Ondo Jos clash: Èmi nìkan ló padà dé nínú àwa márùn ún tí a jọ lọ ìpàdé àdúrà ní Jos- Bell
Awọn ti ori ko yọ ninu ikọlu to waye si awọn Fulani ipinlẹ Ondo ti wọn lọ si Plateau ba BBC Yoruba sọrọ ilẹ kun.
Usman Ahmad ti isẹlẹ naa kọkọ ba a lojiji bi o ṣe ṣoju rẹ ni aya oun ṣi n ja ninu paya di isinyi.
- Orí ayélujára ni mo ti gbọ́ pé ìgbéyàwó mi àkọ́kọ́ ti foríṣọ́npọ́n - Funke Akindele Bello
- Wo ìgbà mẹ́ta tí Olusegun Obasanjo ti fi ìdọ̀bálẹ̀ nàá fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ níwájú àwọn oríadé
- Ìyànjẹ ni ìyà tó jẹ́ wa nígbà tí a lọ ṣàdúrà ní Plateau láti Ondo- Usman Mohammed
- Ìdí rèé ti mo fi ní kí aráàlú máa di ìhámọ́ra ogun nítorí àwọn janduku- Gómìnà Katsina
- Ìyànjẹ ni ìyà tó jẹ́ wa nígbà tí a lọ ṣàdúrà ní Plateau láti Ondo- Usman Mohammed
Lana Abdullahi to farapa pupọ naa sọ idaamu ti wón koju nigba ti wọn n sa asala fun ẹmi ara wọn.
Abubakar Bello mẹnuba ipa ti awọn soja ko funara ilu lati doola ẹmi iye awọn to ṣeku.

Harunna Mohammed atawọn to ku naa ni iru eyi ko dara nilu to lolori.
Alaga ẹgbẹ Fulani Miyetti Allah, Muhammad Kabir gba wọn nimọran lati maa beere fun eto aabo ki wọn to lọ sibi eto adura kankan léyin iṣẹlẹ yii.
