ri daju pe awọn eeyan ri tiwọn ṣe lorilẹ-ede yii."
Lawan ni bo tilẹ jẹ pe apo ofo ni awọn ba, ti owo epo si tun ti ja walẹ ju ti atẹyinwa lọ, awọn n lo iwọnba owo diẹ to wọle si apo ijọba lati tun ilu ṣe.
- Ó ti di ẹ̀ṣẹ̀ láti bẹ̀bẹ̀ fún afipábánilòpọ̀ nípìnlẹ̀ Ekiti- Ìjọba ìpínlẹ̀ Ekiti
- Ìbálòpọ̀ ọ̀lọ́jọ́ méje mú kí ilé ẹjọ́ tú ìgbéyàwó ọdún mẹ́wàá ká ní Ibadan
- Kílódé tí Ọọni Ife, Oba Ogunwusi kò fi gbọdọ̀ rí ọmọ rẹ̀ tuntun ti Olorì Naomi bí títí di bíi ẹ̀yìn oṣù mẹ́fà?
- Fatai Rolling Dollar, Ọmọ ìdílé oyè tó gbé igbá orin tí Ebenezer Obey ń ṣiṣẹ́ lábẹ́ rẹ̀!
- Kí lo mọ̀ nípa ìbẹta kan ṣoṣo tí Alaafin Oyo bí? Wọ́n pé ọdún méjìlá báyìí
Aarẹ ile aṣofin naa sọ pe ti eeyan ba ri adari to ni ọpọlọ pipe to si ni ifẹ awọn eeeyan rẹ lọkan, ohun kan to ku to yẹ ki iru ẹni bẹẹ ṣe ni pe ko fi ọwọ sowọpọ pẹlu rẹ lati ṣiṣẹ.
O ṣalaye pe Naijiria ti fi akoko kan pa owo gọbọi wọle ri ṣugbọn ko yọ lara awọn ara ilu.
O ni bayii ti owo to n wọle ko to nnkan, ijọba n ṣe awọn ohun amayedẹrun kaakiri Naijiria lati Guusu titi de Ariwa.
Lọsẹ to kọja ni ijọba apapọ kede pe ọrọ aje Naijiria ti gba rifaasi fun igba keji ni eyi to tun fi dẹnukọlẹ sii laarin ọdun merin.
Awọn onimọ nipa eto ọrọ aje ni ifasẹyin to de ba ọrọ aje yii ni eyii to buru julọ lati ọdun 1987.
- Nàìjíríà fohùn ránṣẹ́ padà sílé aṣofin UK pé ọ̀rọ̀ EndSars kò sí lẹ́nú wọn láìgbọ́ ìwádìí tán!
- Elon Musk, Ọ̀gá àgbà iléeṣẹ́ SpaceX, Tesla CEO ń bá Bill Gates du ipò ẹni tó lówó jùlọ ṣèkejì lágbayé
- Ganiyat tó fi irin gbígbóná àti àdá ya ara ọmọ àbúrò ọkọ rẹ ti dèrò àgọ́ ọlọ́pàá l' Ogun
- Ohun mẹ́wàá pàtàkì nípa Maradona àti ìbáṣepọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ẹlẹ́sẹ̀ ayò Diego Costa rèé
- Ọmọbìnrin tó tayọ nínú ìdànwó WAEC ọdún 2019 pẹ̀lú A1 méje ti kú

















