Minimum wage: NLC ló ń fa ọwọ àfikún owó òṣìṣẹ́ sẹ́yìn!

Oríṣun àwòrán, Others
ìjọba àpapò tí fẹ̀sùn kán àjọ àwọn òṣìṣẹ́ pé, àwọn ni wón ń fà ifaseyin bá ṣíṣe àfikún sí owó àwọn osise lórílẹ̀ èdè Naijiria.
Alága àjọ tí ń rí sí owó oṣù, àti ipòwòwọlé, Olóyè Richard Egbule, lo sọ ọrọ yìí ni Abuja nígbà tí ó ń fi ọ̀rọ̀ j'omi toro oro pelu àwọn akọ ròyìn lọ́jọ́ ajé.
Egbule ni Ìjọba àpapọ́ ní ẹgbẹ́ òsìsẹ́ tún bèrè fún àfikún owó osù fún àwọn tó ń gba owó osù tó ju 30,000 Naira tí wọn béré fún lọ.
ìjọba àpapò wa fikun wi pe ti awọn ba fikun owo bi ẹgbẹ osisẹ se beere rẹ, iye owo ti ijọba a ma a san fun owo osu.









