El-Zakzaky: Arúfin ni ijọba Muhammadu Buhari gan-an - Ladoja

Gomina tẹlẹri nipinlẹ Ọyọ, ti o tun jẹ Osi Olubadan ti ilẹ Ibadan, Oloye Rashidi Ladọja ti bẹnu atẹ lu ijọba apapọ lori ẹgbẹ Shiite, gẹgẹ o ti ṣe alaye wi pe ijọba apapọ gan an lo n ru ofin lori aṣẹ ti ile ẹjọ pa wi pe ki wọn da adari ẹgbẹ naa, El-Zakzakky silẹ.Ladọja sọ ọrọ naa nibi ipade awọn oniroyin ti o waye lọjọ Aiku ni ile rẹ to n bẹ ni agbegbe Bodija niluu Ibadan.
- Ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ní ìpínlẹ̀ Bayelsa jáwé olúbori nínú ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀
- Manchester United dáná sun Chelsea bi ẹràn àgbò iléyá
- N jẹ Arsenal ò ti dà òkùtà sí Newcastle nígbá báyìí?
- Ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ní ìpínlẹ̀ Bayelsa jáwé olúbori nínú ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀
- Jesu orí ayélujára kan rèé tó wa fun isoji ni Afirika
- Drone àti CCTV ni yóò máa ṣọ́ ọ̀pọ̀ igbó tó wà nílẹ̀ Yorùbá - Ooni








