Nigerians doing good abroad: Yoruba ń mókè, wọ́n ń gbéṣẹ́ ńlá ṣe lókè òkun

Oríṣun àwòrán, other
Kii ṣe olè, ọlẹ ati gbajuẹ nikan ni ọmọ Naijiria paapaa Yoruba n ṣe loke okun.
Ni ẹnu ọjọ mẹta yii, oniruuru iroyin iwa kotọ nipa awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria to wa loke okun lo n fọn kalekako lori ayelujara.
Koda, aarẹ Muhammadu Buhari funrarẹ ko ṣai mẹnu le ọrọ yii nibi ipade idagbasoke Afirika to lọ ṣe ni Japan.
- Kíni ẹ mọ̀ nípa Ọmọ́táyọ̀ Olútóyè, Ọ̀jọ̀gbọ́n obìnrin àkọ́kọ́ nínú ẹkọ́ èdè Yorùbá lágbàyé
- Iléeṣẹ́ ológun Nàìjíríà sẹku pa àwọn jàndùkú nínú igbó Kaduna, wo nkan tí wọn rí gbà lọ́wọ́ wọn
- Ṣe ẹ ti gbọ́ ri? Ọmọ ọdún mẹ́rìnlá kàwé gboyè jáde ni Oxford
- Àsìkò tí tó fún àwọn ọ̀dọ́ láti gbá ìṣàkóso orílẹ̀èdè Nàìjíríà- Peter Obi
- Ọwọ́ àwọn agbófinró Abuja tẹ afurasí 480 tó sá kúró lọ́gbà ẹ̀wọ́n Kuje
Eyi lo wa n faa ti ọpọ fi n ṣe beere boya ohun rere kan tilẹ lee ti Nasarẹti yii jade.
Amọṣa diẹ niyi lara awọn ọmọ Yoruba to n da bi ẹdun, rọ bi owe.
Dokita agba Oluyinka Olutoye:

Oríṣun àwòrán, BBC Sport
Dokita agba Oluyinka Olutoye jẹ ọkan lara awọn ogo orilẹ-ede Naijiria ti itanṣan wọn n tan ka gbogbo agbaye fun ipa rere ti wọn n ko kaakiri.
Lati kekere ni Dokita Oluyinka Olutoye ti ni ifẹ si iṣẹ dokitaKíni ẹ mọ̀ nípa Ọmọ́táyọ̀ Olútóyè, Ọ̀jọ̀gbọ́n obìnrin àkọ́kọ́ nínú ẹkọ́ èdè Yorùbá lágbàyé
Gẹgẹ bii ọrọ rẹ, 'lati kekere ni mo ti maa n ṣe ere dokita kaakiri inu ile wa' nitori ifẹ rẹ si iṣẹ naa.
- Wò ó bí èsì ìbò ààrẹ ní Kenya ṣe lọ
- Ẹgbẹ́ NLC kọ lẹ́tà sí Buhari pé kó fi ìdá àádọ́ta 50% kún owó oṣù òṣìṣẹ́ Nàìjíríà
- Ǹkan ti ọlọ́pàá sọ rèé lórí ìjà Fulani àti OPC tó mú ẹ̀mí èèyàn mẹ́rin lọ ní Kwara
- Irọ́ lọ̀gá ṣọ́jà 81 division pa pé ọlọ́pàá yìnbọn sí ṣọ́jà tó pa Ìsìpẹ́tọ̀ Orukpe, ẹ ní kó gbé ṣọ́jà náà jáde - iléeṣẹ́ ọlọ́p
- Ń kó gbá àádọ́ta bílíọ́nù lóṣooṣù lọ́wọ́ Ambode – Tinubu
Koda aarẹ Muhammadu Buhari funrarẹ ko ṣai mẹnu le ọrọ yii nibi ipade idagbasoke Afirika to lọ ṣe ni Japan.A ń fikunlukun pẹ̀lú FBI láti mú àwọn "Yahoo Boys" tó kù- EFCC
Eyi lo wa n faa ti ọpọ fi n ṣebeere boya ohun rere kan tilẹ lee ti Nasarẹti yii jade?Ẹ yọjú sí FBI bí ẹ kìí bá ṣe ''yahoo boys'' - Abike Dabiri-Erewa.
Ki lo bi ero pe iwa buruku ni awọn ọmọ Naijiria n hu loke okun:
Ni ẹnu ọjọ mẹta yii, oniruuru iroyin iwa kotọ nipa awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria to wa loke okun lo n fọn kalekako lori ayelujara.
Amọṣa diẹ niyi lara awọn ọmọ Yoruba to n da bi ẹdun, rọ bi owe ni Olutoye Olayinka. Baba rẹ ni Alani ti ilu Ido-Ani, Oluwatomiloye I.
Ta ni Olutoye Olayinka?
Ọmọ ilu Idoani ni Dokita Olayinka Olutoye.
Awọn obi rẹ ni Ọgagun agba Olufẹmi Olutoye to ti fẹyinti ninu iṣẹ ologun ati Ọjọgbọn Ọmọtayọ Olutoye to jẹ Ọjọgbọn akọkọ ninu ẹkọ imọ Yoruba.
Awọn mẹfa ni awọn ẹgbọn ati aburo rẹ, mẹta jẹ obinrin, meji ninu wọn si jẹ ọkunrin.
Ileẹkọ alakọbẹrẹ Lagos University Staff School ni o lọ ki o to kọri si ileeko girama King's College ni ilu Eko kan naa.

Oríṣun àwòrán, others
Lẹyin to pari ile ewe girama rẹ, Olutoye gba ọgba fasiti Ọbafẹmi Awolọwọ lọ lati kọṣẹ imọ iṣegun oyinbo nibẹ.
Ọdun 1988 ni o kẹkọọ gboye ninu imọ iṣegun oyinbo ati iṣẹ abẹ.

Oríṣun àwòrán, others
Adebayo Ogunlesi: ọmọ ọjọgbọn onimọ iṣegun to ra papakọ ofurufu Gatwick lọwọ èèbó
Tani ọlọpọlọ pipe oludokowo Adebayo Ogunlesi to gba aarẹ ile ifowopamọ agbaye ṣiṣẹ?
Ilu Makun ni ipinlẹ Ogun ni wọn ti bi Adebayo Ogunlesi ti o si ti wa di ilumọka agbẹjọro ati ouldukowo lagbaye
Pupo ninu awọn arinrinajo to ba gba papakọ ofurufu Gatwick kọja nilẹ Gẹẹsi a maa kan saara si bi wọn ti ṣe ṣe eto papakọ ofurufu naa.
Iyipada ti wọn mu ba papakọ naa waye lẹyin ti ile iṣẹ aladani kan raa lọwọ ajọ to n ṣamojuto rẹ BAA niye owo biliọnu pọun kan le diẹ lọdun 2009.
- NFF kò ti san owó tó jẹ Super Falcons ní Morocco títí di àsìkò yìí
- Ẹ má bú ọkọ́ mi mọ́, Bàbá Tobi kò jẹ́bí bó ṣé dáná sún aṣọ èrè ṣíṣá ọmọ rẹ - Ìyá Amusan
- Tobi ní òun kò ní jẹ́ asáré ojú títì lásán, mo sì ń tì í lẹ́yìn - Alàgbà Amusan
- "Bi mo tilẹ̀ jẹ́ apárí síbẹ̀ kò tìmí lójú", Liliya Kukushkina
- Ilé ti sú ọmọ mi torí ìdaṣẹ́sílẹ̀ ASUU ló ṣe lọ ṣiṣẹ́ nílé ìtura, tó fi pàdé ikú òjijì - Màmá Rachel Opadele
Ọrọ Gatwick kọ la fẹ fayọ ninu itan kekere yi bi kii ṣe ti ọmọ Yoruba to jẹ oludari ile iṣẹ Global Infrastructure Partners to ra Gatwick pa.
Ẹni ti a n sọrọ rẹ ni Adebayo Ogunlesi-ọmọ bibi ilu Makun nipinlẹ Ogun to si jẹ ilumọọka oludokowo lagbaye nii ṣe.
Ọmọ ti ẹya ba bi, ẹya nii jọ.
- Wo àwọn nọ́mbà ìpè agbófinró tó yẹ kò mọ̀, èyí tó pè tí ìkọlù agbébọn bá dé
- Àwọn aya Yekeen Ajileye ló fa ìpinyà láàrin wa débi pé mo fẹ́ pa ara mi - Abija
- 'Láti ojú orun, ohùn kan máa ń tọ́ka ewé àti ègbòogi sí mi, báyìí la ṣe ń ṣe agbo fún ǹkan ọmọ ọkùnrin'
- Bàbà ọmọ ọdún 75 kó HIV ran ọmọ ọdún 14 lẹ́yìn tó fi ipá báa lò
- Gbogbo ọjà di títì pa nílùú Akure, ṣugbọ́n nítorí kí ni?
Lati kekere ni Adebayo ti ṣẹnu ṣamuṣamu ti a si le sọ wi pe ile lo ti baa.
Baba rẹ, ọjọgbọn Theophilus Ogunlesi ni onimọ iṣegun akọkọ to gba oye ọjọgbọn nilẹ Naijiria.
Ile iwe girama Kings College nilu Eko ni Adebayo lọ ti o si pegede nibẹ.
Lẹyin to pari ẹkọ, girama, o tẹsiwaju lọ ilẹ ẹkọ fasiti Oxford nibi to ti kawe gboye imọ nipa imọ iwa ẹda, oṣelu ati ọrọ aje, iyẹn Philosophy Politics and Economics.
Olukemi Olufunto Adegoke Badenoch
Ni oṣu, keje ọdun 2019 ni Olootu ijọba ilẹ Gẹẹsi tẹlẹ, Bori Johnson yan arabinrin Olukemi Olufunto Adegoke Badenoch gẹgẹ bii minisita abẹle fun ọrọ awọn ọmọde ati idile.

Oríṣun àwòrán, kemi badenoch
Ni oṣu kinni, ọdun 1980 ni wọn bi i ni ilu Wimbledon lorilẹ-ede Gẹẹsi ṣugbọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria ni awọn obi rẹ,
Dokita Fẹmi Adegoke ati Ọjọgbọn Feyi Adegoke ni orukọ wọn
- Buhari, pe ìpàdé àpérò ọmọ Nàíjíríà fún àgbékalẹ̀ òfin tuntun - Afe Babalola
- Egungun Oloolu ti ilẹ̀ Ibadan fojú han aráyé! Gbọ́ àwọn ǹkan tó ń dẹ́rù ba obìnrin, ọmọde nípa rẹ̀ àti èèwọ̀ rẹ̀
- Ọkọ àfẹ́sọ́nà kọ̀ mí sílẹ̀ pé mo ní iṣan lápá, ọ̀yan mi sì ǹ rá torí iṣẹ́ ọ̀gbìn – Àgbẹ̀ Obìnrin
- Kò rọrùn rárá láti dàgbà ní agbègbè bíi Mushin, àànú Ọlọ́hun ló sọ mi di agbábọ́ọ̀lù Super Falcons - Rasheedat Ajibade
Wọn gbe e pada wa si orilẹ-ede Naijiria lẹyin ibi rẹ, ṣugbọn o pada si ilẹ Gẹẹsi nigba ti o pe ọmọ ọdun mẹrindinlogun.
Ilu Eko lo ti lo igba ewe rẹ.
Ni ọdun 2017 ni wọn dibo yan an si ile igbimọ aṣofin ilẹ Gẹẹsi lati ṣoju fun ẹkun Saffron Walden.
















