Couple selling human parts: Iléeṣẹ́ ọlapàá ní afurasí tọkọtaya náà ta ẹ̀yà ara ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́rin náírà

Oríṣun àwòrán, Other
Leyin ifewero awon agbofinro pelu awon awon afurasi Tokotaya se iku pa arabinrin kan ni agbegbe Leme ni Abeokuta ni won ti fi idi e mule pe egberun lona aadorin naira won ta eye ara arabinrin naa si ilu ibadan.
Alukoro fun Ile ise olopaa ipinle Ogun, Ogbeni Abimbola Oyeyemi so fun BBC News Yoruba pe Ile ise olopaa si n tesiwaju ninu iwadii won sugbon awon afurasi Tokotaya naa ti jewo pe awon ni won se iku pa arabinrin naa.
"Arabinrin naa wa ki won naa, won si se ounje oyinbo indomie fun pelu eyin, ninu ounje naa ni ogun orun wa, bi o se je ounje naa tan ni o sun, won si fun ni orun pa mole ki o to dipe won bere lati ma ge awon ara arabinrin naa si we we."
- Ki lo ṣokunfa ikọlu to n waye si ẹni to ba wọ aṣọ Sunday Igboho tabi Yoruba Nation n'Ibadan?
- Makinde buwọ́lu Sẹ́nẹ́tọ̀ Lekan Balogun gẹ́gẹ́ bí Olubadan tuntun
- "Ìná tó ń ṣe àkóso ojú pópó ló dá ọkọ̀ agbówórìn dúró, tí adigunjalè fi kọ lù ú"
- Ọlọ́pàá kánkan kò ku sùgbọ́n a pa ọkan ninu àwọn tó fẹ́ já ọkọ̀ agbówórìn gbà-Ọlọ́pàá
- Ìyá Sunday Igboho wà lórí àìsàn torí kò rí ọmọ rẹ̀ - Agbekoya
- Davido, bá mi kọ ẹsẹ orin kan nínú àwo orin mi, jẹ́ ká da ayé láàmú - Portable Zazzu
- Ọmọ ọdún 18 dèrò àtìmọ́lé lórí ẹ̀sùn pẹ ó gún akẹgbẹ́ lọ́bẹ pa
- Aregbẹsọla kìí ṣe Olọ́run, iṣẹ́ Oyetola ló máa fọhùn lọ́jọ́ ìdìbò- Ismail Omipidan
"Ka ma gbegbe pe awon ara adugbo naa ti ri okun kan leba Ojo bi Ojo Melo seyin kin owo to gba awon afurasi Tokotaya my. Iwadi ti fimule pe iku ojosin to ko pe ni won iyoku si ninu yara won ti owo siti te won".
Alukoro tesiwaju pe awon afurasi Tokotaya naa ni won ti se ijamba iku fun awon meji ti won siti jewo pe awon ta eye ara arabinrin naa fun eegerun lona adorin si ilu ibadan ni".
"Enikeji ni ti won pa niyen, won sin ta won fun awon korolosi ede bi won ti won si eye ara arabinrin na fun eegberun lona adorin, ijoba ipinle Ogun si ti pinu lati ripe owo te awon ara bi naa, ti won si fi oju ba Ile ejo."











