Unijos students victims: 'Àwọn Fulani yabo 'hostel' wa, ọpẹ́lọpẹ́ àwọn Sọ́jà tí gómìnà Lalong rán wá pèsè aàbò fún wa kó tó pẹ́ jù'

Àkọlé fídíò, Unijos students victims: Àwọn Fulani yabo 'hostel' wa, ọpẹ́lọpẹ́ àwọn Sọ́jà tí gómìnà ìpí

A dupe pe ori ko wa yọ, a ko mọ ibi ti ọpọ akẹkọọ ṣi wa- Aarẹ UNIJOS

Awọn akẹkọọ ipinlẹ Oyo ba BBC sọrọ lori ohun to ṣẹlẹ si wọn ni Jos.

Kolawole Adedokun to jẹ aarẹ wọn sọrọ ilẹ kun.

jos

Ogunlowo Samuel sọ bi awọn Fulani ṣe wa kọlu wọn ni nu ile egbe wọn .

O sọ bi wọn ṣe jajabọ pẹlu iranlọwọ awọn sohja ti gomina Lalong ran wa sibẹ.

jos

Adesokan Afeez naa sọ diẹ lara ohun to ju awọn akanda ẹda ri to nipinlẹ Plateau.

Gbogob awọn akẹkọọ naa fi ayo han pe awọn apda sile pẹlu iranlọwọ moto akero ti gomina Seyi Makinde fi ranṣẹ si wọn.

Wọn tun sọ pe ọpọ ninu awọn akẹkọọ ni wọn ko tii ri titi di asiko yii to jẹ ọmọ Yoruba nilẹ Hausa.