Ìjàmbá oͅkòͅ wáyé sí oͅkòͅ abeͅnugan ilé ìgbìmòͅ asͅòfin Oyo

Aworan

Oríṣun àwòrán, OTHERS

Ijamba oͅkoͅ ti waye peͅlu oͅkoͅ to n gbe abeͅnugan ile igbimoͅ asͅofin nipinleͅ Osun, Hoͅnoͅrebu Timothy Owoeye.

Ijamba oͅkoͅ naa waye ni opopona Osogbo si Ilesa nibi ti oͅkoͅ to n boͅ lati iha keji yi kuro ni oͅna reͅ to si loͅ koͅlu oͅkoͅ abeͅnugan naa.

Oͅpoͅloͅpoͅ awoͅn to wa ninu oͅkoͅ naa lo fi ara pa, ti woͅn si gbe woͅn loͅ si ileewosan UNIOSUN ati ileewosan to wa ni ile igbimoͅ asͅofin fun itoͅju to peye.

Ikoͅlu naa ti da sunkeͅreͅ fakeͅreͅ oͅkoͅ sileͅ loju popo nitori awoͅn oͅkoͅ to ni ijamba oͅkoͅ naa wa ni oju popo.