Senato Francis Fadahunsi: Ká ni wọ́n fún Buhari lọ́dún mẹ́wàá sẹ́yin ní, bóyá kò bá rí i ṣe

Àkọlé fídíò, Senato francis Fadahunsi: Ká ni wọ́n fún Buhari ladún mẹ́wàá sẹ́ypin ní, bóyá kò bá rí i ṣ

Buhari kó ní agbárà mọ́, òun kọ́ ló ń ṣe ìjọba- Senato Francis Fadahunsi

Opo awọn ọmọ Naijiria lo ti n sọrọ ibi ti eto aabo Naijiria de duro labẹ iṣẹjọba aarẹ Buhari yii.

Senato Francis Adenigba Fadahunsi n ṣoju awọn ekun ipinlẹ Osun labẹ asia ẹgbẹ oṣelu PDP nile igbimọ aṣofin agba ni Abuja.

Fadahunsi

Oríṣun àwòrán, @fadahunsi

O ni pe agba ti de fun Buhari ni awọn to yii ka ṣe n baa ṣe ijọba rẹ.

O tun ṣalaye pe adura lo ku lasiko yii pẹlu awọn igbese akin.

Fadahunsio ni ọ̀rs Afghanista ti kọ awọn oloselu lọgbọn pe ko seni ti ko le gba ijọba.

O ni 'Rebel' le gba ijọba ti agbofinro ba dawọ silẹ bi o ṣe n ṣẹlẹ laisko yii ni Naijiria.

Fadahunsi salaye ọna abayọ lori ọrọ awọn ṣọja ati ipa to yẹ ki onikaluku ara ilu ati akọroyin ko fun idagbasoke Naijiria lai yọ oloselu kọọkan silẹ.