Coronavirus Update: Báwo lo ṣe leè mọ Oogùn apakòkòrò 'Sanitizer' tó jẹ́ ayédèrú?

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Oogun apakokoro lọwọ ti oloyinbo n pe ni "Hand Sanitizer" ti di ja pataki lori igba bayii koda o ti di nkan pataki to gbud wa lapo rẹ nibikibi too ba n lọ nitorii arun Coronavirus.
Ṣugbọn ọna ati mọ awọn eyi to jẹ ayederu too ba ri i lori igba ṣe pataki lasiko yii nitori pe ileeṣẹ awọn apoogun orilẹede Naijria to n ṣe iwadii ati idagbasoke (NIPRD) ni ida mẹtalelọgọta oogun apakokoro to wa ni ilu Abuja nikan tii ṣe oluulu orilẹede yii ni kii ṣe ojulowo.
Eyi waye gẹgẹ bi orilẹede Naijiria ṣi ṣe n ba arun coronavirus finra eyi to ti mu ẹgbẹrun marunlelọgbọn o din diẹ to si ti pa eniyan to din diẹ lẹgbẹrin titii ọjọ Ẹti ọjọ ikẹtadionlogun oṣu keje ọdun 2020.
Ajọ eleto ilera lagbaye, WHO lo fi ontẹ jan lilo oogun apakokoro lati le maa pa awọn kokoro to ba wa lọwọ lasiko ti ko ba si ọṣẹ ati omi larọwọto.
Ṣugbọn lilo oogun apakokoro nikan ko to lati dena arakan arun gẹgẹ bi awọn onim ṣe sọ ọ. Wọn gba awọn eeyan nimọran lati maa tẹle ilana eto ilera eyi to fi mọ lilo iboju-bomu nigboro, fifi ọṣẹ ati omi fọwọ ati jijinasiraẹni.
Ggẹ bi iroyin ti ileeṣẹ to n ri si eto ilera lorilẹede Naijiria fi sita nipa awọn oogun apakokoro, wọn ni beeyan ba bọ sọja lati ra a, o ni lati la oju rẹ daadaa lati wo o boya oogun apakokoro naa ni awọn nkan wọnyii:
- Wo o boya Sanitaisa ti wọn ta fun ni ọjọ ti wọn ṣe e lara ati ọjọ ti ọjọ ori rẹ yoo tan. Bi ko ba ti ni, gbargudu ni wọn gbe le ọ lọwọ.
- Wo o boya sanitaisa ọhun ni iye ọti to to ida ọgọta nin. Bi ko ba ti ni, irọ nla gbaa ni.
- Wo o daadaa boya sanitaisa hun ni nọmba aj NAFDAC. Boo ba ri i nibẹ, o ti gba fa fa fa "fao"
- Wo beba tabi ọra ti wọn lẹ mọ ọ lara. Bi ko ba dun un wo loju, wọn ti gba ọ niyẹn o!
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post
- Àwọn ọ̀dọ́ ilẹ̀ Yoruba kò gbọdọ̀ gbàgbé àṣà ati ohun àdàyébá wọn - Ooni Ile Ife
- Eruku sọ lálá níbi ayẹyẹ ìgbéyàwó Lizzy Anjorin, àwòrán àti fídíò nìyíì
- Orin ìsìn ọjọ́ ìbí àṣẹ̀yìndè Ibidunni Ighodalo yóò wáyé, Tope Alabi, Kenolly àtàwọn míì tí yóò kọrin níbẹ̀ rèé
- Gbọ́ ọ̀rọ̀ lẹ́nu afurasí tí Ọlọ́pàá ní ó pa Barakat Bello, Grace Oshiagwu àtàwọn míì l'Akinyele Ibadan










