SERAP: Ìbọ̀wọ̀ fófin ni bí wọ́n se fi Sowore sílẹ̀

Serap

Oríṣun àwòrán, TWITTER

Àkọlé àwòrán, Awọn ololufẹ rẹ lori ero ayelujara ni igbẹkẹle mẹkunu ni ile-ẹjọ, eleyii to fihan wi pe otitọ a bori dandan.
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Idunnu subu layọ fun ọpọlọpọ awọn ololufẹ Ọmọyẹle Soworẹ, lẹyin ti ile ẹjọ paṣẹ fun Ajọ DSS lati fi i silẹ ni kiakia.

Awọn ololufẹ rẹ lori ero ayelujara ni igbẹkẹle mẹkunnu ni ile-ẹjọ, eleyii to fihan wi pe otitọ a bori dandan.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Ẹgbẹ ajafẹtọ ọmọniyan, SERAP ti gbori yin fun idajọ to ni ki ile-ẹjo fi Ọmọyele Sowore silẹ ni panpẹ ajọ DSS ni kiakia.

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

SERAP ni idunnu ati ayọ lo jẹ fun awọn bi Sowore to ti wa ni panpẹ Ajọ DSS fun ọjọ mejilelaadọta ṣe gba itusilẹ, ti yoo si pada si ọdọ ẹbi ati ara rẹ.

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Ninu atẹjade to fi lede, Akọwe Ajọ SERAP, Kolawole Oluwadare ni ko lẹtọ lakọkọ ki ijọba fi si atimọle.

Omoyele Sowore ń jẹ́jọ́ igbìmọ̀dìtẹ̀ láti gba ìjọba lọ́wọ́ Ààrẹ Buhari:

Omoyele Sowore yoo fojuba ile ẹjọ giga loni nilu Abuja.

Sowore

Oríṣun àwòrán, @Sowore

Àkọlé àwòrán, Oye ni eeyan n wo nigba mii

Sowore ti o ti wa ni ahamọ fun igba diẹ ni wọn fi ẹsun orisi meje kan to fi mọ pe o n gbimoditẹ lati gba ijọba, ṣiṣagbatẹru igbesunmọmi ati kiko owo ilu lọ si il okeere lọna aitọ.

Omoyele Sowore

Oríṣun àwòrán, @YeleSowore

Àkọlé àwòrán, Omoyele Sowore ń jẹ́jọ́ igbìmọ̀dìtẹ̀ láti gba ìjọba lọ́wọ́ Ààrẹ Buhari

Loṣu to kọja ni Sowore pe fun iwọde ati ifẹhonu han lati fi tako awọn ohun to pe ni aiṣedeede ijọba Naijiria.

Ile iṣẹ ọtẹlẹmuyẹ Naijiria to mu sọ pe o n dun ikoko mọ igbe aye alaafia ati ifọkanbalẹ awọn eeyan orile-ede Naijiria.

Àkọlé fídíò, Sport Betting: Idí rèé tí àwọn ọ̀dọ́ kan fi n ta tẹ́tẹ́...

Ọjọ kọkanlelogun, oṣu Kẹsan ni gbedeke aṣẹ itimọle ti ileeṣẹ ọtẹlẹmuyẹ gba nile ẹjọ ko ni eyi ti wọn fi sọ Sowore si ahamọ fọjọ marundinlaadọta.

Àkọlé fídíò, Yollywood: Kò sí ẹni ti òbí mi kò lè sọ̀rọ̀ sí -Sisi Quadri