Sowore: Àjọ DSS kò nílò àṣẹ ààrẹ Buhari kí wọ́n tó ṣe ojúṣe wọ́n- Garba Sheu

Sowore
Àkọlé àwòrán, Àjọ ọtẹlẹ̀múyẹ ń se ojúṣe wọn lórí ọ̀rọ̀ Soworẹ ní-Ilé iṣẹ́ ààrẹ
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ilé iṣẹ́ ààrẹ Naijiríà ti sọ̀rọ̀ lórí awuyewuye to jẹyọ lọ́jọ́ ẹti lórí ọ̀rọ̀ ajìjàngbara Omoyele Sowore àti àjọ DSS, eyi to sì ti mú ọ̀pọ bẹ̀nu àtẹ lu ìjọba Muhammadu Buhari àti àjọ DSS.

Lọ́sàn òní ni ilé iṣẹ́ ààrẹ fẹ̀si sí ìdáhun àwọn ara ilú, nígbà ti olùbádàmọràn pàtàkì sí ààrẹ Buhari lọ́ra ìròyìn Garuba Sheu fẹ̀si lóri àtẹjiṣẹ́ Twitter rẹ̀ pé, ko sí ǹkan to buru nínú ǹkan ti ilé iṣẹ́ ọ̀tẹ̀lẹ̀múyẹ ṣe.

O ni nítorí kò sí ìjọba ti orí rẹ̀ pé ti yoòó maa wo Sowore niran láti bẹ̀rẹ ǹkan to fẹ́ rawọle láti dá wàhálà míràn silẹ̀ lórilẹ̀-èdè Naijiria.

O ní àjọ DSS ń ṣe ǹkan ti ofin fún wọ́n lágbára láti ṣe ni wọ̀n kò si nílò lati kọ́kọ́ gba àṣẹ lọ́wọ́ ilé iṣẹ ààrẹ ki wọ́n to ṣe ojúṣe wọ́n.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Garba Sheu fi kun un pé "kò yẹ ko ya ẹnikẹni lẹ́nu to ba ti n wo ìṣesi àti ihuwàsí to fi mọ ọ̀rọ̀ ẹnu Sowore pé oun gàn an ló n fa ojú ajọ DSS mọra."

"Sowore pè fún ìjìjàngbara láti lé ààrẹ ti orilẹ̀-èdè Naijiria dibò yàn kuro lórí oye"

Sowore Nile Ejo
Àkọlé àwòrán, Sowore: Àjọ DSS kò nílo àṣẹ ààrẹ kí wan to ṣe ojúṣe wọ́n- Garba Sheu

"Orílẹ̀-èdè naijiria ti n ba wàhálà ìgbésùnmọmi finra ti ogunlọgọ ènìyàn sì ti kú nígbà ti mílíọnu ènìyàn ti dí alárinkiri nitori aìrilegbé ní ìhà àrewa orilẹ̀-èdè Naijiria."

Awọn Boko Haram ti wọ́n n fa wàhála náà ni lọkan pé àwọn ń jà fún ìdí kan ni.

Àkọlé fídíò, Èyí ni ìtàn bí ẹni tí mó gbọ́njú mọ̀ bíi bàbà ṣe fipá bá mi lájọṣepọ̀

Kíní àwọn ọmọ Naijiria ń sọ

Bí àwọn kan ṣe ni bẹ́ẹ̀ ni òòtọ́ ọ̀rọ̀ ni Garba Sheu ń sọ ni àwọnnmíràn ti n tutọ soke foju gbàá.

Díẹ̀ lára èsì ti àwọn ọmọ Naijiria fún Garba Sheu.

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

Skip X post, 3

End of X post, 3

Skip X post, 4

End of X post, 4

Skip X post, 5

End of X post, 5

Àkọlé fídíò, Yoruba language: Àmì ohùn ṣe pàtàkì nínú èdè Yorùbá