BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Nollywood
Regina Daniels ṣàlàyé ìdí tó fi di ẹni tó ń jókòó sórí 'wheel chair'
12 Ọ̀wàrà 2026
3:59
Fídíò,
Awọn òṣèré ayé òde òní ò láàánú mọ́, t'ara wọn nìkan ni wọ́n mọ̀ - Murphy Ray Eyiwumi
, Duration 3,59
8 Ọ̀wàrà 2026
Ohun tó fa ìjà tí ayé ń pariwo láàrin èmi àti Ogogo rèé àti bí a ṣe yanjú rẹ̀ - Yinka Quadri
7 Ọ̀wàrà 2026
Olu Jacobs, àgbà òṣèré wọ káà ilẹ̀ sún l'Ekoo
2 Ọ̀wàrà 2026
Ẹ jẹ́ kí n padà sí sinimá ṣiṣe, ó hàn pé mí ò kí ń ṣe ẹlẹ́ṣẹ́ – Nkechi Blessing sọ̀rọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n jàn án mọ́lẹ̀ pẹ̀lú ẹ̀ṣẹ́
2 Ọ̀wàrà 2026
1:17
Fídíò,
'Mo fẹ́ bá àwọn tí kò bọ̀wọ̀ fún mi wí láì lo ẹgba' Gbajúmọ̀ òṣèré', Nkechi Blessing sọ̀rọ̀ ṣáàjú ẹ̀ṣẹ̀ kíkàn tó fẹ́ jà pẹ̀lú Phyna
, Duration 1,17
1 Ọ̀wàrà 2026
Ọ̀kan ṣoṣo tó kù nínú gbogbo nǹkan tí mo fẹ́ ṣe nílé ayé rèé – Fatomilola
28 Owewe 2026
Ilé ayé kò ṣe é fi ojú lásán gbé, ohun búburú máa ń ṣẹlẹ̀ sí onínú ire - Ìyàwó Femi Adebayo tẹ́lẹ̀
23 Owewe 2026
0:58
Orin,
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
, Duration 0,58
16 Ọ̀wàrà 2026
Mọ̀ nípa àìsàn tó máa ń mú èèyàn gbàgbé nǹkan tó ṣe Olu Jacobs kó tó jáde láyé
17 Owewe 2026
Ìṣẹ́ alájótà, àtàwọn ohun tuntun míràn tí o kò mọ̀ nípa Temitope Osoba, gbajúmọ̀ òṣèré tí wọ́n ń sin òkú rẹ̀ lónìí
10 Owewe 2026
Mo pinnu láti fi Ogogo ṣe olùbádámọ̀ràn pàtàkì nínú ìjọba mi tí mo bá di gómìnà – Yayi
9 Owewe 2026
Wo bí ètò ìsínkú gbajúmọ̀ òṣèré tíátà, Temitope Osoba tó jáde láyé láìpẹ́ yìí yóò ṣe lọ
9 Owewe 2026
Kí ló ṣokùnfà ikú gbajúmọ̀ òṣèrèbìnrin, Nimmy Ferrari tó jáde láyé lásìkò tó ń palẹ̀mọ́ láti ṣí ilé tuntun tó kọ́?
8 Owewe 2026
3:17
Fídíò,
Bukky Wright sọ̀rọ̀ lórí ikú Kola Oyewo àti Ogogo, bí wọn kò ṣe pe ọ̀pọ̀ àgbà òṣèré tó jìyà tíátà sí iṣẹ́ mọ́ àti ohun tí ìjọba le ṣe láti ṣèrànwọ́
, Duration 3,17
4 Owewe 2026
Ṣé lóòótọ́ ni Kira, ọmọ Ogogo bímọ tuntun? Mọ̀lẹ́bí Ogogo sọ̀rọ̀ síta
28 Ògún 2026
Ètò ìsìnkú ti bẹ̀rẹ̀ fún Taiwo Hassan 'Ogogo'
26 Ògún 2026
Wo àwọn òṣèré tíátà Yoruba méje tó jáde láyé lọ́dún 2026
25 Ògún 2026
A sa gbogbo ipá wa láti gba ẹ̀mí Ogogo là – Yayi
24 Ògún 2026
Ọdún kan sẹ́yìn ni mo ti ń ṣàìsàn, dókítà kò sì mọ ohun tó ń ṣe mí - Opebe onítíátà
21 Ògún 2026
3:24
Fídíò,
Àwọn olólùfẹ́ Kola Oyewo sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ lẹ́yìn ìsìnkú rẹ̀
, Duration 3,24
11 Ògún 2026
4:02
Fídíò,
Àwọn sinimá kan wà tí mo ṣe tí àwọn òbí mi kò lè wò nítorí… - Bolaji Ogunmola, òṣèré tíátà
, Duration 4,02
10 Ògún 2026
Àgbà òṣère;Kola Oyewo wọ káà ilẹ̀ sùn l'Osun
7 Ògún 2026
Wó kókó méjìlá tó yẹ kí o mọ̀ nípa Temitope Osoba, òṣèré tíátà tó jáde láyé
6 Ògún 2026
Page
1
nínú
33
1
2
3
4
5
6
7
33
Tókàn
You might also like:
news
|
sport
|
weather
|
worklife
|
travel
|
future
|
culture
|
world
|
business
|
technology