Mike Bamiloye, adarí Mount Zion bèrè bóyá àpaàyàn kọ́ ní ẹni tó ń ṣí ara sílẹ̀ lọ ṣọ́ọ̀ṣì, ṣé apàyàn kọ́ ni ẹ́ báyìí?

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Gbajugbaja oṣere kritẹni, Mike Bamiloye to jẹ oludasilẹ ẹgbẹ oṣere Mount Zion ti ja gudugbẹ ọrọ lulẹ lori aṣọ wiwọ ni ṣọọṣi.
Bamiloye ni ''o n wọ aṣọ to ṣi ara silẹ lọ si ṣọọṣi, o tumọ si pe o ti pinnu lati di apayan ni ṣọọṣi.''
''Iwọ ni tiẹ, ijo ati mu ọmọlakeji ṣubu ni iwọ mọ ọ jo ni tiẹ ti wọn ba n kọ irin ninu isin,'' Bamiloye lo sọ bẹẹ.
- Oral Sex: Bóo bá ń gba ẹnu ní ìbálòpọ̀, wo àìsàn tóo lè kó lójú ara rẹ
- Wo ojú Akeem t'Ọlọ́pàá mú pé ó fipá bá ọ̀dọ́mọbìnrin kan sùn létí odò l'Oṣun
- Yàtọ̀ sí Eko, wo ohun t'áwọn ìpínlẹ̀ meje míràn ń sọ nípa ìwọlé àwọn akẹ́kọ̀ọ́
- Wòlí àti Pásítọ́ ló máa ń rọ̀jọ̀ àdúrà sórí ibọ́n wa kí a tó lọ digunjalè- Kayode Williams
- Ogun Àgbẹ́kọ̀yà, ìjà òmìnira fáwọn àgbẹ̀ ni tàbí ìfẹ́míṣòfò?
- 'Àwa ọmọ Nàìjíríà tó farapa fẹ́ wálé láti Lebanon, ìjọba kó wa pamọ́'
Bamiloye ni ''iwọ to sọ pe o n jo lati yin Ọlọrun ni ti o si mọ pe fun ra rẹ pe irọ lo n pa.''
Content is not available
View content on FacebookBBC kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta.End of Facebook post
Gbajugbaja oṣere kristẹni naa wa beere pe ''njẹ apayan ni ṣọọṣi kọ niọ bayii.''
Ọpọ lo ti di ẹbi aṣọ iwọkuwọ ṣọọṣi ru awọn obinrin nikan, ṣugbọn awọn mii sọ pe ki lawọn ọkunrin naa n wo lara obinrin ti wọn kko kọ oju mọ isin ni ṣọọṣi.
Awọn miiran tiẹ ni aṣọ iwọkuwọ lawujọ gan an lo sẹ okunfa iwa ifipabanilopọ to ti pọ si ni Naijiria bayii.
- Ọkùnrin kan da ṣọ́ọ̀ṣì rú lásìkò ìgbéyàwó, Ó ní òun lọkọ àárọ̀ ìyàwó tuntun
- Mi ò fẹ́ ìrànwọ́ ẹgbẹ́ òṣèré, àwọn kọ́ ló kóbá mi- Chief Kanran
- Ohun tí a mọ̀ nìyí nípa gbọ́nmi síi omi ò tó lórí ọ̀rọ̀ oyè Babaloja-General ní ìpínlẹ̀ Oyo
- YWC yọ Ààrẹ Banji Akintoye nípò àbi Akintoye tú ìgbìmọ̀ aláṣẹ YWC ká?
- Ìpínlẹ̀ Osun kéde ọjọ́ táwọn iléèwé yóò ṣí padà
- Victoria Rubadir ọmọ Kenya ló gba àmì ẹ̀yẹ Komla Dumor BBC World News.











