Sudan: Wọ́n ti ti gbogbo ilé ìwòsàn pa, ọ̀pọ̀ èèyàn ń sá káàkiri ní báyìí nítorí ìkọlù àwọn darandaran ní agbègbè Massalit

Oríṣun àwòrán, EPA
Ìjà tún ti bẹ́ sílẹ̀ ní agbègbè Darfur, ní Sudan
Igba akọkọ kọ niyii ti awọn Arabu darandaran ati awọn ara agbegbe Massalit ti n koju ara wọn nipa ọrọ ilẹ.
Iroyin ni laasigbo tun ti bẹ silẹ ni ilu El Geneina, ni Darfur lorilẹede Sudan, ti iye eniyan to le ni igba si ti ba iṣẹlẹ naa lọ.
- Olórí ìgbìmọ̀ aláṣẹ́ tó ga jù ní Sudan, Ọ̀gágun Burhan ti kéde ìlú ò fararọ
- South Sudan ṣì ń ṣẹ̀jẹ̀, àwọn orílẹ̀èdè alámùúlétì rẹ̀ figbe ta
- Wahala iyan rọ dẹdẹ sori South Sudan
- Ó lé ní ọgọ́rin èèyàn tó kú nínú ìjà ẹlẹ́yàmẹ́yà tó wáyé ní Dafur- Aláṣẹ Sudan
- Ìjọba Amẹrika yọ orúkọ Sudan kúrò nínú ìwé orílẹ̀-èdè tó ń ṣagbátẹrù ẹgbẹ́ agbésùnmọ̀mí
- Sudan bẹ Ààrẹ Trump pé kó yọ ọ́ kúrò nínú àwọn orílẹ́-èdè agbésùnmọ̀mí
- Ète ìdìtẹ̀ gbàjọba forí sánpọ́n ní Sudan
Iroyin ni opin ọṣẹ ni iṣẹlẹ naa waye pẹlu iro ibọn lakọlakọ.
Igba akọkọ kọ niyii ti awọn Arabu darandaran ati awọn ara agbegbe Massalit ti n koju ara wọn nipa ọrọ ilẹ.
Ni Ọjọ Isinmi ni awọn agbebọn ikọ Janjaweed militia ti wọn ni atilẹyin awọn ikọ ologun ti wọn n pe ni Rapid Support Force koju ija si ilu El Geneina.
Ẹgbẹgbẹrun eniyan to n gbe agbegbe yii lo sa kuro ni ile wọn lasiko ogun Darfur to waye ni nkan bi ogun ọdun ṣẹyin.

Oríṣun àwòrán, @Bundaswetv
Nibo ni ọrọ ogun de duro ni Ukraine?
Germany gbé ìgbésẹ̀ láti fi ọkọ̀ ogun sọwọ́ sí Ukraine láti kojú Russia
Germany dá sí ìjà Russia àti Ukraine, yóò fi ohun ìjà ogun sọwọ́ sí Ukraine
Orilẹ-ede Germany ti kede erongba rẹ lati fi ohun ija ogun ṣọwọ si orilẹ-ede Ukirane fun iranlọwọ lẹyin ogun ti Russia gbe tii.
Iroyin ni Germany ti ṣetan lati fi awọn ọkọ ti wọn maa n gbe ibọn le lori ranṣẹ si Ukraine lọna ati le koju ogun Russia.
Ọrọ yii lo n jade lẹyin ipade eto abo to waye laarin awọn adari eto abo EU ati Nato.
- Látàri ìjà Russia àti Ukraine, Bí a ṣe fẹ́ dènà ìyàn oúnjẹ ní Naijiria rè é- Buhari
- Kíni àjọ ECOWAS ilẹ̀ Adúláwọ̀ ń sọ báyìí lórí ìjà Russia àti Ukraine?
- Wo ìdí pàtàkì mẹ́ta tí Russia se kọlu Ukraine
- Russia ń kọlu àwọn iléèwé àti iléèwòsàn - Ukraine
- Wọ́n ti ṣe ìsìnkú àpapọ̀ fún èèyàn 50 lára àwọn tó jóná níbúdò ìfọpo tó gbiná ní Imo
- Óṣe! Àwọn ọmọdé mẹ́rin pàdánù ẹ̀mí wọn bí wáyà iná ṣe já lé wọn lórí
- Emmanuel Macron borí Le Pen ní ìbò ààrẹ France
- Kíni àjọ ECOWAS ilẹ̀ Adúláwọ̀ ń sọ báyìí lórí ìjà Russia àti Ukraine?
- Wo àwòràn ohun tó sẹlẹ̀ ní UKraine
Ireti wa pe minisita eto abo Germany, Christine Lambrecht, yoo ṣalaye lori bi eto naa yoo ṣe lọ laipẹ.
Bo tilẹ jẹ pe wọn ko tii sọ bi wọn yoo ṣe fi awọn ohun ija ogun naa ranṣẹ, amọ eyii yoo jẹ igba akọkọ ti Germany yoo fi ohun ija ogun ṣọwọ si Ukraine.
Ṣaaju ni awọn kan ti kọkọ n bu ẹnu atẹ lu Germany pe o kọ lati fi ohun ija ogun ṣọwọ si Ukraine gẹgẹ bii ilẹ Amẹrika, ilẹ Gẹẹsi atawọn orilẹ-ede mii to wa lẹyin Ukraine ṣe ṣe ṣaaju.
- 'Aláàfin ti rí ikú rẹ̀ ṣáájú ọjọ́ tó wàjà, ó sọ̀rọ̀ sílẹ̀ kó tó kú'
- Wo àwọn òrékelẹ́wà tí yóò ṣe opó lẹ́yìn Aláàfin Oba Adeyemi tó papòdà
- Ìgbẹ́jọ́ Ilànà Ọmọ oodua àti Náìjíríà ti bẹ̀rẹ̀ nílé ẹjọ́ ní Ekiti
- 'Ẹran ẹtu ni mo yìnbọn sí, àmọ́ òkú ìmáàmù ni mo bá nígbà tí mo fẹ́ gbe e'
- Ẹ yé fi ìpapòdà àwọn lọ́balọ́ba ìpínlẹ̀ Oyo kọmi lọ́rùn - Gómìnà Seyi Makinde
- "Kòríkòsùn lèmi àti Alaafin ṣùgbọ́n kété táwọn kan kẹ́ẹ́fín pé èmi láàyò ni gbogbo nǹkan dojúrú." Badirat Ajoke, olorì tẹ́lẹ̀ kẹ́dùn Alaafin
- Wo ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ sí àwọn olòrì Alaafin Adeyemi àtàwọn tó bá fẹ́ fẹ́ wọn
- Mo ti gbà báyìí pé ohun gbogbo tó n dán kọ́ ni wúrà - Olori Badirat Adeyemi
- Ìjọba àpapọ̀ ṣí ẹnubodè Idiroko àti àwọn mẹ́ta mìíràn, wo ohun tí BBC bá bọ̀ níbẹ̀
Germany ti sọ pe, yatọ si awọn ọkọ to ni ibọn lori yii, awọn yoo tun fi ọgọrun awọn ọkọ mii ti wọn n lo loju ogun sọwọ si Ukraine.
Ẹwẹ, nitori ogun ti Russia gbe ti Ukirane, Germany ti ṣe afikun iye owo to la kalẹ fun eto iṣuna ẹka eto abo rẹ pẹlu ọgọrun billiọnu euro.














