Nkechi Blesssing: Orí ayélujára n gbọ́ná jànjan láàrín gbájúgbajà méjì lójú òpó Instagram

O yá ẹ lọ wá nkan fìdílé kí ẹ wá gbọ́ làbárì ọ̀rọ̀ lórí bí gbọ́misi-omi ò ṣe bẹ́ sílẹ̀
Láìpẹ́ yìí ni oníruúru àwọn ènìyàn ń jáde pé àwọn ya ǹkan sí àra (Tatoo) láti fi ifẹ́ hàn sí gbájugbajà tí wọ́n bá mọ.
Ní ǹkan bi ọṣẹ mẹrin sẹyiní ọ̀pọ̀ ènìyàn tí ya àwòrán sí ara ni orúkọ Olarewaju Okuneye ti gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Bobrisky
- Yajoyajo: Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin tó lé ni 300 gbé ní ìlú Jangebe
- Kánífà Àdìrẹ gbé Odunlade re ìlú òyìnbó, Bobrisky rọ̀jò owó lé olólùfẹ́ lórí, Muka Ray pàdánù àbúrò
- Ariwo ẹkún sọ níbi ìsìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja
- Fayemi ló tó gbangba sùn lọ́yẹ́ láti jẹ ààrẹ Nàìjíríà lọdún 2023- Àwọn lọ́balọ́ba Ekiti
- Mo ń ṣe ẹ̀tọ́ mi fún Damilare lọ́dọ̀ màmá àgbà, àmọ́ ǹkan tí ẹ kò mọ̀ nípa ọ̀rọ̀ yìí ló pọ̀ - Mide-Funmi Martins
Sáájú ọmọbinrin kan ni ó kọọ́kọ́ ya Bobrisky tí Bobrisky tikara rẹ si gbe wa sori ayélujára lat sọ bi inú òun ṣe dun tó

Oríṣun àwòrán, Bobrisky222?instagram
Bí ó ṣe tún bùṣe gàdà ni ọmọbìnrin mi @officikal_ewatomigold1 náà tún ya àwòràn Bobrisky miran si ara
Sùgbọ́n lẹ́yìn èyí ni ẹnikan pé Bobriksky sita lori ayálujara pé ko ka òun sí lẹ́yìn tí òun náà ya àwòràn Boborisky si ara.
Bobrisky pẹ́lú rawọ ẹ̀bẹ̀ si ẹni náà pé ti àìkani kún kọ́ bíkò ṣe pé òun kò mọ̀. Ìròyìn fi yéni pé, gbogbo àwọn tó bá ya tatto sára ni oun fun lówó.

Oríṣun àwòrán, Bobrisky222

Oríṣun àwòrán, @koroma_judith
Báwo ni ìjà ṣe bẹ́ sílẹ̀ láàrin Bobriksky àti Nkechi Blessing
Bí ọ̀pọ̀ àwọn olólùfẹ́ Bobrisky ṣe n se èyí, ni àwọn olólufẹ́ àwọn gbájúgbàja míràn tó fi mọ́ Nkechi Blessing àti ọ̀kan ninu àwọn ọmọ ilé ẹlẹgbọ́n àgbà ọdún tó kọja Ka3na Jones.
Sùgbọ́n fún ti àwọn méjì òkè yìí ọ̀rọ̀ bẹ́yìn yọ ni, nítorí ọwọ́ ti Bobrisky fi mú àwọn olólúfẹ́ tírẹ kòọ́ ni àwọn méjì yìí fí mú olólùfẹ́ tiwọn.
Ní ti Ka3na, o bu ẹnu àtẹ lu irú ìwà ti ẹni to pe ara rẹ̀ ni olólkùfẹ́ òun hùn nítori òun kò faramọ́ ǹkan tó ṣe nípa yíya orúkọ òun si itan rẹ̀
Ó ni ọ̀pọ̀ ọ̀nà ni ènìyàn le gba fi ìfẹ́ hàn sùgbọ́n kìí ṣe nípa yíya àwòràn sí ara.
Lai pẹ́ sí àsìkò naáà ni ẹlòmíràn tún yá orúkọ gbájúgbàjà òṣèré Nkechi Blessing si ara rẹ̀, tí Nkechi Blessing pẹ̀lú sí ni oùn kò ni owóláti fún ẹnikẹ́ni o, lẹ́yìn ki òun dúpk lọ́wọ́ ẹni bẹ́ẹ̀ lójú òpó Instagram kò si ǹkan ti yó[[o ti ẹ̀yìn rẹ̀ jáde.
Kíni Bobrisky sọ?
Ní kété ti Bobrisky gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí lo kọ èrò tirẹ̀ jáde pé, gbogbo àwọn to ń kọ orúkọ tpàbi ya àwòràn sí ara, òun kò ni ṣe ǹkan kan ju pé kí òun gbé si ojú òpò Instagram lọ.
Bí o til jẹ́ pé, Nkechi Blessing padà bẹ ọmọbinrin tó ya tàtóò náà síbẹ̀ ìjà kò tá láàrín Bobrisky àti Nkechi Blessing

Oríṣun àwòrán, NAIJA

Oríṣun àwòrán, Bobrisky222
Lẹ́yìn èyí ni ọ̀rọ̀ náà bá di ìà gboro láárìn Bobriksky, Nkechi Blessing àti àwọn olólùfẹ́ wọn.
Àwọn ìtakurọ sọ tó n lọ láàrin àwọn gbájúgbajà méjèèjì rèé.

Oríṣun àwòrán, Bobrisky222

Oríṣun àwòrán, Nkechi blessing

Oríṣun àwòrán, Bobrisky222

Oríṣun àwòrán, AFP

Oríṣun àwòrán, Nkechi Blessing














