BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Corronation: Àwòrán ayẹyẹ ìwúyè Olu ti Warri
21 Ògún 2021
Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn 22 Ògún 2021
Gbogbo ètò lo ti to fún ayẹyẹ ìwúyè Olu ti Warri Omooba Tsola Emiko
Àkọlé àwòrán,
Gbogbo ètò lo ti to fún ayẹyẹ ìwúyè Olu ti Warri Omooba Tsola Emiko
Àkọlé àwòrán,
Awon alejo nibi ayẹyẹ iwúye Olu Warri
Àkọlé àwòrán,
Ẹni ọdun mẹtalelọgbọn ni Olu Warri tuntun naa Utieyinoritsetsola Emiko oun si ni Olu ẹlẹkọkanlelogun
Àkọlé àwòrán,
Ọba onipo kini ni Olu warri, oun si ni ọba lori gbogbo ọmọ Itsekiri nile ati lẹyin odi
Àkọlé àwòrán,
Ni Ọjọ Eti gbogb àwọn ọdọ ilu lo n wọde pẹlu ọba tuntun naa ki gbogbo eniyan le ri
Àkọlé àwòrán,
Awon ọmọ oye ile Ginuwa ni awọn ọdọ tro wọ tẹle lẹyin, awọn si ni wọn fi idi rẹ mulẹ pe oun ni awọn fi jẹ Ọba
Àkọlé àwòrán,
Gbogob awọn eniyan jankanjankan lo peju sibi ayẹyẹ Iwuye naa
Àkọlé àwòrán,
Ọba onipo kini ni Olu warri, oun si ni ọba lori gbogbo ọmọ Itsekiri nile ati lẹyin odi, gbogbo agbaagba ilu naa peju sibi ayẹyẹ naa
Àkọlé àwòrán,
Gbogbo awọn alejo lo joko gẹgẹ saaju asiko ti ayẹyẹ iwuye naa bẹrẹ
You might also like:
news
|
sport
|
weather
|
worklife
|
travel
|
future
|
culture
|
world
|
business
|
technology