Kò rọrùn rárá láti dàgbà ní agbègbè bíi Mushin, àànú Ọlọ́hun ló sọ mi di agbábọ́ọ̀lù Super Falcons - Rasheedat Ajibade

Àkọlé fídíò, Rasheedat Ajibade WAFCON 2022: Tí m bá wo bí mo ṣe bẹ̀rẹ̀ ní Mushin táwọn ẹgbẹ́ mi ń máà m

Ṣaaaju ifsẹwọnsẹ ti yoo waye laarin awọn agbabọọlu obinrin orilẹede Naijiria ati Cameroon lonii ni papa isere Stade Mohamed V Stadium ni Casablanca lẹyin ti wọn lu awọn agbabọọlu Burundi lalubami lọjọ Aiku to kọja, BBC Yoruba mu iroyin nipa igbaradi awọn ẹgbẹ agbabọọlu ti Naijiria wa.

Ọkan lara wọn to jẹ agbabọọlu aarin to si jẹ ọmọ Yoruba, Rasheedat Ajibade kẹnu bọ ọrọ nipa ibẹrẹpẹpẹ rẹ ni agbegbe Mushi ni ipinlẹ Eko, Naijiria.