RuizJoshua2: Anthony Joshua di akànṣẹ́ kẹrin nínu ìtàn tí yóò gba ogo rẹ̀ padà lẹ́yìn tó sọ ọ́ nù

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Awọn odu akanṣẹ ti wọn ti padanu igbanu ẹyẹ wọn ṣugbọn ti wọn tun gba a pada niwọnyii:
Muhammed Alli: ni ọjọ karundinlogun oṣu keji ọdun1978, Muhammed Ali sọ igbanu ẹyẹ rẹ nu fun Leon Spinks .
Lẹyin oṣu meje, Ali pada wa gba a pada. Oun si ni akọkọ akanṣẹ ti yoo gba ogo Akanṣẹ agba, heavyweight nigba mẹta lagbaye.
Lẹnnox Lewis: ni ọjọ kejilelogun ọdun 2001, Hasim Rahman ya agbaye lẹnu nigba to na Lennox Lewis to jẹ odu akanṣẹ nigba naa. Rahman gba igbanu ẹyẹ WBC, IBF ati IBO lọwọ Lewis nibi ija wọn to waye lorilẹede South Africa.
ṣugbọn ni atunja ija wọn to waye lẹyin oṣu meje, Lewis fọ lẹnu tan yanyan ni Las Vegas.
Evander Holyfield: Holyfield padanu igbanu ẹyẹ WBA, IBF ati Lineal sọwọ Micheal Moorer eleyii to ya ọpọ ololufẹ ẹṣẹ kikan lẹnu.
Lẹyin to gba ẹyẹ lọwọ Holyfield, George Foreman to jẹ Ọmọ ọdun marunlaadọta nigba naa ni Moorer gba lati ba ja ṣugbọn Foreman naa bi ejo aijẹ.
Ni ọjọ kọkanla ọdun 1997 ni Holyfield ati Moorer wa ja papda. Ni asiko ti a n sọ yii, Holyfield ti gba igbanu WBA rẹpada nigba to lu Mike Tyson ni igba meji ọtọọtọ. Moorer ni tirẹ gba igbanu IBF to ṣofo lasiko naa nigba to fi na Axel Schulz
Nítorí Anthony Joshua borí, Keyamọ fori kó 'ẹsẹ lórí twitter Buhrai, Atiku ko dakẹ

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Kii ṣe iroyin mọ pe Anthony Joshua ti gba igbanu ogo rẹ pada lẹyin to bori Andy Ruiz ninu idije ẹṣẹ kikan to waye ni lu Riyadh ni Saudi Arabi lọjọ Abamẹta.
Amọṣa bi awọn eeyan loniranran ṣe n kii ku oriire, ẹnu o gba iroyin ohun ti awọn ọmọ Naijiria kan fi oju Minisita keji fun ọrọ oṣiṣẹ ati idaleeṣẹ silẹ, Festus Keyamọ ri loju opo twitter rẹ kọja sisọ o.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1
Gẹgẹ bi gbogbo awọn ololufẹ Anthony Joshua naa ni amofin Keyamọ kii loju opo twitter rẹ, ṣugbọn kaka ki wọn dara pọ mọọ lati dawọ idunnu naa, ọrọ alufansa ni wọn fi daa lohun.
Akọkọ ẹni to daa lohun ni eeyan kan to lo orukọ Bigdaddy terry @terry_abiola lo kọkọ dahun pe 'Sọrọ nipa DSS, ẹgbọn, maa sọrọ nipa AJ
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 2
Ọgbẹni kan labẹ orukọ @calabar_virgin pẹlu bi Keyamo leere pe ṣe kii ṣe pe o fẹ ka iṣẹgun AJ ku ara aṣeyọri aarẹ Buhari. Bẹẹ loun pẹlu tun beere Sowore.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 3
Eyi ni awọn ọrọ miran tawọn ọmọ Naijiria sọ si Keyamo lori:
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 4

End of X post, 5

End of X post, 6

End of X post, 7

End of X post, 8
Ẹwẹ Aarẹ Buhari, igbakeji aarẹ tẹlẹ, Alhaji Atiku Abubakar ti ranṣẹ ikini ku oriire si Anthony Joshua,
Koda Sẹnetọ ana, Dino Melaye gan ko gbẹyin
Ninu ọrọ tirẹ, Aarẹ Buhari gbosuba fun un pe o ja igbanu ẹyẹ rẹ gba pada lọwọ Andy Ruiz.
Ni tirẹ, Alhaji Atiku Abubakar ni ohun to dun mọ ni lodo ikun ju guguru oloyin lọ
Ni pe AJ gba ipo rẹ pada.
Patí oṣù mẹ́ta tí mo ṣe ló jẹ́ kí Anthony Joshua fọ́ mi lẹ́nu-Andy Ruiz

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Anthony Joshua ti gba igbanu ẹyẹ abẹṣẹkubiojo to gbayii julọ lagba fun ipele WBO, WBA, ati IBF pada lọwọ ẹni to doju rẹ kọ orun alẹ ni nnkan bii oṣu mẹfa sẹyin, iyẹn Andy Ruiz.
Iṣọwọ ta bi ẹṣin rẹ pẹlu bi o ṣe n kan ẹṣẹ ni ki-ki loju agba ko jẹ ki Ruiz raye ṣe irufẹ ọṣẹ ti o ṣe fun un ni osu mẹfa sẹyin.
Ni tirẹ, Andy Ruiz tọrọ aforiji lọwọ olukọni rẹ, Manny Rabbles fun jija a kulẹ.
- DJ Cuppy gbóṣùbà ràbàndẹ̀ fún Anthony Joshua ṣáájú ìjà rẹ̀ pẹ̀lú Andy Ruiz
- Ajíyìnrere àgbáyé Reinhard Bonnke jẹ́ Ọlọ́run nípè
- Òkété ti bórù! Manchester United fọ́ Manchester City lẹ́nu pẹ́tẹpẹ̀tẹ mọ́lé
- Ọlọ́pàá, adájọ́ àtàwọn aṣọ́bodè ló gba rìbá jùlọ ní Nàìjíríà-NBS
- Ìròyìn nípa ìyàwó túntún fún ọkọ mi kò mì mí lọ́kàn rárá-Aisha Buhari
Bakan naa ni Ruiz ṣalaye fawọn akọroyin peode lilọ lalọju lo koba oun. O ni ode ariya gbogbo ti oun lọ fun oṣu mẹta laisimi dipo ki oun tete maa gbaradi lo ṣakoba fun oun nitori oun ti wa sanra asanju ṣaaju ija naa.
Agbawọlẹ ni ti eekan ni Anthony Joshua fi ija naa ṣe nitori gbogbo awọn onidajọ lewaju ija naa ni wọn gbe idajọ kalẹ pe AJ lọwọ rẹ moke juls nigba ti ija naa fi ti ẹnu bodo ni randi kejila.
Njẹ a lee pe e ni ija ẹṣẹ kikan to dun julọ ninu itan bi? Rara, ṣugbọn kii ṣe eyi ti ko mu gbogbo awọn to wo o maa da omi ẹni nitori awogbadun rẹ.
Anthony Joshua ka batani ẹṣẹ fun Ruiz daradara.
"Lakọkọ mo fẹ dupẹ lọwọ Ọlọrun" ni ọrọ ti Joshua fi bọnu nigba to n ba awọn oniroyin sọrọ lẹyin ija naa. "Bakan naa ni mo tun fẹ sọ pe eeyan bii temi ko nilo awawi, ọmọ mi (Dereck) Chisora sọ fun mi pe bi mo ba fẹ bori ninu ija yii mo gbọdọ ṣetan lati ku."
Amọ o, eyi ni ohun ti awọn ọmọ Naijiria kan n sọ lori twitter nipa ija ọhun.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 9

End of X post, 10

End of X post, 11

End of X post, 12

End of X post, 13

End of X post, 14

End of X post, 15

End of X post, 16