Coronavirus in Nigeria: Ènìyàn 653 ló tún ṣẹ̀ṣẹ̀ lùgbàdì ààrùn Coronavirus ní Nàìjíríà, 129 láti Eko nìkan

Ayẹwo tun fihan pe eeyan ọtalelẹgbẹta o din meje lo ti kun iye awọn to ni arun coronavirus lorilẹede Naijiria lọjọ Abamẹta.
Iye awọn eeyan wọnyi ni ajọ to n gbogun ti ajakalẹ arun lorilẹede Naijiria, NCDC ni awọn ṣawari nipa ayẹwo lati awọn ipinlẹ mejidinlọgbọn kun ẹgbẹrun marundinlogoji o le diẹ to wa nilẹ tẹlẹ.
- Gbọ́ ọ̀rọ̀ lẹ́nu afurasí tí Ọlọ́pàá ní ó pa Barakat Bello, Grace Oshiagwu àtàwọn míì l'Akinyele Ibadan
- Èèmọ̀! Eyín oníròyìn fò yọ lásìkò tó n ka ìròyìn lọ́wọ́ lórí tẹlifísàn
- Ààrẹ Buhari fi ọ́fíìsì reluwé tó wà ní ìlú Agbor sọríi ààrẹ àná, Goodluck Jonathan
- Àwọn ọ̀dọ́ ilẹ̀ Yoruba kò gbọdọ̀ gbàgbé àṣà ati ohun àdàyébá wọn - Ooni Ile Ife
Ipinlẹ Eko lo moke julọ pẹlu eeyan marundinlọgọfa ti Kwara si tẹle e pẹlu eeyan marundinlaadọrun ti Enugu ati olu ilu ilẹẹwa Abuja si tẹlee pẹlu ọgọrin ati mejidinlọgọrin ni ṣiṣẹ n tẹle.
Bayii ni awọn ipinlẹ yooku ṣe to tẹle ara wọn lori atẹ awọn ayẹwo gbe sita lọjọ Abamẹta:

Nínú èèyàn 600 tó ní coronavirus lọ́jọ́ Ẹtì, 275 ló wá láti agbègbè ilẹ̀ Yorùbá

Ẹgbẹta eeyan ni ayẹwo tun ti fihan pe o tun ti kun iye awọn eeyan to ni arun COVID-19 lorilẹ-ede Naijiria lọjọ kẹtadinlogun, oṣu keje, ọdun 2020.
Ninu ikede olojoojumọ to maa n gbe sita lori bi nnkan ṣe n lọ si pẹlu ajakalẹ arun COVID-19 lorilẹ-ede Naijiria, ajọ to n gbogunti ajakalẹ aarun lorilẹ-ede Naijiria, NCDC ṣalaye pe gẹgẹ bi iṣe rẹ, ipinlẹ Eko lo moke ninu ipinlẹ ogun ti arun naa tun ti ko awọn eeyan mọra ni Naijiria.
NCDC ni eeyan ẹgbẹrun marundinlogoji ati ọtalenirinwo o din mẹfa, (35, 464) ni ayẹwo ti fihan pe o larun naa ni Naijiria.
Ninu eyi ti ẹgbẹrun mẹrinla ati ojilelẹbẹta o din meje eeyan ti ri iwosan, ọrinlelẹẹdẹgbẹrin o din mẹjọ lo ti gba ekuru jẹ lọwọ ẹbọra nipasẹ arun naa.
Eyi ni agbekalẹ awọn ipinlẹ ti ayẹwo fihan lọjọ Ẹti ọjọ kẹtadinlogun, oṣu keje pe o laarun naa:

Ènìyàn 156 ló tún ṣẹ̀ṣẹ̀ lùgbàdì ààrùn Coronavirus ní ìpínlẹ̀ Eko

Oríṣun àwòrán, Others
Àpapọ̀ àwọn tuntun to ṣẹṣẹ lugbadi ààrùn Coronavirus ní Nàìjíríà jẹ 595 ní 1/07/2020
Ninu ikede ti Ajọ NCDC fi sita fihan pe , awọn to ti ni aarun naa ti pe 34,854 bayii.
Ṣugbọn ṣa, eniyan 14292 ti ri iwosan, awọn 769 si ti ku.
- Mo ti pinnu láti túṣu dé ìsàlẹ̀ ìkòkò lóríì ìdí tí kò sí ìdàgbàsókè ní Niger Delta - Buhari
- Ènìyàn 156 ló tún ṣẹ̀ṣẹ̀ lùgbàdì ààrùn Coronavirus ní ìpínlẹ̀ Eko
- A fura pé ejò lọ́wọ́ nínú ikú Tolu Arotile, ẹ ṣe ìwádìí ikú rẹ̀ - Afenifere, Gani Adams, Huriwa
- Ohun tí o kò mọ̀ nípa Ebila "One Million Boys" àti Ekugbemi, olórí ẹgbẹ́ òkùnkùn méjì tó da ìlú Ibadan rú
Abajade ipinlẹ kọọkan ninu esi tuntun naa re e:
- Eko-156
- Ondo-95
- Rivers-53
- Abia-43
- Oyo-38
- Enugu-29
- Edo-24
- FCT-23
- Kaduna-20
- Akwa Ibom-17
- Anambra-17
- Osun-17
- Ogun-14
- Kano-13
- Imo-11
- Delta-6
- Ekiti-5
- Gombe-4
- Plateau-4
- Cross River-2
- Adamawa-1
- Bauchi-1
- Jigawa-1
- Yobe-1
Àpapọ̀ àwọn tuntun to ṣẹṣẹ lugbadi ààrùn Coronavirus ní Nàìjíríà jẹ 643 ní 15/07/2020
Ninu ikede ti Ajọ NCDC fi sita ni Ọjọ Ìṣẹgun lo ti fojuhan pe , awọn to ti ni aarun naa ti pe 34,259 bayii.

Oríṣun àwòrán, Others
Ṣugbọn ṣa, eniyan 13,999 ti ri iwosan, awọn 760 si ti ku.
Abajade ipinlẹ kọọkan ninu esi tuntun naa re e:
- Eko-230
- Oyo-69
- FCT-51
- Edo-43
- Osun-35
- Rivers-30
- Ebonyi-30
- Kaduna-28
- Ogun-27
- Ondo-23
- Plateau-20
- Benue-17
- Enugu-16
- Imo-10
- Delta-6
- Kano-4
- Nasarawa-2
- Kebbi-1
- Ekiti-1
Àpapọ̀ àwọn tuntun to ṣẹṣẹ lugbadi ààrùn Coronavirus ní Nàìjíríà jẹ 463 ní 14/07/2020
Ninu ikede ti Ajọ NCDC fi sita ni Ọjọ Ìṣẹgun lo ti fojuhan pe , awọn to ti ni aarun naa ti pe 33,616 bayii.
Ṣugbọn ṣa, eniyan 13,792 ti ri iwosan, awọn 754 si ti ku.
Abajade ipinlẹ kọọkan ninu esi tuntun naa re e:
- Eko -128
- Kwara-92
- Enugu-39
- Delta-33
- Edo-29
- Plateau-28
- Kaduna-23
- Oyo-15
- Ogun-14
- Osun-14
- FCT-12
- Ondo-9
- Rivers-9
- Abia-8
- Bayelsa-5
- Ekiti-3
- Borno-2
Ààrùn Coronavirus tún ti ran ènìyàn 595 l'órílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Àpapọ̀ àwọn tuntun to ṣẹṣẹ lugbadi ààrùn Coronavirus ní Nàìjíríà jẹ 595 ní 13/07/2020
Ninu ikede ti ajọ NCDC fi sita ni Ọjọ Aje lo ti fojuhan pe , awọn to ti ni aarun naa ti pe 33,152 bayii.
Ṣugbọn ṣa, eniyan 13,671 ti ri iwosan, awọn 744 si ti ku.
- Ìyàwó mi ló ṣì ń dáná, bu oúnjẹ mi, gé èékáná fún mi - Pásítọ̀ Adeboye
- Ọkùnrin kan fipá bámi lòpọ̀ lọ́mọ ọdún mọ́kàndínlógún- Funke Oshonaike
- Ọlọ́pàá kọ́ lo pa olórí àwọn ''One Million Boys'' Ebila n'Ibadan- Ọ̀gá ọlọ́pàá Oyo
- Kí ló fa ìjà láàrin Wunmi Toriola àti Seyi Edun?
- Bí òṣìṣẹ́ Amotekun bá fi orúkọ sílẹ̀ lórí ayélujára, àwọn ọ̀daràn yóò tètè fojú hàn - Oludari Amotekun l'Oyo
Abajade ipinlẹ kọọkan ninu esi tuntun naa re e:
- Eko-156
- Oyo-141
- FCT-99
- Edo-47
- Kaduna-27
- Ondo-22
- Rivers-20
- Osun-17
- Imo-13
- Plateau-10
- Nasarawa-8
- Anambra-8
- Kano-5
- Benue-5
- Borno-5
- Ogun-4
- Taraba-3
- Gombe-3
- Kebbi-1
- Cross Rivers-1
Àpapọ̀ àwọn tuntun to ṣẹṣẹ lugbadi ààrùn Coronavirus ní Nàìjíríà jẹ 571 ní 12/07/2020
Ninu ikede ti ajọ NCDC fi sita ni Ọjọ Aiku lo ti fojuhan pe , awọn to ti ni aarun naa ti pe 32,558 bayii.

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ṣugbọn ṣa, eniyan 13,447 ti ri iwosan, awọn 740 si ti ku.
Abajade ipinlẹ kọọkan ninu esi tuntun naa re e:
- Eko -152
- Ebonyi-108
- Edo-53
- Ondo-46
- FCT-38
- Oyo-20
- Kwara-19
- Plateau-17
- Osun-14
- Bayelsa-14
- Ekiti-14
- Katsina-14
- Akwa Ibom-11
- Kaduna-11
- Rivers-11
- Niger-10
- Ogun-7
- Kano-6
- Cross River-4
- Bauchi-2
Àpapọ̀ àwọn tuntun to ṣẹṣẹ lugbadi ààrùn Coronavirus ní Nàìjíríà jẹ 664 ní 11/07/2020
Ninu ikede ti ajọ NCDC fi sita ni Ọjọ Abameta lo ti fojuhan pe , awọn to ti ni aarun naa ti pe 31,987 bayii.
Ṣugbọn ṣa, eniyan 13, 103 ti ri iwosan, awọn 724 si ti ku.
Abajade ipinlẹ kọọkan ninu esi tuntun naa re e:
- Eko-224
- Abuja-105
- Edo-85
- Ondo-64
- Kaduna-32
- Imo-27
- Osun-19
- Plateau-17
- Oyo-17
- Ogun-17
- Rivers-14
- Delta-11
- Adamawa-10
- Enugu-7
- Nassarawa-6
- Gombe-3
- Abia-3
- Ekiti-3
Àpapọ̀ àwọn tuntun to ṣẹṣẹ lugbadi ààrùn Coronavirus ní Nàìjíríà jẹ 575 ní 11/07/2020
Ninu ikede ti ajọ NCDC fi sita ni Ọjọ Ẹti lo ti fojuhan pe , awọn to ti ni aarun naa ti pe 31,323 bayii.
Ṣugbọn ṣa, eniyan 12,795 ti ri iwosan, awọn 709 si ti ku.
Abajade ipinlẹ kọọkan ninu esi tuntun naa re e:
- Eko-224
- Oyo-85
- FCT-68
- Rivers-49
- Kaduna-39
- Edo-31
- Enugu-30
- Delta-11
- Niger-10
- Katsina-9
- Ebonyi-5
- Gombe-3
- Jigawa-3
- Plateau-2
- Nassarawa-2
- Borno-2
- Kano-1
- Abia-1
Ajọ to n ṣamojuto ajakalẹ aarun ni Naijiria, NCDC, kede pe 499 lo tun ṣẹṣẹ ni Covid-19 ni Naijiria.
Eyi jẹyọ ninu esi ayẹwo ti ajọ naa fi sita l'Ọjọbọ, fun ipinlẹ mẹtalelogun, ati ilu Abuja.

Oríṣun àwòrán, Getty Images
- Lagos-157
- Edo-59
- Ondo-56
- Oyo-31
- Akwa Ibom-22
- Borno-21
- Plateau-19
- Kaduna-18
- Katsina-18
- Bayelsa-17
- FCT-17
- Delta-14
- Kano-11
- Rivers-10
- Enugu-8
- Ogun-6
- Kwara-4
- Imo-3
- Nasarawa-2
- Osun-2
- Abia-1
- Ekiti-1
- Niger-1
- Yobe-1
Apapọ iye eniyan to ti ni aarun naa ni ipinlẹ kọọkan l'orilẹ-ede Naijiria niyii:

Oríṣun àwòrán, Ncdc
Àpapọ̀ àwọn tó ní ààrùn Coronavirus ní Nàìjíríà tayọ 30,000 ní 08/07/2020
Ọtalenirinwo eeyan ni aarun coronavirus tun ṣẹṣẹ ran mọ l'orilẹ-ede Naijiria.
Ninu ikede ti ajọ NCDC fi sita l'Ọjọbọ lo ti fojuhan pe , awọn to ti ni aarun naa ti pe 30,249 bayii.
Ṣugbọn ṣa, eniyan 12,373 ti ri iwosan, awọn 684 si ti ku.
Abajade ipinlẹ kọọkan ninu esi tuntun naa re e:
- Lagos-150
- Rivers-49
- Oyo-43
- Delta-38
- FCT-26
- Anambra-20
- Kano-20
- Plateau-18
- Edo-14
- Ó ṣeéṣe kí àrùn Coronavirus tànkálẹ̀ gba inú afẹ́fẹ́- WHO
- 'Rọ́bọ́ọ̀tì ni yóò máa yẹ̀ yìn wò kẹ́ẹ tó rìnrìnàjò òfurufú ní Nàìjíríà'
- Hushpuppi di gbajúmọ̀ ẹlẹ́wọ̀n tó ní nọ́ńbà l‘Amẹrika, orúkọ̀ rẹ̀ wà lórí ayélujára
- Olórí òṣìṣẹ́ ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara, Adisa Logun ti dágbére fáyé lẹ́yìn tó lùgbàdì àrùn Covid-19
Awọn ipinlẹ to ku ni:
- Bayelsa-13
- Enugu-13
- Osun-12
- Kwara-10
- Borno-8
- Ogun-7
- Kaduna-6
- Imo-4
- Bauchi-3
- Gombe-3
- Niger-2
- Adamawa-1
Ènìyàn 575 ló tún ní ààrùn Covid-19 ní Nàìjíríà ní 05/07/2020
Awọn to ni aarun Covid-19 ni Naijiria ti pe 29,789, lẹyin ti ajọ NCDC tun kede eeyan 503 to tun ṣẹṣẹ ni i.
Apapọ awọn to ti ri iwosan nipinlẹ kọọkan si ti pe 12,108. Sugbọn eniyan 669 ti ku.
- Lagos-153
- Ondo-76
- Edo-54
- FCT-41
- Enugu-37
- Rivers-30
- Benue-24
- Osun-20
- Kaduna-15
- Kwara-13
- Abia-9
- Borno-8
- Plateau-6
- Taraba-5
- Ogun-3
- Kano-3
- Kebbi-2
- Nasarawa-2
- Bayelsa-1
- Gombe-1
Ènìyàn 575 ló tún ti ní ààrùn Covid-19 ní Nàìjíríà 06/07/2020
Esi ayẹwo ajakalẹ aarun Coronavirus ti ajọ NCDC fi sita lọ̀jọ̀ Aje fihan pe, ọrinlelẹẹdẹgbta ati maarun (575) eeyan lo tun ti ni aarun naa ni Naijiria.
Awọn ẹni tuntun naa wá lati ìpínlẹ̀ mọkandinlogun, ati olu ilu Naijiria, Abuja.
- Lagos-123
- FCT-100
- Delta-58
- Edo-52
- Ogun-42
- Katsina-24
- Bayelsa-23
- Rivers-22
- Borno-19
- Plateau-18
- Ondo-18
- Oyo-17
- Kwara-15
- Osun-13
- Enugu-9
- Nasarawa-7
- Abia-6
- Cross River-5
- Kaduna-3
- Ekiti-1
Lọwọlọwọ, eniyan 29,286 lo ti ni aarun naa, 11828 ti ri iwosan, 654 si ti ku.
Ènìyàn 575 ló tún ní ààrùn Covid-19 ní Nàìjíríà ní 05/07/2020
Orilẹ-ede Naijiria tun ti ni akọsilẹ ojilelẹẹdẹgbẹta ati mẹrin eeyan to tun ti ni Covid-19.
Ajọ to n mojuto ajakalẹ aarun, NCDC, kede pe ipinlẹ mejidinlogun, ati ilu Abuja ni awọn esi ayẹwo naa ti jade.
Akojọpọ esi naa re e fun ipinlẹ kọọkan.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post
Ènìyàn 603 ló ní Covid-19 ní Nàìjíríà ní 04/07/2020
Ajọ to n mojuto ajakalẹ aarun ni Naijiria, NCDC, sọ pe esi ayẹwo aarun coronavirus t'oun kede lọjọ Abamẹta fihan pe, eniyan mẹtalelẹgbẹta lo tun ti ni aarun naa.
Esi ayẹwo lati ipinlẹ mọkandinlogun ni wọn gbe jade lọjọ Abamẹta.
Awọn ipinlẹ naa niyii:
- Lagos-135
- Edo-87
- FCT-73
- Rivers-67
- Delta-62
- Ogun-47
- Kaduna-20
- Plateau-19
- Osun-17
- Ondo-16
- Enugu-15
- Oyo-15
- Borno-13
- Niger-6
- Nasarawa-4
- Kebbi-3
- Kano-2
- Sokoto-1
- Abia-1
Akojọpọ awọn to ti ni ti pe 28,167. Eniyan 11,462 ti ri iwosan, 634 si ti kú.













