Babatunde Gbadamosi: Mo ta gbogbo dúkìá mi lásìkò kan kí ń tó padà di eèyàn lónìí
Ojú Iya Jadesola Akande ri tó lọwọ awọn ọlọpaa kogberegbe ni LASU ni 1989- Babatunde Gbadamosi
Oju ẹni ma la a ri to .... ni ọrọ awọn agba Yoruba.
Oludije dupo gomina nigba kan ri ni ipinlẹ Eko to tun jẹ gbajugbaja onisowo to n kọ ile gbigbe ta fun awọn eeyan ba BBC Yoruba sọrọ lori ọna atila awọn ọdọ.
- Kò tíì tó àsìkò pé kí Nàìjíríà pín ṣùgbọ́n...- Olowu ilẹ̀ Kuta
- Wo ohun tó fẹ́ mú kí àwọn aṣòfin Ogun fi ọlọ́pàá mú 'ọba aládé' kan ní Ijebu
- "Ìgbẹ̀yìn Naijiria yóò burú ju ti Afghanistan lọ tíjọba kò bá dẹ́kun ẹlẹ́yàmẹ̀yà"
- Èyí lohun tí Amòfin àgbà Nàìjíríà, Malami sọ níléẹjọ́ lónìí nípa àjọṣepọ̀ rẹ̀ pẹ̀lu Fulani àti ìkọlù tó wáyé nílé Igboho
- Ayédèrú sọ̀wédowo lọ̀gá àgbà ọlọ́pàá fún wa, pọ́ún ló ń ta bí a bá múu dé báǹkì
Babatunde Gbadamosi ti ọpọ mọ si Onisowo ile ọlọpọ eero ni ipinlẹ Eko mẹnuba bi irinajo rẹ se bẹrẹ nile ẹkọ giga fasiti LASU to jẹ Lagos State University.

Oríṣun àwòrán, others
O sọ nipa ohun ti oju awọn akẹkọọ ri lọwọ awọn ọlọpaa kogberegbe 'Mopol' nigba naa.
Gbadamosi sorọ nipa iya Jadesola Akande to jẹ adari ileẹkọ LASU ni 1989 naa jẹ ṣege iya ainidii lọwo awọn agbofinro ọhun.
- Àjọ SERAP gbé Buhari lọ sílé ẹjọ́ lórí N106bn tí wọ́n ló d'àwátì láwọn ilé iṣẹ́ ìjọba
- Àwọn jàndùkú afẹ̀mí-ṣòfò ṣekúpa èèyàn 24 ní Kaduna àti Katsina lọ́jọ́ kan ṣoṣo
- Kí ló lè mú ìjọba pàṣẹ pé kí wọ́n ka gbogbo ẹranko igbó àti ẹja inú omi?
- Àwọn ajínigbé tú àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ Bethel mẹ́ẹ̀dọ́gún míràn sílẹ̀