Chloroquine: Àwọn oníṣègùn òyìnbò ní China sọ pé Coronavirus o le duro wo tan

Oríṣun àwòrán, Other
Ọrọ yii da bi ọrọ iwe mimọ to sọ pe ''okuta tawọn ọmọle kọ silẹ, lo di pataki igun ile.
Oogun iba to wọpọ nilẹ Afirika, papaa julọ lorilẹede Naijiria ni bi ogun ọdun si ọgbọn sẹyin, Chloroquine phosphate ni awọn onimọ iṣegun ti sọ pe, oogun naa ṣiṣẹ fun itọju aarun Coronavirus to n tan kalẹ kaakiri.
Ẹka ijọba imọ ijinlẹ ati imọ ẹrọ lorilẹede China lo sọ pe, oogun Chloroquine ṣiṣẹ daadaa lara awọn to ni aarun naa tawọn ti danwo lara wọn.
- Coronavirus: Ó dá mi lójú pé ìwá ìbàjẹ́ ló fa àrùn yìí - Ọ̀gá àgbá EFCC
- Ṣé lóòtọ́ọ́ ni Adìyẹ Broiler ń fa àìsàn Coronavirus?
- Ọkọ̀ dáńfó tí mò ń wà ní mo fi kọ́lé, rán ọmọ mẹ́ta ní fásitì - Obìnrin àkọ́kọ́ tó ń wa dáńfó l‘Eko
- Olúbàdàn, ẹ bá wa bẹ́ Seyi Makinde kó tú wa sílẹ̀ - Oyo NURTW
- Lẹ́yìn ọdún mẹ́wàá, Tokyo àti Auxillary ṣèpàdé bòńkẹ́lẹ́
- NURTW yóò fikùnlukùn pẹ̀lú Gómìnà Makinde láìpẹ́
- Akẹ́kọ̀ọ́ fásitì Ebonyi ló kó iba Lassa wọ Eko
- Ìhàlẹ̀ lásán ní NURTW ń ṣe torí pé a dínà owó tí wọn ń kó sápò - Ìjọba Ọyọ
Awọn onimọ iṣegun oyinbo lo Chloroquine fun itọju iba fun ọpọlọpọ ọdun, ki o to di pe oogun naa ko ran awọn kokoro to maa n fa aisan iba mọ.
Loju opo Twitter COVID-19 ti wọn ti n dawọn eeyan lohun lori aarun coronavirus, wọn sọ nipa oogun Chloroquine pe o n dena aarun coronavirus.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1

Oríṣun àwòrán, Reuters
Iroyin to tẹ wa lọwọ lati orilẹede China fidi rẹ mulẹ pe, awọn dokita onimọ iṣegun ti dan oogun naa wo lara awọn to laarun coronavirus nile iwosan mẹwaa, wọn si ri pe o ṣiṣẹ daadaa.
Ẹwẹ, onimọ kan nipa oogun oyinbo to ba BBC sọrọ ṣalaye pe bo ya oogun Chloroquine le ṣiṣẹ fun aarun coronavirus tabi bẹẹ kọ, ajọ eto ilera lagbaye(WHO) ati ajọ ilẹ Amẹrika to n ṣakoso ounjẹ lo le sọ.
Ohun ti ajọ ilera lagbaaye sọ ni pe o ṣeesẹ ki oogun aarun coronavirus jade ni bii ọdun kan aabọ si akoko yii.
Nibayii, oju opo Twitter ti n yeruku lala lori iroyin pe oogun Chloroquine dara fun itọju aarun coronavirus.
Ọpọ lo dunnu si iroyin naa, bakan naa ni wọn ṣe iranti bi wọn ti maa n loogun ọhun fun itọju aarun iba lati ọjọ to ti pẹ.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 2

End of X post, 3

End of X post, 4
Harry Obi ni tiẹ sọ pe, ta lo lo ro pe oogun Chloroquine le ṣe itọju coronavirus, o ni o daju pe, awọn dokita oniṣegun oyinbo yoo tun ni oogun naa nitori wọn ti lo ọpọ rẹ fun itọju aarun iba tẹlẹ.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 5
Ọgbẹni Adekunle ni ta lo mọ boya oogun Flagyl gan le ṣe itọju aarun HIV lẹyin tawọn onimọ iṣegun ti sọ pe, Chloroquine dara lati koju corona virus.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 6

End of X post, 7

End of X post, 8