Eegunjobi Omotanbaje Ajobiewe- Èébú ní wọ́n kọ́kọ́ ń bù mí nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ ẹ̀ṣà pípé ní
Ìyàwó mẹ́tàlá ni bàbá mi fẹ́ ṣùgbọ́n èmí níkàn ní wọ́n bí- Ajobiewe Apẹ̀ṣà
Iṣẹ Oniburẹdi ni mo kọ ki ifẹ aṣa Yoruba to mu mi ya si idi iṣẹ ẹṣa pipe to sọ mi di eeyan loni- Ajobiewe
Gbajugba apẹṣa ni, Eegunjọbi Ajobiewe ni BBc ba lalejo lori aṣa Yoruba.
O sọ itan igbesi aye rẹ bi baba rẹ sẹ fẹ iyawo mẹtala to si jẹ pe oun nikan ni ọmọ lọwọ wọn.
O ni iṣoro ọmọ bibi yii lo bi orukọ pa ẹgan rẹ ti wọn sọ oun pe: Ọmọ tan ibajẹ - Omọtanbajẹ
- Ìdí márùn ún tí agbára Covid 19 ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ kò fi tó tí àwọn ilẹ̀ àgbáyé míràn
- A máa ná N10.2 bílíọnù fi tún wáyà iná àti inú ilé Aso Rock ṣe- Buhari
- Àṣìṣe ńlá ni Tinubu ṣe tó ti Buhari lẹ́yìn tó fi dé ipò- Oba Shomolu-Bariga
- Owó iṣẹ́ abẹ ìdí kìí ṣe ẹ̀rù ọmọdé- Dr Laser
- Wo ìdí tí Tẹni, ọ̀dọ́mọdé olórin obìnrin kìí fi ń ṣí ìhòhò rẹ silẹ̀
- Ẹfunsetan Aniwura, ọmọ Ẹ̀gbá tó di akíkanjú obìnrin nílẹ̀ Ibadan
Kini ẹṣa?
Kini Ijala?
Kini pataki oriki?
Idahun yii wa lara awọn ohun ti agba ọjẹ apẹṣa yii sọrọ nipa rẹ.
- Sunday Igboho ti ní kí Ìjà òmìnira Yorùbá Nation tẹ̀síwájú láìnáání ìdojúkọ àwọn ìjọba- Alhaji Ajikobi!
- Ìdí tí wọ́n fi ń pè mi ní Maradona rèé- Ibrahim Babangida
- Àwòrán ayẹyẹ ìwúyè Olu ti Warri
- Mo fẹ́ ìdájọ́ òdodo lórí ikú tó pa ọmọ mi- Baba ọmọ ti SARS pa
- Àlàyé tí Ooni Ile Ife ṣe nìyìí lórí ìpànìyàn tó dá ìkáyàsókè sílẹ̀ láàrín Ife ati Modakeke lọ́jọ́ Ẹ́tì
Ajobiewe Eegunjọbi gba awọn ọdọ ni imọran pe aforiti lẹnu iṣẹ ti eeyan ba yan laayo lo ṣe pataki.
O mẹnuba bi oun ṣe jogunba iṣẹ ẹṣa pipe lati ọdọ baba oun.
O tun sọrọ pataki ati ipa ti aṣa n ko lawujo Yoruba.
