Nkechi Blessing, Mr Latin, Damola Olatunji: Ẹ̀ṣẹ̀ Nkechi àti ìjìyà tí a fún un ló fi ń yí ọ̀rọ̀ mọ́ ara wọn

Bi wọn ṣe n jẹ ekuru ọrọ kan ko tan lawo lagbo òṣèré Yoruba ni wọn tún n gbọn ọwọ omiran s'awo ni ọrọ ṣe tun yi mọ gbajugbaja òṣèré Nkechi Blessing
Damola Olatunji to jẹ òṣèré ati adari ere, Bolaji Amusan ti ọpọ mọ sí Mr Latin tó sì jẹ pe oun ni ààrẹ ẹgbẹ àpapọ osere, TAMPAN.
- Eèmọ̀ wọ̀lú, ẹni tó ń ta ọtí àti ògógóró gún Oníbárà rẹ̀ pa ní Osun!
- Báàlù ìjagun kan já lulẹ̀ ní ìlú Buhari, ẹ̀mi àwọn aráàlú bọ́
- Sunday Igboho ránṣẹ́ tuntun nípa agbẹjọ́rò rẹ̀ ní Benin republic, Ó ní...
- Wo ọ̀nà méje tí o lè fi dáàbò bò ọmọ rẹ níbàyìí tí iléẹ̀kọ́ ti bẹ̀rẹ̀ padà
- Sunday Igboho ní ₦4m sí ₦3m ni ìkọ̀ọ̀kan amòfin mẹ́wàá ní Cotonou gbà láì dènà kí òun má lọ sẹ́wọ̀n
Ninu ìfòròwánilénuwò kan ti wọn pe Nkechi Blessing si pẹlu atokun eto Chude Jideonwo lasiko to ni beere ọrọ nipa ẹsun biba ọmọde lopọ ti osere Baba Ijesa ni jẹ lọwọ ni o ti tu kẹkẹ ọrọ silẹ ti pẹtẹpẹtẹ rẹ ti ta ba awọn oṣere ọkunrin.
O darukọ ààrẹ wọn, Mr Latin o si darukọ alaga awọn adari ere, Damola Olatunji. BBC Yoruba kan sí àwọn méjèjì fún esi.
Igbiyanju lati gbọ lẹnu Mr Latin lasiko ti a ko iroyin yii jọ já sí pabo amọ Damola Olatunji sọ tẹnu rẹ pé Nkechi Blessing ko to bẹẹ kò fi esun kan oun pe oun maa ni bèrè fun Ibalopọ gẹgẹ bí awọn iwe iroyin kan ṣe gbee jade.
Damola Olatunji sọ fún BBC Yoruba pe bi won ba pa akọle iroyin tàwọn eeyan n kọ ti ti wọn gbọ ọrọ Nkechi daadaa, ko sọ pé òun n beere fun Ibalopọ ki oun to fun un ni ipa pataki julọ lati ko ninu ere.
Gẹgẹ bí Nkechi ṣe sọ, "ọpọlọpọ awọn ọkunrin adari ere ló máa fi gbogbo ẹnu ati aya gbangba sọ fún ẹ pé ninu koo jọwọ ara rẹ fun Ibalopọ koo to le gba ipa to ṣe pataki ju tabi koo gbagbe rẹ.
O ni oun ti ṣaaju f'ohun sita pe adari ki adari ti ko ba ti san owo iṣẹ fún òun koun to ṣeré fun un, oun o ṣe... Mo ti "block" Damola Olatunji to jẹ ọrẹ mi lori Watssap tẹlẹ bayii, mo lero pe o ni ọrọ mii pẹlu mi, ọkan lára àwọn adari ere si ni".
Damola Olatunji ni l'ẹba ọrọ owo sisan ni Nkechi ti darukọ oun kii ṣe ọrọ Ibalopọ.
Amọ o ni bi "Nkechi ba filè fi iru ẹsun bẹẹ kan mi, ile ẹjọ la ti máa parí ẹ".
- Kókó nǹkan tí ẹgbẹ́ NINAS ń bèrè fún ní ibi ìpàdé UN General Assembly
- Èmi tí wọ́n kọ́kọ́ pé ọkọ Bimbo kú gàn an ti di jálajála lórí ìròyìn burúkú náà- Jaye Kuti, ọ̀rẹ́ Bimbo Oshin
- Eèmọ̀ wọ̀lú, ẹni tó ń ta ọtí àti ògógóró gún Oníbárà rẹ̀ pa ní Osun!
- Ìwọ́de Yoruba Nation lólú iléeṣẹ́ àjọ UN wáyé, bó ṣe lọ nìyí
- Àwa ọmọ Iyabo Oko ló dá owó gọbọi fi gbé ìyá wa lọ sí India fún ìtọjú- Ewa, ọmọ Iyabo Oko
- Atọ́kùn egúngún, ọmọ rẹ̀ àti èèyàn méjì dèrò àtìmọ́lè lórí ẹ̀sùn ìpànìyàn ní mọ́ṣálááṣí






















