CAF kéde Asisat Oshoala, Rasheedat Ajibade, Chiamaka Nnadozie lára àwọn agbábọ́ọ̀lu obìnrin fún àmì ẹ̀yẹ 'CAF Awards' tọdún 2022

Aworan Rasheedat Ajibade

Oríṣun àwòrán, caf

Ajọ ere bọọlu nilẹ Afirika, CAF ti kede orukọ awọn agbabọọlu obinrin ti yoo kopa fun ami ẹyẹ awọn agbabọọlu obinrin ni Afrika ti ọdun 2022.

Lara awọn ipele ami ẹyẹ ti wọn yoo kede awọn agbabọọlu obinrin to bori fun ni agbabọọlu obinrin to pegede julọ laafirika, agbabọọlu obinrin fun ẹgbẹ agbabọọlu to pegede julọ, agbabọọlu ọdọbinrin to pegede julọ l’Afirika, pẹlu ẹgbẹ agbabọọlu obinrin to pegede julọ ni Afrika.

Atẹjade ti Ajọ CAF fi sita tun sọ pe, wọn yoo kede awọn oludije fun ami ẹyẹ akọnimọọgba ikọ agbabọọlu Obinrin to pegede julọ pẹlu ẹgbẹ agbabọọlu obinrin orilẹede to pegede julọ laipẹ.

Ajọ naa ni ijafafa awọn agbabọọlu obinrin nibi idije ife ẹyẹ bọọlu awọn Obinrin ni Afirika, WAFCON yoo wa lara awọn ohun ti wọn yoo gbe yẹwo lati yan awọn oludije ti yoo bori ọkọọkan awọn ipele ami ẹyẹ kọọkan.

Ni ọjọ kọkanlelogun oṣu keje ọdun 2022 ni wọn yoo kede orukọ awọn agbabọọlu obinrin to ba pegede lawọn ẹka naa ni ilu Rabat lorilẹede Morocco.

Ayẹyẹ ami ẹyẹ naa yoo waye ṣiwaju ifẹsẹwọnsẹ aṣekagba ife ẹyẹ bọọlu awọn obinrin nilẹ Afirika, WAFCON to n lọ lọwọ lorilẹede Morocco.

Awọn oludije fun ami ẹyẹ agbabọọlu obinrin to pegede julọ ni Afirika

Aworan Asisat atawọn agbabọọlu kan

Oríṣun àwòrán, caf

Awọn oludije fun ami ẹyẹ agbabọọlu obinrin to pegede julọ ni Afirika

  • · Lesege Radiakanyo (Botswana & Double Action)
  • · Refilwe Tholakele (Botswana & Township Rollers)
  • · Rukiya Bizimana (Burundi & Etoile du matin)
  • · Ajara Nchout Njoya (Cameroon & Internazionale Milano)
  • · Gabrielle Onguene (Cameroon & CSKA Moscow)
  • · Jeanette Yango (Cameroon & FC Fleury)
  • · Rose Bella (Cameroon & Trabzonspor)
  • · Evelyn Badu (Ghana & Alvaldsnes)
  • · Doris Boaduwaa (Ghana & Sekondi Hasaacas)
  • · Perpetual Agyekum (Ghana & Sekondi Hasaacas/Alvaldsnes)
  • · Sanaa Mssoudy (Morocco & AS FAR)
  • · Ghizlane Chebbak (Morocco & AS FAR)
  • · Fatima Tagnaout (Morocco & AS FAR)
  • · Zenatha Coleman (Namibia & Fenerbahce)
  • · Asisat Oshoala (Nigeria & Barcelona)
  • · Rasheedat Ajibade (Nigeria & Atletico Madrid)
  • · Chiamaka Nnadozie (Nigeria & Paris FC)
  • · Uchenna Kanu (Nigeria & Tigres UANL)
  • · Andile Dlamini (South Africa & Mamelodi Sundowns)
  • · Bambanani Mbane (South Africa & Mamelodi Sundowns)
  • · Chrestinah Thembi Kgatlana (South Africa & Atletico Madrid)
  • · Jermaine Seoposenwe (South Africa & Sporting Clube de Braga)
  • · Refiloe Jane (South Africa & AC Milan)
  • · Linda Motlhalo (South Africa & Djurgardens IF)
  • · Odette Gnintegma (Togo & Raja Ain Harrouda)
  • · Mariem Houij (Tunisia & ALG Spor)
  • · Sabrine Ellouzi (Tunisia & Feyenoord)
  • · Fazila Ikwaput (Uganda & Dove FC)
  • · Racheal Kundananji (Zambia & SD Eibar)
  • · Grace Chanda (Zambia & BIIK Kazygurt)
Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: The BBC is not responsible for the content of external sites.

End of X post, 1

Awọn oludije fun ami ẹyẹ agbabọọlu obinrin to pegede julọ ni ẹgbẹ agbabọọlu l'Afirika

  • · Andile Dlamini (Mamelodi Sundowns)
  • · Bambanani Mbanie (Mamelodi Sundowns)
  • · Zanele Nhlapho (Mamelodi Sundowns)
  • · Andisiwe Mgcoyi (Mamelodi Sundowns)
  • · Evelyn Badu (Sekondi Hasaacas/Alvaldsnes)
  • · Doris Boaduwaa (Sekondi Hasaacas)
  • · Janet Egyir (Sekondi Hasaacas)
  • · Perpetual Agyekum (Sekondi Hasaacas/Alvaldsnes)
  • · Fatima Zahra Dahmos (AS FAR)
  • · Ghizlane Chebbak (AS FAR)
  • · Sanaa Mssoudy (AS FAR)
  • · Fatima Tagnaout (AS FAR)
  • · Grace Mfwamba (Malabo Kings)
  • · Stephanie Gbogou (Malabo Kings)
  • · Rose Bella (Malabo Kings)
  • · Fatoumatta Dukureh (Wadi Degla)
  • · Hayama Abdellatif (Wadi Degla)
  • · Gift Monday (River Angels/FC Robo)
  • · Maryann Ezenagu (River Angels)
  • · Bassira Toure (AS Mande)
Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: The BBC is not responsible for the content of external sites.

End of X post, 2

Awọn Oludije fun Ami ẹyẹ agbabọọlu ọdọbinrin to pegede julọ l’Afirika

  • · Rukiya Bizimana (Burundi & Etoile du Matin)
  • · Rediet Assresahagn (Ethiopia & Hawassa City FC)
  • · Evelyn Badu (Ghana & Sekondi Hasaacas/Alvaldsnes)
  • · Doris Boaduwaa (Ghana & Sekondi Hasaacas/Alvaldsnes)
  • · Yasmine Zouhir (Morocco & AS Saint-Etienne)
  • · Gift Monday (Nigeria & River Angels/FC Robo)
  • · Flourish Sebastine (Nigeria & Bayelsa Queens)
  • · Hapsatou Malado Diallo (Senegal & US Parcelles Assainies)
  • · Clara Luvanga (Tanzania & Yanga Princess)
  • · Fauzia Najemba (Uganda & BIIK Kazygurt)

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: The BBC is not responsible for the content of external sites.

End of X post, 3

Awọn oludije fun ami ẹyẹ ẹgbẹ agbabọọlu obinrin to pegede julọ ni Afirika

  • · Mamelodi Sundowns (South Africa)
  • · Sekondi Hasaacas (Ghana)
  • · AS FAR (Morocco)
  • · Malabo Kings (Equatorial Guinea)
  • · Wadi Degla (Egypt)
  • · River Angels (Nigeria)
  • · AS Mande (Mali)
Skip X post, 4
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: The BBC is not responsible for the content of external sites.

End of X post, 4