Ukraine and Russia Crisis: Wo àwòràn ohun tó sẹlẹ̀ ní UKraine

Die lara awon isele to sele ni Ukraine ni yii pelu aworan.

Ukraine ati Russia
Àkọlé àwòrán, Awon ọmọ ogun UKraine ree lẹ́gbẹ̀ẹ́ mọ́to to baje lasiko ti wọ́n n ja pẹ̀lú awọn omo ogun Rusia
Ukraine ati Russia

Oríṣun àwòrán, NADOLU AGENCY / GETTY IMAGES

Àkọlé àwòrán, Ile gogoro nitsi Kyiv ni papako ofurufu Zhuliany nibi ti ado oloro kan ti bugbamu lọ́jọ́ Abameta
Ukraine ati Russia

Oríṣun àwòrán, NADOLU AGENCY / GETTY IMAGES

Àkọlé àwòrán, Asoju ẹkun Kyiv, Vitali Klitschko ked konile-o-gbele ni olu ilu Ukraine lati aago marun un ojọ́ kerindinlogun, osu keji si aago mẹ́jọ́ lojo kejidinlogun.
Ukraine ati Russia

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Aworan to n safihan ile gogoro ti aown eeyan n gbe tẹ̀lẹ́ sugbon ti ado oloro ti ba ipele meje nibẹ̀ ni egbẹ́ kan..
Ukraine ati Russia

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Awon osise alaabo to n mojuto isllẹ̀ pajawiri lenu ise won ni Ukraine leyin ikolu RussiA
Ukraine ati Russia

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Aworan to n safihan awon ibudo ikolu nibi ti ado oloro ti sose nile gogoro laarin aja marun un akoko
Ukraine ati Russia

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Awon eeyan ti wọ́n sa pamọ̀ si lasiko ti oko ofurufu n da ado oloro lati oju orun nitosi ile ti won ti baje
Ukraine ati Russia

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Opo igba ni ọ̀rọ̀ naa di oju ọ́lamọ́ ko too nigba ti omo ogun Russia gbiyanju lati dana ogun wọ́ aarin awọ́n omo ogun Ukraine ki won le wo inu ilu naa tan.
Ukraine ati Russia

Oríṣun àwòrán, NADOLU AGENCY / GETTY IMAGES

Àkọlé àwòrán, Awon eeyan n sa kuro ni ekun Zhuliany ni Kyiv ti won si n lo fori pamo sibo mii
Ukraine ati Russia

Oríṣun àwòrán, NADOLU AGENCY / GETTY IMAGES

Àkọlé àwòrán, Awon omo ogun Ukraine lasiko ti wọ́n n daabo bo enu ibode lati wo ekun wọ́n ki awon Russia ma baa le wọ́ olu ilu Ukraine