Fuel Scarcity: Ẹ múra o, ọ̀wọ́n gógó bẹntiró ń rúgbó bọ̀- IPMAN ṣèkìlọ̀ fún àwọn ọmọ Nàìjíríà

Awọn alagbata epo aladani atawọn alagbata epo to da duro ti kẹdẹ pe ọwọn gọgọ epo bẹntiro ti tan kalẹ de ilu Abuja, pe yoo si buru ju ti tẹlẹ lọ.
Alaga ẹgbẹ awọn alagbata epo IPMAN ni ipinlẹ Kano, Bashir Danmalam lo sọ elẹyii fun awọn oniroyin lọjọ Aje niluu Abuja.
Danmalam ni nnkan to fa bi ọwọn gọgọ epo bẹntiro naa bi ajọ Nigerian Midstream and Downstream Petroleum Regulatory Authority ṣe kuna lati sanwo toto ẹẹgbẹgbẹta biliọnu naira fun awon ọmọ ẹgbẹ.
- Àwọn olùkọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga gbogbonìṣe Poly ní Nàìjíríà , ASUP fẹ́ bẹ́rẹ́ ìyanṣẹ́lódì, wo ohun tí yóò ṣẹlẹ̀
- Buhari pàṣẹ fún àwọn mínísítà tó bá fẹ́ dupò òṣèlú láti kọ̀wé fi iṣẹ́ sílẹ̀ ní kíá
- Genevieve Nnaji fi fídíò sí Instagram, lẹ́yìn wákàtí díẹ̀ tí ìròyìn sọ pé ó ní àrùn ọpọlọ
- Johnson Sulemann sọ̀rọ̀ sókè lórí ẹ̀sùn tí Stephanie Otobo fi kàn án
- Buhari kò ní fi oṣù mẹ́fà kún ìjọba rẹ̀ bí àwọn kan ṣe ń bèrè - Ìjọba àpapọ̀̀̀
- Wo àwọn tó ra fọ́ọ̀mù ipò Ààrẹ ẹgbẹ́ òṣèlú APC
Danmalam ni gbese naa ti le ọpọlọpọ ọmọ ẹgbẹ IPMAN kuro lẹnu iṣẹ wọn nitori wọn ni anfaani lati ṣe iṣe wọn tori ọwọn gọgọ epo disu.

"O ti le bi oṣu mẹjọ ti awọn ọmọ ẹgbẹ wa ko ni anfaani lati tesiwaju ninu ise wọn nitori gbese ti wọn jẹ wa ati bi epo disu ṣe gbowo lori."
Danmalam rọ ijọba Naijiria lati da sọrọ naa ko to di pe o tan kaakiri ipinlẹ yooku.
- Ṣé lóòtọ́ ni Jonathan ti gbẹ̀yìn darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ APC? Nkan tí PDP àti APC sọ rèé
- Kò sí akẹ́kọ̀ọ́ ìpínlẹ̀ Sokoto, Zamfara tí yóò ṣe ìdánwò WASSCE lọ́dún 2022
- Wo ìdí tí Ilé aṣòfin àpàpọ̀ Nàìjíríà ṣe yí òfin ìdìbò padà fún ààrẹ, gómìnà, àwọn aṣòfin àtàwọn míràn
- Ìdí mẹ́ta tí Goodluck Jonathan kò fi lè díje dupò lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú kankan lásìkò yìí
- Wo àwọn obìnrin mẹ́wàá tí ipa wọn kò ṣe fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn ní ààfin Oyo
- Olùkọ́ Chrisland College mẹ́rin fojú balé ẹjọ́ lórí ẹ̀sùn ìbálòpọ̀












