UFC245: Kamaru Usman, f'ẹ̀ṣẹ́ borí ààyò Trump, Colby Covington ní ìjà UFC

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Bii bara ni abẹṣẹkubiojo ọmọ orilẹede Naijiria, kamaru Usman lu Colby Covington ti wọn jọ koju ija lowurọ ọjọ aiku lati ṣi wa nipo to ni akọle rẹ, welterwwight ni idje UFC 245.
Ija naa waye ni gbagede T-Mobile Arena ni Las Vegas, orilẹede Amẹrika.
Laarin idije ija naa, bi Colby ṣe n ta a ni Kamaru n gbakuru mọ ọ koda o tun fi ẹṣẹ fọ Colby leyin isalẹ ti gbogbo oju rẹ si kun fun ẹjẹ.
Lati idaji ni gbogbo eniyan lori ayelujara ti n reti ohun ti ija yii yoo bi.
Ni bayii, Kamaru náà ni yóò tún jẹ́ ọmọ Afíríkà àkọ́kọ́ tó fẹ̀ṣẹ́kùbíòjò gbaigbanu ẹyẹ idije Ultimate Fighting Championship.
Ni kete ti
Covington could barely stand to listen to Usman's victory speech, charging out of the Octagon to the back as soon as the Nigerian's hand was raised.
But even in defeat, "Chaos" established himself as one of the greatest fighters on the planet with an excellent display that will surely still see his stock rise.
It was an extremely close fight that could have gone either way had it gone the distance, as both men met in the middle of the Octagon and traded blows from start to finish, eschewing their world-class wrestling abilities in favour of an all-out brawl.
But Covington's fortunes changed when Usman broke his jaw at the end of the third round with a hard right.













