Nítorí kí Aafa lè máa rí iṣẹ́ ṣe ní wọ́n kò ṣe kó Alumaajiri nílẹ̀ tó fi di ohun tó dà yìí- Olagunsoye Oyinlola

Àkọlé fídíò, Nítorí kí aafa lè máa rí iṣẹ́ ṣe ní wọ́n kò ṣe kó Alumaajiri nílẹ̀ tó fi di ohun tó dà yìí

Wo ọ̀nà àbáyọ mẹ́rin láti fi borí ogun Boko Haram ní Nàìjíríà- Olagunsoye Oyinlola

Oloye Olagunsoye Oyinlola ba BBC soro ni kikun lori ohu to ṣokunfa ogun Boko Haram ni ariwa Naijiria.

O sọ ohun ti oju rẹ ri ni Maiduguri lasiko to fi wa lẹnu iṣẹ ologun nibẹ.

Oyinlola

Oríṣun àwòrán, others