Rape survivor: Ìyá mi ni ń kò gbọdọ̀ sọ̀rọ̀ kí ilé má bà á dàrú- Oluwatobi Raji
Ariwo 'Idi mi gba ina jẹ' ni Woli ni ki n maa pa ko to kọlu mi- Tobi Raji
Oluwatobi Raji ni BBC wa kan ti o sọrọ nipa iriri rẹ gẹ gẹ bi ẹni to ti la ifipabanilopọ kọja.
O ni ọkunrin mẹwaa lo ti fipa ba oun lo pọ ri ṣugbọn oun n sọ nipa rẹ ki ọpọ ọdọ ma ba a ko si iru gbaga bẹẹ ni.
- Ìjà ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ni o, àwọn dókítà NARD tó ń yanṣẹ́lódì fárígá pẹ̀lú ìjọba
- Tètè wá gbé òkú eèyàn rẹ bí bẹ́ẹ̀ kọ́ a ó sìn wọ́n papọ̀ mọ́ tí 200 lópin ọ̀sẹ̀- Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá
- Kò sí ọmọ Zambia kan tó má sùn pẹ̀lú ebi mọ́ lásìkò tèmi gẹ́gẹ́ bíi Aàrẹ- Hichilema ṣèlérí
- Ojú wa rí tó gẹ́gẹ́ bíi akẹ́kọ̀ọ́ UNIJOS kí Makinde tó wá fi mọ́tò kó wa padà sí ìpínlẹ̀ Oyo- Akẹ́ọ̀ọ́ UNIJOS
- Mẹ́fà nínú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ẹ̀kọ́ Islamiyya Tegina ti kú, àwọn ajínigbé ṣì ń bèèrè N200m
Tobi sọ bi ọrọ yi ṣe bẹrẹ pẹlu aburo iya rẹ lọmọ ọdun mẹjọ.
O sọ bi iya oun ṣe ni ki oun dakẹ ki ile ma baa daru.
O ni ni iya oun ba ni ki oun pa a móra.
Tobi gba Obi ati alagbatọ se gbọdọ tọju awọn ọmọ wọn.
- Mẹ́fà nínú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ẹ̀kọ́ Islamiyya Tegina ti kú, àwọn ajínigbé ṣì ń bèèrè N200m
- Ìyànjẹ ni ìyà tó jẹ́ wa nígbà tí a lọ ṣàdúrà ní Plateau láti Ondo- Usman Mohammed
- Ọkùnrin mẹ́wàá ló ti fipá bá mi lòpọ̀ rí, àbúrò ìyá mi lálákọ́kọ́- Oluwatobi Raji
- Ǹkan mọ́kànlá tí o ni láti mọ̀ nípa Sẹnatọ Biyi Durojaiye tó d'Ólògbé
- Wo ìgbésẹ̀ tí ìjọba ìpínlẹ̀ Plateau gbé lẹ́yìn ìkọlù tó wáyé lónìí
Tobi Raji sọ awọn nkan mii to ṣẹlẹ si ati idi ti oun ṣe n fọnrere lodi si ifipabanilopọ ati ipa to yẹ ki Ijoba ko lori iṣẹlẹ bẹẹ.