Female Driver: Sokunbi ni obìnrin àwakọ̀ Dáńfó l‘Eko, tó ń lọ̀ láti ìpínlẹ̀ kan sí òmíì
Yoruba ni ohun ti ọkunrin lee se, awọn obinrin gan lee se ju bẹẹ lọ, idi isẹ ẹni si laa ti mọ ni lọlẹ.
Folasade Sokunbi, tii se awakọ danfo akọkọ to n na ipinlẹ kan si omiran salaye fun BBC Yoruba pe, awọn ẹbi, ara ati ọrẹ tako isẹ naa nibẹrẹ, amọ oun ko gba fun wọn.
- Ṣé lóòtọ́ọ́ ni Adìyẹ Broiler ń fa àìsàn Coronavirus?
- Oyè Ibadan kò sí fún títà - Otun Olubadan, Lekan Balogun
- Àbòsí ló wà níbẹ̀ tí ìpínlẹ̀ Eko ò bá ṣe Amotekun- Bode George
- BBC Yorùbá pé ọdún méjì! Ẹ wò wá ẹ wo iṣẹ́ ọwọ́ wa
- Àwọn adigunjàlè pà òṣìṣẹ́ Aso Rock l’Abuja
- Anthony Joshua gba nọ́mbà ìdánimọ̀ NIN, àwọn ọmọ Nàìjíríà kan kérora lórí ètò náà
- Coronavirus: Ó dá mi lójú pé ìwá ìbàjẹ́ ló fa àrùn yìí - Ọ̀gá àgbá EFCC
- Àwọn ìgbà tí ìmọ̀ràn Pásítọ̀ Adeboye lóri igbéyàwó ti fa àríyànjiyàn
Sokunbi ni isẹ asejere ni isẹ danfo wiwa, bi o tilẹ jẹ pe ko rọrun rara, sibẹ, oun fẹ di ọga nla.









