Muhammadu Buhari: Ààrẹ Nàìjíríà balẹ̀ bàgẹ̀ s'Abuja lẹ́yìn ìpádé UNO nílùú New York

Muhammadu Buhari

Oríṣun àwòrán, Facebook/Femi Adesina

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Ba o lọ, a kii de, eyi lo difa fun Aarẹ orilẹede Naijiria, Muhammadu Buhari to pada silu Abuja lati orilẹede Amẹrika.

Aarẹ Buhari kopa ninu ipade apero ajọ iṣọkan agbaye eleyi to waye niluu New York.

Ipade ọhun niiṣe ẹlẹẹkẹrinlelaadọrin iru'ẹ lati igba ti wọn ti da ajọ iṣọkan agbaye silẹ lọdun 1945.

Oludamọran fun aarẹ lori iroyin ori ayelujara, Bashir Ahmad lo kede loju opo Instagram ati Twitter rẹ Aarẹ ti pada silu Abuja.

Skip Instagram post
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post

Skip X post
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post

Aarẹ kopa ninu oniruuru eto nibi apero awọn olori orilẹde niluu New York.

Buhari sọrọ igbiyanju ijọba rẹ lati gbogun ti oṣi ati iṣẹ to n ba ọpọ finra ni Naijiria.

Buhari tun sọrọ nipa eto ẹkọ ati ayipada oju ọjọ lorilẹede Naijiria.