Èdè Yorùbá: Àjọ̀dún àádọ́ta ọdún Ẹgbẹ́ Akọ́mọlédè àti Àṣà Yorùbá Nàìjíríà

Awọn ọmọ ẹgbẹ Akọmọlede ati aṣa Yoruba

Ayẹyẹ lati dawọọ Ẹgbẹ Akọmọlede ati Aṣa Yoruba Naijiria ti wọn da ẹgbẹ ọhun silẹ.

Ilu Kabba nipinlẹ Kogi ni eto naa ti bẹrẹ lọjọ karun un oṣu kẹjọ, eto yii yoo tẹsiwaju di ọjọ kẹjọ oṣu kẹjọ ko to kasẹ nilẹ.

Aarẹ ẹgbẹ naa ninu ọrọ ikini sibi ipade naa fawọn oloye ẹgbẹ lami ẹyẹ fun iṣẹ takuntakun ti wọn ti ṣe.

Wọnyi ni diẹ lara aworan to ṣapejuwe bi eto naa ṣe lọ niluu Kabba nipinlẹ Kogi

Ẹgbẹ akọmọlede ati aṣa Yoruba
Awọn ọmọ ẹgbẹ Akọmọlede ati aṣa Yoruba
Ọmọ ẹgbẹ akomolede ati aṣa Yoruba
Awọn ọmọ ẹgbẹ Akọmọlede ati aṣa Yoruba
Awọn oloye ẹgbẹ gba ami ẹyẹ
Awọn ọmọ ẹgbẹ Akọmọlede ati aṣa Yoruba