Bobrisky: Ayé lèmi fẹ́ jẹ kí n tó sọ̀rọ̀ ọ̀run, má ṣe wàhálà wàásù fún mi nípa ọ̀run

Oríṣun àwòrán, Bobrisky/facebook
Okunẹyẹ Idris Ọlanrewaju ti ọpọ eeyan mọ si Bobrisky, ti ke si gbogbo awọn to n waasu ijọba ọrun fun un pe ki wọn lọ simẹdọ nitoripe oun ti gboju kuro ni ohunkohun to nii ṣe pẹlu ọrun.
Ẹyin naa kọ haa!
Bobrisky ṣalaye lori awọn ikanni rẹ loju opo ayelujara pe, ki gbogbo awọn to n waasu fun oun pe ki oun yi igbe aye oun pada o lọ wa ọrọ mii sọ nitori pe lọwọ ti oun wa bayii, 'aye laa jẹ ka to ṣọrun' loun gbe dani o.
- Bobrisky sọ̀rọ̀ sókè lórí ìdí tí kò fi kópa nínú àwẹ̀ Ramadan tó ń lọ lọ́wọ́
- Ǹjẹ́ Bobrisky àti Mompha ń gbée síi fúnra wọn lóòtọ́? Ohun táa mọ̀ nìyí
- Kí ló wà láàrin Olorì Badra àti Bobrisky, tí ọ̀rọ̀ wọn fi wọ̀?
- Òntàjà góòlù wọ́ Bobrisky nìlẹ̀ pé ó ra góòlù àwìn tó wọ̀ lọ́jọ́ ìbí rẹ̀ láì san owó pé
- Mo fẹ́ di obinrin to dára júlọ lágbàyé-Bobrisky
- Ìdí tí wọ́n fi dá mi padà láti Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì - Bobrisky
- Bobrisky@30: Àpótí òní páálí láwọn àlejò yóò fí wọlé síbi àpéjẹ̀ Bobrisky
O ni ki wọn jẹ ki oun jẹ igbadun aye yii na ki wọn to maa sọrọ ọrun.

Oríṣun àwòrán, Facebook/Bobrisky
"Maa wulẹ damu ara rẹ lati waasu fun arabinrin yii, Emi ti yọ ọwọ mi kuro ninu ohun gbogbo to niiṣe pẹlu irinajo ọrun."
Eyi ni ohun ti Bobrisky kọ soju opo ayelujara Facebook rẹ pe aye loun kọkọ fẹ jẹ na o ki oun to maa sọrọ ọrun.
Ikede yii si lo jẹ iyalẹnu fun ọpọ awọ̀n ololufẹ Bobrisky, ti wọn si n tọr aforijin fun, ti ọpọ wọn si n tubọ waasu fun nipa ọrun rere.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Wo ọ̀nà tí obìnrin tó ti ní ìbálòpọ̀ tẹ́lẹ̀, ṣe le sọ ara rẹ̀ di ‘Virgin' lẹ́ẹ̀kejì
- Iyorchia Ayu dí Alágá ẹgbẹ́ òṣèlú PDP, àwọn ọmọ ìgbimọ̀ tó kù rè é
- Òjò owó àti ẹbùn ń rọ fún Iyabo Ojo fún ayẹyẹ ọdún kan ikú ìyà rẹ
- Ayẹyẹ ìwúyè Grand Mufti wáyé ní Iwo, ọ̀pọ̀ adarí ẹ̀sìn Islam péjú
- Ìdìbò abẹ́nú APC Oyo pàpà wáyé lẹ́yìn tí jàǹdùkú mú alága ìbò abẹ́nú nígbèkùn
- Agbébọn ṣe ń gba owò ilẹ̀ ní Ariwa, agbèrò ń gbà ní gúúsù, kò sí ìyàtọ̀ - Lai Muhammed
- Ìjíròrò tó wáyé láàrín Bola Tinubu àti Igbákejì ààrẹ Yemi Osinbajo, ohun tí a rí gbọ́ nípa rẹ̀ nìyí
- Kí ló mú ọkùnrin kan fi ejò Sèbé olóró pa aya rẹ̀ lójú oorun?
- Wo ọ̀nà tí o lè gbà borí àìsàn rọpá-rọṣẹ̀ tó ń pa ọ̀gọ̀rọ̀ lágbáyé












