Pastor Adeboye: Ariwo lórí ayélujára nítorí ọ̀rọ̀ ìkíni kú ọjọ́ọ́bí tí Pásítọ̀ Adeboye kọ sí ìyàwó rẹ̀, Folu

Pasitọ Adeboye ati iyawo rẹ

Oríṣun àwòrán, Pastor Adeboye

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 6

Pasitọ ijọ Redeem tun ti m'oke patapata lara awọn ti wọn n ka atẹjade wọn ju lori ayelujara.

Ọpọlọpọ igba ni orukọ alufa yii ti sun soke lori ayelujara to si tun jẹ ọkan lara awọn gbajugbaja ojiṣẹ Ọlọrun lagbaye amọ ọrọ tirẹ a maa fa ọpọlọpọ ọrọ jade lori ayelujara paapaa lẹnu awọn ọmọ Naijiria.

Ki la tun wa ri gbọ bayii?

Pasitọ Folu Adeboye

Oríṣun àwòrán, Pastorfoluadeboye

Ọna ti Baba Adeboye gba ṣe ayẹsi ọjọ ibi iyawo rẹ, Folu Adeboye lọtẹ yii to pe ọdun mejilelaadọrin ma nii- ni awọn ọdọ Naijiria ba tu sita loju opo Twitter Adeboye lati da si ọrọ naa yala ni ti ṣiṣi fila fun ohun ti Pasitọ yii ẹni ọdun mẹtalelọgọrin funrararẹ sọ nipa iyawo rẹ, Folu Adeboye tabi tita ko o.

Ninu aduru ọrọ to fi sita, eyi ti awọn eniyan han ni bi o ti ni " Oni lọjọ ibi iyawo mi mo si fẹ́ ki awọn obinrin kọ awọn ẹkọ kan latara rẹ paapaa ọpọlọpọ awọn ọdọ.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

"Bi iṣẹ ṣe pọ fun un to, iyawo mi lo ṣi n da ina ounjẹ to si n bu ounjẹ ti mo n jẹ, koda o ṣi maa n ge eekana fun mi. Ọpọlọpọ obinrin ode oni lo n fi gbogbo iṣẹ lẹ fun ọmọ ọdọ..."

Baba Adeboye ni koda lasiko kan, iyawo oun ti gẹ irun fun oun nitori ilu ti iṣẹ iranṣẹ gbe wọn lọ lasiko naa.

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

Skip X post, 3

End of X post, 3

Pasitọ Adeboye ati iyawo rẹ

Oríṣun àwòrán, PAstor Adeboye

Fun ọpọlọpọ, ṣe ni awọn ọrọ naa wu awọn eeyan lori bi ifẹ to jinlẹ to eyi ṣi ṣe wa laarin awọn lọkọ laya iranṣẹ Ọlọrun yii pẹlu bi wọn ṣe dagba to - afi bii ifẹ ti kii ti tabi d'ogbo.

@benmichael4ever fi fidi sita ninu eyi to ti gboriyin fun Pasitọ Adeboye to si wọ eebu le awọn obinrin to n bu u lori pe wọn ko lọpọlọ. Wọn ni ọpọlọpọ awọn to n tẹle wọn lori Facebook ati Twitter ṣugbọn wọn ko reeyan kankan tẹle wọn lọ sile baba wọn pe o fẹ fẹ wọn gẹgẹ bi ọkọ tabi aya.

Skip X post, 4
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 4

Ni ti awọn ti ko gba ti ọ̀rọ̀ ti Pasitọ Adeboye fi sita yii, ṣe ni wọn n bu ẹnu atẹ lu u. Ṣe ko si b'ọmọ ṣe dara to ti ko ni ni ọta.

@solomon__c bu ẹnu atẹ lu u pe gbogbo ọrọ naa loju toun da bi ẹni to n keree gbogbo ipo ati iyi nla ti wọn ti gba ni.

Skip X post, 5

End of X post, 5

Koda ọpọlọpọ fidio lawọn ọmọ Naijiria fi ranṣẹ si Mama Adeboye gẹgẹ bi ikini ku ọjọ ibi to fi mọ awọn oṣere adẹrinpoṣonu gan atawọn ọmọ ijọ irapada naa.

Skip Instagram post, 1
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 1

Skip X post, 6
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 6

Pasitọ Adeboye ati iyawo rẹ

Oríṣun àwòrán, Pastor Adeboye

Haa, aṣe Baba Adeboye ko lee da ounjẹ jẹ, ko si lee da eekanna ara rẹ ge laisi iyawo rẹ lariwo ti awọn eeyan kan n pa bayii lori ayelujara ni kete ti iranṣẹ Ọlọrun Adejare Enoch Adeboye ki aya rẹ ku ọjọ ibi rẹ to waye ni ọjọ kẹtala oṣu keje.

Ẹni ọdun mejilelaadọrin ni iyaafin pasitọ Folu Adeboye da lọdun yii ọrọ ikini ti baba Adeboye si fi ranṣẹ sii lori ayelujara ti n fa wahala.

Ni kete to gbe ọrọ rẹ yii jade ni awsn ọmọ Naijiria kan ti fọn sori ayelujara lati fi ero wọn han lori ọrọ naa.

Ọkan lara awọn ọmọ orilẹede Naijiria kan loju opo Twitter @Mochevious kọọ soju opo naa pe, baba Adeboye i ba ti sọ pe " Ku ọjọ ibi ẹran ninu ẹran ara mi" ko si fi mọọ bẹẹ. Ni bayii a ti mọ pe ko lee ṣe awọn nnkan pẹ-pẹ-pẹ bii ko dana fun ara rẹ ati ko ge eekanna rẹ.TMI."

Bakan naa, @Benxta_ naa sọ pe "Mi o lee gbagbọ pe Adeboye yoo joko o si wa ọna lati lo anfani ọjọ ibi iyawo rẹ fi sọrọ lori ara rẹ ati agbara to ni lori rẹ. Dipo ko kuku ti laa mọlẹ pe 'ku ọjọ ibi ifẹ mi'

Skip X post, 7
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 7

Amọṣa bi awọn wọnyii ṣe n sọ tiwọn lawọn kan naa n gbe sẹyin baba Adeboye pe otitọ ọrọ lo sọ.

@TifeOfficial nitirẹ kọọ pe "tẹlẹ, o yẹ kawọn obinrin maa tẹriba fun awọn ọkọ wọn. Pasitọ Adeboye kan n sọ ododo ọrọ ni lati fi imoore han fun iyawo rẹ fun itẹriba to ni, nitori naa iwa oponu patapata gbaa ni lati maa fi ẹnu tẹmbẹlu rẹ, nitoripe ootọ ọrọ lo sọ."

Skip X post, 8
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 8

Skip X post, 9

End of X post, 9

@OgbeniDipo kọọ soju opo tirẹ pe: "Njẹ o lee pe baba to bi ọ lọmọ ni oponu nitori pe o ko fara mọ ohun to sọ? Ki lo de ti ti Pasitọ Adeboye fi yatọ?"

Skip X post, 10
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 10

Ìyàwó mi ló ṣì ń dáná, bu oúnjẹ mi, gé èékáná fún mi - Pásítọ̀ Adeboye

Pasitọ ijọ Redeem tun ti m'oke patapata lara awọn ti wọn n ka atẹjade wọn ju lori ayelujara.

Ọpọlọpọ igba ni orukọ alufa yii ti sun soke lori ayelujara to si tun jẹ ọkan lara awọn gbajugba ojiṣẹ Ọlọrun lagbaye amọ ọrọ tirẹ a maa fa ọpọlọpọ ọrọ jade lori ayelujara paapaa lẹnu awọn ọmọ Naijiria.

Ki la tun wa ri gbọ bayii?

Pasitọ Folu Adeboye

Oríṣun àwòrán, Pastorfoluadeboye

Ọna ti Baba Adeboye gba ṣe ayẹsi ọjọ ibi iyawo rẹ, Folu Adeboye lọtẹ yii to pe ọdun mejilelaadọrin ma nii- ni awọn ọdọ Naijiria ba tu sita loju opo Twitter Adeboye lati da si ọrọ naa yala ni ti ṣiṣi fila fun ohun ti Pasitọ yii ẹni ọdun mẹtalelọgọrin funrararẹ sọ nipa iyawo rẹ, Folu Adeboye.

Ninu aduru ọrọ to fi sita, eyi ti awọn eniyan han ni bi o ti ni " Oni lọjọ ibi iyawo mi mo si fẹ́ ki awọn obinrin kọ awọn ẹkọ kan latara rẹ paapaa ọpọlọpọ awọn ọdọ.

Skip X post, 11
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 11

"Bi iṣẹ ṣe pọ fun un to, iyawo mi lo ṣi n da ina ounjẹ to si n bu ounjẹ ti mo n jẹ, koda o ṣi maa n ge eekana fun mi. Ọpọlọpọ obinrin ode oni lo n fi gbogbo iṣẹ lẹ fun mọ ọdọ..."

Baba Adeboye ni koda lasiko ohun, iyawo oun ti gẹ irun fun oun nitori ilu ti iṣẹ iranṣẹ gbe wọn lọ lasiko naa.

Skip X post, 12
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 12

Skip X post, 13

End of X post, 13

Pasitọ Adeboye ati iyawo rẹ

Oríṣun àwòrán, PAstor Adeboye

Fun ọpọlọpọ, ṣe ni awọn ọrọ naa wu awọn eeyan lori bi ifẹ to jinlẹ to eyi ṣi ṣe wa laarin awọn lọkọ laya iranṣẹ Ọlọrun yii pẹlu bi wọn ṣe dagba to - afi bii ifẹ ti kii ti tabi d'ogbo.

@benmichael4ever fi fidi sita ninu eyi to ti gboriyin fun Pasitọ Adeboye to si wọ eebu le awọn obinrin to n bu u lori pe wọn ko lọpọlọ. Wọn ni ọpọlọpọ awọn to n tẹle wọn lori Facebook ati Twitter ṣugbọn wn ko reeyan kankan tẹle wn lọ sile baba wọn.

Skip X post, 14
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 14

Ni ti awọn ti ko gba ti ọ̀rọ̀ ti Pasitọ Adeboye fi sita yii, ṣe ni wọn n bu ẹnu atẹ lu u. Ṣe ko si b'ọmọ ṣe dara to ti ko ni ni ọta.

@solomon__c bu ẹnu atẹ lu u pe gbogbo ọrọ naa loju toun da bi ẹni to n keree gbogbo ipo ati iyi nla ti wọn ti gba ni.

Skip X post, 15
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 15

Koda ọpọlọpọ fidio lawọn ọmọ Naijiria fi ranṣẹ si Mama Adeboye gẹgẹ bi ikini ku ọjọ ibi to fi mọ awọn oṣere adẹrinpoṣonu gan atawọn ọmọ ijọ irapada gan.

Skip Instagram post, 2
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 2

Skip X post, 16
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 16