BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Oniru: Fún ojú lóúnjẹ lórí ohun tó n ṣẹlẹ̀ nílé Oba Idowu Oniru tó wàjà
24 Owewe 2019
Erin Oba Idowu Abiodun Oniru ti Iru ni erekuṣu nipinlẹ Eko g[kè àlọ!
Àkọlé àwòrán,
Abawọle aafin ree loni lẹyin ti wọn tufọ Oba Oniru to waja
Àkọlé àwòrán,
Ọpọ ara, ọrẹ ati ojulumọ ni wọn n daro Oba Oniru nipinmlẹ Eko laarọ yii
Àkọlé àwòrán,
Awọn obinrin ile ni aafin Oniru n ṣe idaro Oba Idowu Abiodun to lọ ba awọn bab nla rẹ
Àkọlé àwòrán,
Ipinlẹ Eko n sọ awọn idagbasoke to ṣẹlẹ lasiko aye Oniru ti Iru
Àkọlé àwòrán,
Tilu tifọn ni wọn fi kede oku Oba Oniru to waja ni Eko, Iku Oba Alade nilẹ Oodua kii ṣe iku yẹpẹrẹ
Àkọlé àwòrán,
Erin wo! Ajanaku sun bi oke!.........Oniru lọ!
Àkọlé àwòrán,
Aafin Oba Oniru gan an ti n mọọ lara pe onile ti re ibi agba n re lọmọ ọdun mejilelọgọrin.
Àkọlé àwòrán,
Ojọ kan ni iṣu a dilẹ lẹyin gbogbo asunṣujẹ laye, ko ẹni ti ko ni re ibi agba n re lọjọ kan!
Àkọlé àwòrán,
Ko si ohun ti a mu wa sile aye ni ọrọ ri ni aafin Oniru laarọ yii.
Àkọlé àwòrán,
Wiwọ ni ero n wọ lọ ki awọn ẹbi Oba naa lataarọ ti wọn ti n gbọ
Àkọlé àwòrán,
Ko si ẹni ti oko baba rẹ ko ni di igboro lọjọ kan nile aye yii
Àkọlé àwòrán,
Oloola iju gan an a ku lọjọ kan bẹẹ naa ni eku ati aayan naa a ṣiwọ iṣẹ lọjọ kan.
Àkọlé àwòrán,
Adura onikaluku ni pe ki iku ka iṣẹ rere mọ koowa lọwọ lọjọ ti ọlọjọ ba de nitori pe gbese ni iku
You might also like:
news
|
sport
|
weather
|
worklife
|
travel
|
future
|
culture
|
world
|
business
|
technology