Akomolede: Bolaji Faleke ni Olùkọ́ tó ń kọ́ wa ní àṣà oge ṣiṣe lórí BBC Yorùbá
Arabinrin Bolaji Faleke ló kọ wa ni lonii pẹlu iṣẹ Aṣetilewa lori oge ṣiṣe lati Ikeja Central Primary School ni ipinle Eko.
Imọtoto ni Yoruba gba pe o le ṣẹgun arun gbogbo paapaa laisko ajakalẹ arun Coronavirus to n ba agbaye finra yii.
Aṣa oge ṣiṣe ni ilẹ Yoruba ni a n gbe yẹwo loni lori eto Akọmólede ati aṣa lori BBC Yoruba ti ọsẹ yii.
- Wo àwọn ọmọdé mẹ́ta tó ń fi èdè Yorùbá dá bírà ní Finland!
- Ẹ wá dánrawò níbí pẹ̀lú Àpólà Ọ̀rọ̀ Orúkọ, "Noun Phrase"
- Ta ni ìyàwó Chadwick Boseman, tó jẹ́ àwòkọ́ṣe rere f'áwọn ọ̀dọ́ Adúláwọ̀?
- Fijilanté ṣèṣì yìnbọn pa Sunday ní Ondo, wọ́n ní wọ́n rò pé ẹranko ni!
- Ìjọba Ghana ṣí iléeṣẹ́ àwọn ọmọ Nàìjíríà padà. Ó fún Nàìjíríà l'èsì àwọn ẹ̀sùn tó fi kàn-án
Iyatọ wo lo wa laarin oge ṣiṣe laye atijọ ati ni isinyi?
Iwẹ wiwẹ, Tiro lile, Irun didi, Irun fifa, Eyin lile, Ila kikọ, Ayika titunṣe, Ilẹ gbigba ati bẹẹ bẹẹ lọ wa lara oge ṣisẹ laye atijọ.
- Wo ojú Akeem t'Ọlọ́pàá mú pé ó fipá bá ọ̀dọ́mọbìnrin kan sùn létí odò l'Oṣun
- Yàtọ̀ sí Eko, wo ohun t'áwọn ìpínlẹ̀ meje míràn ń sọ nípa ìwọlé àwọn akẹ́kọ̀ọ́
- Wòlí àti Pásítọ́ ló máa ń rọ̀jọ̀ àdúrà sórí ibọ́n wa kí a tó lọ digunjalè- Kayode Williams
- Iléẹjọ gíga jùlọ da ẹjọ́ SDP àti PDP nù, wọ́n ní Yahaya Bello ló wọlé ìbò gómìnà Kogi
Nigba ti tatoo yiya, atike igbalode kikun, ete kikun, eti lilu lọna to pọ, imu lilu, ṣokoto wiwọ fun obinrin ati bẹẹ bẹẹ lọ jẹ ti igbalode.
Mọ sii nipa awọn sitaili to wa nita ninu ẹkọ yii.
- Ìjà d'ópin, fún ìgbà àkọ́kọ́, bàálù gbéra láti Israel lọ sí UAE
- Wọ́n ti sún ìdájọ́ àwọn sójà tó pa ìyá àti ọmọ ní ọdun 2018 sí oṣù tó m bọ̀
- Ààrẹ Buhari buwọ́lu gbígbé ìṣàkoso nọ́mbà ìdánimọ̀ (NIMC) lọ sí ẹ̀ka ìjọba tó ń rí sí ìbáraẹnisọ̀rọ̀
- Ṣé Nàìjíríà lẹ́mìí nkan tí Ghana ń ṣe fáwọn akẹ́kọ̀ọ́ "Secondary" tí yóò wọlé ní October yìí?
- Ọkùnrin kan di èrò ọ̀run nítorí pé o fi ẹ̀sùn kan alájọgbélé rẹ̀ pé o n yan ìyàwó ẹnìkan lálè

