Yorùbá films: Iya Rainbow di ònílé tuntun, ilé méjì ni wọ́n fi ta á lọ́rẹ

Oríṣun àwòrán, Iya Rainbow
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Agba osere Yoruba, Idowu Phillips, ti ọpọ eeyan mọ si Iya Rainbow tun ti di onile tuntun.Ọsẹ to kọja ni osere naa kede loju opo Instagram rẹ pe ileesẹ kan lo fi ile fulaati meji ta oun lọ rẹ ni agbegbe Mowe, nipinlẹ Ogun.Koda, o ni wọn tun fi orukọ oun sọ opopona kan ninu esiteeti aladani naa.
Skip Instagram post
Allow Instagram content?
Warning: Third party content may contain advertsThis article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of Instagram post
- Ìsìnkú Kashy Godson tí wọ́n fẹ̀sùn ikú rẹ̀ kan Barry Jhay ti wáyé lónìí ọjọ ìbí rẹ̀
- Àjẹ́ àti Aṣẹ́wó ní ìyá Rainbow - Òjòpagogo
- Nígbà tí èmi náà rí fídíò Kashy tí ẹnu rẹ̀ ń ṣẹ̀jẹ̀ ṣáájú ọjọ́ tó kú, mo bèrè àwọn ìbéèrè kan - Ẹ̀gbọ́n Barry Jhay
- Báwo ni Barry Jhay ọmọ Alhaji Sikiru Ayinde Barrister se kó sí gbaga ọlọ́pàá?
- Wòlíì Kasali gba Bunmi ìyàwó rẹ̀ àkọ́fẹ́ padà, ìjà parí!



















