Kayode Williams ọmọ lẹyin Oyenusi, ògbóǹtarìgì adigunjalè tó ń fi àyípadà rẹ̀ ran àwọn ẹlẹ́wọ̀n lọ́wọ́
Oyenusi ló mú mi wọ ẹgbẹ́ adigunjalè kó tó di pé mo b'Ólúwa pàdé - Kayode Williams
Kayode Williams ni igbe aye ọtọọtọ gba a ni ki eeyan lọ sẹwọn ati ki o tẹwọn de eyi to si nilo ilanilọyẹ akọtun.
"O nilo ikọni, idari, ọrọ pe o gba ẹsin kọ leleyii, Ọlọrun gbudọ tun un bi tori eeyan ṣaa ni mi..."
"Ọgbà ẹwọn Nàìjíríà tó kàn rí bíi pé wọn kó ẹranko si Zoo ni kò jẹ kí ayé àwọn ọdáràn yí padà"
- Mọ̀ síi nípa Shina Rambo tó pàdé Jesu lọ́gbà ẹ̀wọn lẹ́yìn tó ti jalè
- Àmọ̀tekún kò tọ́ lábẹ́ ìjọba, ẹ búra fún wá, ká bọ́ sígbó láti ṣeré ọwọ́ pẹ̀lú ọ̀daràn - Sunday Igboho
- Ọlọ́pàá Funso ló fi ààyè sílẹ̀ fún mi láti sá kúrò ní àgọ́ ọlọ́pàá tó wà ní Mokola - Sunday Shodipe
- Èèyàn kẹta tó wà nínú ẹlikọ́pítà Quarom aviation tó já lulẹ̀ ní Ikeja náà ti jáde láyé!
O sọ aṣiri bi awọn Pasitọ ati Wolii nla nla ṣe maa n sẹri ibukun sori ibọn wọn ati ifami ororo yan ki wọn to jade lọ ja ole bi wọn ba si dari wọn a wa fi idamẹwa silẹ.
Ko to di atunbi, ogbontarigi ọdaran ni Kayode Williams ti orukọ rẹ ti yipada si Biṣọọbu Kayode Williams bayii.

Oríṣun àwòrán, @kayode
Kayode ni kii ṣe pe iwa awọn pasitọ wu oun lorii loun fi faye oun fun Jesu bi ko ṣe pe Ọlọrun diidi gba ẹnu adajọ to paṣẹ ẹwọn ọdun mẹwaa fun un sọrọ sinu aye oun.
Wiliams sọ bi o ṣe pade ogbontarigi adigunjale Ishola Oyenusi to gbajumọ nigba aye rẹ fun dida ilu ru.
- Gbajúgbajà òṣèré Black Panther jáde láyé!
- Oral Sex: Bóo bá ń gba ẹnu ní ìbálòpọ̀, wo àìsàn tóo lè kó lójú ara rẹ
- Wo ojú àwọn afurasí tó fipá bá Uwaila, akẹ́kọ̀ọ́ Uniben sùn tí wọ́n tún pa á sínúu ṣọ́ọ̀ṣì
- Ìdí tí mo fi gbàdúrà ìyàwó bíi Chanel Chin fáwọn tó d'ẹ̀bi ìkọ̀sílẹ̀ rẹ̀ rù mí rèé - Oluwo
- 'Tíátà ọ́mọdé tí wọ́n ń kọ́ wa ní Bariga ti mú mi lọ Germany, France, Amsterdam...'
O darukọ Ọmọwe Ishola Oyenusi, Babatunde Folorunsho, Baba Koshewọn to jẹ pe ọwọ ọlọpaa ko ki n tẹ ẹ.
Ọmọde ni Kayode nigba naa ṣugbọn itan bi ẹgbẹ awọn agbalagba ọdaran ṣe fi owo tan an toun naa bẹrẹ si ni gbe ibọn to si n mu igbo jẹ ibanujẹ to dori agba kobo.
- Ìtàn ayé Ọba Seriki Abass ti Badagry, tó ní aya 128, ọmọ 144
- Tunde Idiagbon, ọ̀gágun kògbagbẹ̀rẹ́ tó ní ẹ̀ẹ̀kan lóṣù ló yẹ kí ológun máa rẹ́rìín
- Yàtọ̀ sí Eko, wo ohun t'áwọn ìpínlẹ̀ meje míràn ń sọ nípa ìwọlé àwọn akẹ́kọ̀ọ́
- Iléẹjọ gíga jùlọ da ẹjọ́ Wada (PDP) nù ní Abuja lórí ètò ìdìbò gómìnà ìpínlẹ̀ Kogi

