ASUU Strike: Ààrẹ Buhari pàrọwà sí ASUU láti padà sẹ́nu iṣẹ́ nítorí àwọn akẹ́kọ̀ọ́

Oríṣun àwòrán, Others
Íjọba ápápọ ni áwọn ti mu die ninu ádédun ódun 2009 sẹ
Ipadẹ ti o waye larin ijọba apapọ ati ẹgbẹ olukọ ile ẹkọ giga fasiti, ASUU ni ana ode yii ni o fi orisanpon lẹyin ti awọn ikọ mejẹẹji kuna lati se atunse lori orọ iyensẹlọdi ti wón gun lẹ.
Ijiroro naa ni Sultan ti ile Sokoto, Sa'ad Abubakar, Aarẹ fun awọn ọmọ lẹyin kristi, Dr. Supo Ayokunle, Olori oṣiṣẹ ile ijọba, Ọjọgbon Ibrahim Gambari ati Minisita fọrọ oṣiṣẹ, Chris Nigige se oludari fun ni wọn kuuna lati pẹtu si ọokan ẹgbẹ olukọ ile ẹkọ giga fasiti, ASUU lati dawo iyansẹlọdi naa duro nigbati orọ lori bi ijọba apapọ o sẹ mu ilẹri wọn wa si imuse ba tesiwaju.
- Wo àwọn iṣẹ́ méje tí o lè kọ́ láàrín oṣù mẹ́ta ti ASUU da iṣẹ́ sílẹ̀
- Ìdí mọ́kànlá nìyìí tí mo fi fẹ́ díje dupò ààrẹ ní Naijiria – Bukola Saraki
- Óṣe! ènìyàn kan kú ẹlòmíràn farapa bí ọkọ̀ ńlá ṣe jábọ́ léwọn lórí l'Eko
- Fí fún ẹkùn tàbí ẹ̀yà kan ní tíkẹ́ẹ̀tì 'zoning' kò sí nínú òfin ẹgbẹ́ wa - PDP
- Ààrẹ Buhari pàrọwà sí ASUU láti padà sẹ́nu iṣẹ́ nítorí àwọn akẹ́kọ̀ọ́
- Wo àwọn mínísítà ìjọba Nàìjíríà tó ti kọ̀wé fipò sílẹ̀ nítorí àṣẹ Ààrẹ Buhari
Kini o ṣẹlẹ ninu ipade naa?
Ipadẹ naa lo waye ni ilẹ ijọba ni iluu Abuja, ọpọlọpọ awọn ọmọ ẹgbẹ ASUU ni o wa ni ikalẹ ni bi ipadẹ naa.
Ninu ipade naa, ajo ASUU kuna lati pada si ẹnu ise ti wọn si fe tẹsiwaju iyenselodi naa lẹyin ti ijọba apapọ ati awọn adari eesin sẹ ileri pẹ ijọba ti sẹ tan lati mu ileri won wa si imusẹ.
MInIsIta fọrọ oṣiṣẹ, Chris Ngige ni ijọba apapọ ti gba lati mu adenu wọn pẹlu ajo ASUU wa si imusẹ, ti die ninu adenu naa yio si je sisẹ osẹ to n bọ.
Minisita naa ni, orọ lori adehun ọdun 2009 ati orọ owo oṣu wọn ni awọn yamju laipẹ ojọ.
" A ti fi ẹnu ko lori awọn adanu kan, ti a si ni igbagbo pe ni oṣe to n bọ yii o wam si mumuse. Awọn ifenuko wa ni o jẹ nnkan wuri fun ẹgbẹ olukọ ile ẹkọ giga fasiti, ASUU dawo duro iyansẹlọdi ti wọn gunlẹ."
Ọjọgbon Ibrahim Gambari ninu orọ rẹ rọ ẹgbẹ olukọ ile ẹkọ giga fasiti, ASUU lati jọ jare fọwọ wọnu fiye denu ki wọn ṣe suuru ki wọn pada sẹnu iṣẹ nitori awọn akẹkọọ.
Aarẹ ẹgbẹ olukọ ile ẹkọ giga fasiti, Ọjọgbon Emmanuel Osedeke ni o seni laanu pẹ ti awọn o ba yan iyansẹlọdi laayo, ijọba apapọ le pẹ awọn ẹgbẹ olukọ ile ẹkọ giga fasiti, ASUU si ijiroro lati yanju adehun to ye ko wa si mumu sẹ.
O ni pe: "Ọpọlọpọ isoro ni a lẹ yanju lai lo lori iyansẹlodi sugbon nnkan ti ba je pupo.
"Mo ni igbagbo pẹ isoro iyansẹlọdi ni nnkan ti a le yanju larin ojo meta."

Oríṣun àwòrán, Screenshot
Ààrẹ Buhari pàrọwà sí ASUU láti padà sẹ́nu iṣẹ́ nítorí àwọn akẹ́kọ̀ọ́
Aarẹ Muhammudu Buhari ti ra ọwọ ẹbẹ si ẹgbẹ Olukọ ile ẹkọ giga Fasiti, ASUU lati fi opin si iyansẹlọdi ti wọn ṣẹṣẹ fi oṣu mẹta kun.
Bakan naa lo rọ ẹgbẹ awọn akẹkọọ lati jọ jare fọwọ wọnu fiye denu ki wọn ṣe suuru ki awọn fi wa ojutuu si aawọ to n waye laaarin ijọba ati ASUU lori iyanṣẹlodi naa.
Buhari sọ eleyii nibi ayẹyẹ ọdun mọkandinlogun National Productivity ati Conferment of National Productivity Order of Merit to waye niluu Abuja.Ààrẹ Buhari pàrọwà sí ASUU láti padà sẹ́nu iṣẹ́ nítorí àwọn akẹ́kọ̀ọ́
- Fí fún ẹkùn tàbí ẹ̀yà kan ní tíkẹ́ẹ̀tì 'zoning' kò sí nínú òfin ẹgbẹ́ wa - PDP
- Wo àwọn mínísítà ìjọba Nàìjíríà tó ti kọ̀wé fipò sílẹ̀ nítorí àṣẹ Ààrẹ Buhari
- ASUU Strike 2022: Ìjíròrò lórí ìyanṣẹ́lódì ASUU ń tẹ̀síwájú lónìí pẹ̀lú ìjọba àpapọ̀
- Mọ̀ síi nípa IPOB tó ń gbé orí ayélujára dá rúgúdú sílẹ̀ nítorí ọ̀rọ̀ Biafra
- Kìí ṣe àwọn mínísítà tó fẹ́ dupò nìkan ní Buhari ní kó fi iṣẹ́ sílẹ̀ , wo àwọn tó tún kàn
- Ọ̀rọ̀ pátà dídọ̀tí tún rúná sí ìjà láàrin Nkechi Blessing àti ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ tẹ́lẹ̀, Falegan
O fi kun wi pe lati ọjọ kiini oṣu keji ọdun yii ni oun ti pa lasẹ fun olori oṣiṣẹ ile ijọba, Ọjọgbon Ibrahim Gambari, Minisita fọrọ oṣiṣẹ, Chris Nigige ati Minisita fọrọ eto ẹko, Adamu Adamu láti jiroro pẹlu ASUU lati fopin si iyanṣẹlodi gbogbo igba to n waye.
Lati ọjọ kẹrinla, oṣu keji, ọdun 2022 to n ṣe oṣu mẹta sẹyin ni ASUU ti bẹrẹ iyanṣẹlodi onikilọ, ki wọn to sọ ọ alaini gbendeke lọjọ Aje, ọjọ kẹsan-an, oṣu karun-un, ọdun 2022.
Lara ohun ti ASUU n beere fun ṣiṣe amuṣẹ adehun wọn pẹlu ijọba ti ọdun 2009.

Oríṣun àwòrán, Others
ASUU Strike 2022: Ìjíròrò lórí ìyanṣẹ́lódì ASUU ń tẹ̀síwájú lónìí pẹ̀lú ìjọba àpapọ̀
ASUU Strike 2022: Ìjíròrò lórí ìyànṣẹ́lódì ASUU ń tẹ̀síwájú lónìí pẹ̀lú ìjọba àpapọ̀
Lẹyin ti ẹgbẹ olukọ ile ẹkọ giga fasiti, ASUU kede afikun oṣu mẹta si iyansẹlodi, wọn yoo jiroro pẹlu ijọba apapo lonii lori bi iyanṣelodi naa o ṣe wa s'opin
Eleyii di mimo ninu atẹjade ti wọn fi sita lalẹ ọjọru fun awon akọroyin.
- Mọ̀ síi nípa IPOB tó ń gbé orí ayélujára dá rúgúdú sílẹ̀ nítorí ọ̀rọ̀ Biafra
- Èèyàn 60 l'erin ti pa láàrín ọdún yìí nìkan lórílẹ̀èdè Zimbabwe
- Kìí ṣe àwọn mínísítà tó fẹ́ dupò nìkan ní Buhari ní kó fi iṣẹ́ sílẹ̀ , wo àwọn tó tún kàn
- Ọ̀rọ̀ pátà dídọ̀tí tún rúná sí ìjà láàrin Nkechi Blessing àti ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ tẹ́lẹ̀, Falegan
- PDP wọ́gilé ìlànà jẹ kí n jẹ 'zoning' fún yíyan olùdíje ipò ààrẹ
- Àwọn olùfẹ̀hónúhàn dáná sun dúkìá bí ìwọ́de ṣe ń le si
- Ẹ múra o, ọ̀wọ́n gógó bẹntiró ń rúgbó bọ̀- IPMAN ṣèkìlọ̀ fún àwọn ọmọ Nàìjíríà
- Ọwọ́ tẹ afurasí ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn ní ilé ìtura, wo nǹkan tí ọlọ́pàá ká mọ lọ́wọ́
Ẹgbẹ naa ni oṣiṣẹ agba fun Aarẹ Muhammudu Buhari, Ọjọgbon Ibrahim Gambari pẹlu Minisita fọrọ oṣiṣẹ Chris Nigige ni wọn yoo dari ijiroro naa.
Ọpọlọpọ ipadẹ lo ti waye laarin ASUU ati ijọba lati igba ti iyanṣẹlodi onikilọ oṣu kan yii ti bẹrẹ ni ọjọ kẹrinla oṣu kejì, ọdun 2022.
Ipade toni ni o jẹ itẹsiwaju lori gbogbo awọn ifẹnuko wọn nibi ipade ti wọn ṣe ni ọjọ mẹta sẹyin.

Oríṣun àwòrán, @UI
ASUU fi oṣù mẹ́ta kún ìyanṣẹ́lódì wọn nítorí pé.......
Egbẹ Olukọ Fasiti Naijiria kọ lati wọgile iyanṣẹlodi wọn, wọn tun fi oṣu mẹta kun un
Aago mejila oru oni ọjọ Aje ni ẹgbẹ olukọ kede afikun ọsẹ mejila kun asiko iyanselodi wọn bayii.
Aarẹ ẹgbẹ Olukọ Fasiti ASUU, Emmanuel Asodeke to ṣe ikede yii ni Abuja ṣalaye pe ijọba Naijiria ko tii ṣetan lati fopin si iyanṣẹlodi naa.
Asodeke kede yii lẹyin ipade awọn igbimọ tẹẹkoto NEC wọn nile iya ẹgbé ASUU ni Fasiti Abuja.
O ni ijọba Naijiria kọ lati mu adehun wọn ti ọdun 2020 FGN/ASUU MOU ṣe.
- Ẹ má ṣe bẹ̀rù ọ̀rọ̀ Ẹ̀sìn tó gbalẹ̀ kan l'Ekiti, a ti f'òfin bọ ọ̀rọ̀ Pasito Ade Abraham - Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá Ekiti
- Ẹ gba ìpínlẹ̀ Eko kúrò lọ́wọ́ àwọn àjòjì - Atiku sí Bode George
- Ṣé ó ṣeéṣe kí ẹgbẹ́ ASUU fi òpín sí ìyànṣẹ́lódì rẹ̀ lọ́jọ́ Aje?
- Mo dúpẹ́ ó! Mo bẹ́ orí fún gbogbo àgbẹ̀ àti olùfọkànsìn tó ń dáwó fọ́ọ̀mù Ààrẹ fún mi àmọ́ ẹ jẹ́ n lo óògùn ara mi - Emefiele
- Torí oge ṣíṣe, wo obìnrin tó ṣe ìrìbọmi omi tútù àmọ́ tó já sí ikú fún u

Oríṣun àwòrán, Screenshot
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fásitì á bẹ̀rẹ̀ ìwọ́de ìfẹ̀hónú hàn nítorí ìyansẹ́lódí ASUU
Bí ìyanṣẹ́lódì tí ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga fásitì, ASUU gùnlé ṣe ń tẹ̀síwájú, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga ní ìpínlẹ̀ Imo, Kwara àti Eko ti ń gbèrò láti ṣe ìwọ́de ńlá láti fẹ̀hónú wọn hàn lórí ìyanṣẹ́lódì náà.
Gẹ́gẹ́ bí ìròyìn ṣe sọ, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fẹ́ gùnlé ìwọ́de oní àláfíà náà nítorí tí oṣù mẹ́ta ti pé tí ASUU ti bẹ̀rẹ̀ ìyanṣẹ́lódì, tí àwọn NASU náà sì ti kún wọn.
Bákan náà ni kò jọ wí pé ìyanṣẹ́lódì náà yóò wá sópin láìpẹ́ tí èyí sì ń kan àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lóminú.
- Ẹbí kan pàdánù ọmọ mẹsan-án nínú èèyàn 435 tí omiyalé pa
- Irọ́ ni pé Bola Tinubu fẹ́ kúrò ní ẹgbẹ́ òṣèlú APC- Agbẹnusọ Aṣíwájú
- Èsì ìdánwò UTME abala àkọ́kọ́ yóò jáde lọ́sẹ̀ yìí- Àjọ JAMB
- Ẹkún tún sọ ní Zamfara, àwọn agbébọn pa èèyàn 48
- Bí Jibrin ṣe kúrò ní ẹgbẹ̀ òṣèlú APC kò níi ṣe pẹ̀lú Bola Tinubu- Agbẹnusọ ìpolongo
- Kí nìdí táwọn iléeṣẹ́ bàlúù ní Nàìjíríà ṣe fẹ́ wọ́gilé ìrìnnà òfúrufú ní Nàìjíríà lọ́jọ́ Ajé?
- Wo ọ̀nà tí wọ́n ń pè ní "ọ̀nà ikú" tí àwọn ènìyàn ṣì ń ṣe ìrìnàjò lórí rẹ̀ síbẹ̀
Nínú àtẹ̀jáde kan tó gba orí ayélujára kan, ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ Kẹsàn-án, oṣù Karùn-ún, ọdún 2022 ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní ìpínlẹ̀ Eko yóò péjọ sí orítà ilé ẹ̀kọ́ gíga Fásitì ti ìjọba àpapọ̀ ní Yaba ní aago mẹ́jọ òwúrọ̀ fún ìfẹ̀hónúhàn ti wọn.
Ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga Fásitì ìlú Ilorin yóò péjọ sí ẹnu ọ̀nà ilé ẹ̀kọ́ náà fún ìwọ́de.
Ọjọ́rú ní àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ìpínlẹ̀ Imo fi ìwọ́de ti wọn sí.
Ní orí ẹ̀rọ ayélujára Twitter báyìí, igbe kí ìjọba àti ẹgbẹ́ ASUU wá wọ̀rọ̀kọ̀ fi ṣàdá lórí ìyanṣẹ́lódì náà ló gba orí rẹ̀ kan.
- Ẹ gba ìpínlẹ̀ Eko kúrò lọ́wọ́ àwọn àjòjì - Atiku sí Bode George
- Mo dúpẹ́ ó! Mo bẹ́ orí fún gbogbo àgbẹ̀ àti olùfọkànsìn tó ń dáwó fọ́ọ̀mù Ààrẹ fún mi àmọ́ ẹ jẹ́ n lo óògùn ara mi - Emefiele
- Ṣé ó ṣeéṣe kí ẹgbẹ́ ASUU fi òpín sí ìyànṣẹ́lódì rẹ̀ lọ́jọ́ Aje?
- Ẹ má ṣe bẹ̀rù ọ̀rọ̀ Ẹ̀sìn tó gbalẹ̀ kan l'Ekiti, a ti f'òfin bọ ọ̀rọ̀ Pasito Ade Abraham - Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá Ekiti
- Torí oge ṣíṣe, wo obìnrin tó ṣe ìrìbọmi omi tútù àmọ́ tó já sí ikú fún u
- Ikú d'óró! Wole Adetiran tó kọ orin àdákọ àgùnbánirọ̀ Naijiria 'NYSC Anthem' ti jáde láyé


















