Easter celebration: FRSC ń sisẹ́ papọ̀ pẹ̀lú iléesẹ́ ìpèsè isẹ́ òdé láti tún àwọn òpópónà Eko sí Ibadan se

Oríṣun àwòrán, @FRSC
Ajo ẹ̀sọ́ aabo FRSC ipinlẹ̀ Ogun àti Eko kede lati rii pe lilọ-bibọ loju marose Eko si Ibadan rọrùn lasiko ọdún Ajinde.
Ogbeni Olusegun Ogungbemide to n dari eso oju popo FRSC ni ipinle Eko ati Ogbeni Umar Ahmed to n dari FRSC ipinle Ogun ni won a jo fọwọsowọpọ̀ sise papọ̀ lasiko ọdun Ajinde yii.
Ninu atejade ti wọ́n jọ fọwọ́si ni ikede ipese aabo yii ti jade sita.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- A rí àwọn fọ́tò tó fihàn pé ọkọ Osinachi ní ìyàwó míràn sí ìkọ̀kọ̀ - Minisita ọrọ obinrin
- Seyi Makinde ti sọ Auxillary di nǹkan míì sígbòrò, ọlọ́pàá gbọdọ̀ mu - Olopoeyan
- Wo ẹ̀rọ ìgbàlódé tí o lé rì sínú ọwọ́ rẹ̀ láti má a san owó ọ̀jà láì lo káàdì ATM
- Ọ̀rọ̀ǹpọ̀tọ̀niyùn, obìnrin àkọ́kọ́ tí yóò jẹ́ Aláàfin, ẹni tó pààrọ̀ nǹkan obìnrin sí ti ọkùnrin
- Àṣírí ayédèrú ológun méjìlá tó ń gbégi dínà ní Ajah ati agbègbè míì tú sọ́wọ́ iléeṣẹ́ ológun
Kini ajo FRSC tun fẹ́ fi pese iranlọ́wọ́ fara ilu lasiko odun yii?
Agbenuso fun ajo FRSC, Ogbeni Olabisi Sonusi salaye pe igbesẹ̀ yii yoo jẹ́ ko rọrun fun awon arinrirnajo lati Eko si Ibadan lasiko ọdun Ajinde yii.
Bakan naa ni Olusegun Ogungbemide ati Ahmed Umar se ipade pelu awọn ọ́ga agba ileese ijọ́ba apapọ̀ to n risi isẹ́ òde.
Amojuero Adebote salaye pe ajo FRSC, won ti n tun awon opopona se ki irin awọn awakọ le lọ geere.
Olusegun Ogungbemide so pe o le ni ẹsọ́ aabo oju popo egberun meji ti wọ́n ti da sita pẹ̀lú ọkọ̀ metadinlogota ati alupopo mẹ́jọ ti wan yoo wa lopopona marose Eko si Ibadan.
- Àwọn ọlọ́pàá ti fi páńpẹ́ òfin gbé ọkọ olórin ẹ̀mí “Ekwueme” fẹ́sùn lílu ìyàwó rẹ̀ dójú ikú
- Ẹ̀yin obìnrin, ẹ tètè jápa tí ìgbéyàwó yín bá ti la ìgbájú-ìgbámú lọ - Olori Silekunola
- Mo fi Ọlọ́run bẹ̀ yín, ẹ má bú ọkọ mi mọ́ torí ìgbéyàwó wa tó túká - Yewande Adekoya
- Mo gbìyànjú láti ṣẹ́yún àkọ́bí mi saájú ìgbeyàwó - Iyabo Ojo
- Àyè wá dà, èmi ti ní ọ̀rẹ́kùnrin míràn nítèmi o - Nkechi Blessing
- Ṣé Iyabo Ojo ń gbèrò láti ṣe ìgbéyàwó? Wo àwọn ohun tó sọ nípa olólùfẹ́ rẹ̀
O ni isẹ́ akanse yii ti bẹ̀rẹ̀ lati Ojoru, ọjọ́ ketala osu yii titi di ọjọ́ru, ogunjọ́ osu yii.
Ni ipari, ajo FRSC parọ́wa fun awon awakọ lati rọra sare loju popo ki wọ́n si tẹ̀le ofin oju popo gbogbo.
.













