Oͅkùnrin kan sͅosͅo ti mo yó ìféͅ rèͅ ní Naijiria ni Wizkid- Bobrisky

Aworan

Oríṣun àwòrán, Others

Gbajugbaja oͅkunrin ti maa n mura bii obinrin ni Naijiria, Bobrisky ti ni Wizkid nikan ni ilumoͅoͅka oͅkunrin ni Naijiria ti oun yo ifeͅ reͅ.

Bobrisky ti inagije reͅ n jeͅ ‘’Afrca’s First Male Barbie’’ lo fi eleyii lede ni oju opo ikansiraeͅni Twitter reͅ ni Oͅjoͅ Karundinloͅgboͅn, Osu Keͅrin, oͅdun 2023.

Bob wa fi aworan Wizkid lede peͅlu akoͅle pe’’ oͅkunrin kan soso ni Naijiria ti mo jeͅ dodo reͅ’’

Amoͅ lara awoͅn to fesi si oͅroͅ naa lori eͅroͅ ayelujara bu eͅnu ateͅ lu oͅroͅ naa, ti awoͅn miran tileͅ ni awoͅn taka reͅ nu fun Wizkid.

Lorileͅede Naijiria, ifeͅ akoͅ si akoͅ tapa si ofin Naijiria to si ni ijiya ninu to fi moͅ fifi eͅwoͅn jura.

Tani Wizkid ti Bobrisky yo ifeͅ reͅ?

Wizkid jeͅ ilumoͅoͅka olorin ti orukoͅ abisoͅ reͅ n jeͅ Balogun Ayodeji Ibrahim

Oͅjoͅ Keͅrindinlogun, Osu Keͅjoͅ, oͅdun 1990 ni woͅn bi ni agbegbe Surulere ni ilu Eko

Awoͅn moͅleͅbi reͅ jeͅ eͅleͅsin Musulumi ati Kristeͅni, to si ni awoͅn ibatan obinrin to jeͅ mejila

jeͅ oͅkan lara awoͅ olorin ti aje reͅ bu igba jeͅ ni Naijiria, ati ni ileͅ Afrika

Oͅmoͅde lo wa nigba ti o ti n koͅrin amoͅ ti awoͅn moͅleͅbi reͅ ko tii leͅyin

Teͅleͅri Lil Prince ni Inagijeͅ reͅ ko to yipada si Wizkid, abi Big Wiz abi Machala.