Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Fáṣitì ìmọ̀ ẹ̀rọ FUTA ṣe ìwọ́de lórí ìkọlù àwọn ọ̀daràn lágbègbè ilé ẹ̀kọ́ wọn

Aworan awọn akẹkọọ

Ni owuro oni ọjọ kesan osu kejo ọdun 2024 ni awọn ọmọ ilé ẹkó fasiti ìmọ ẹro FUTA ni ilu Akure ṣe ìwọ́de lori ètò abo ati ikọlu awọn ọdanran sì awọn akẹkọ ni agbegbe fasiti oun.

Awon akẹkọ oun gbe igi dina popona Akure si Ilesha lati fi ìbànújẹ won lede lórí ọrọ abo ti wọn ni ko peye. igbesẹ yi lo fa idaduro awon aarinrin àjo ti osi mu ki awọn ikọ ile isẹ oloopa láti wa sì oriko oun.

Lara awon to ba BBC Yoruba sọrọ ni òru mọ́jú oni ni awọn òdaran tún ṣe ikọlù si Ilegbe awon akẹkọ ti owa ni agbegbe na ti won sì gba dukia won lọ.

Awọn akẹkọ naa sope, awon gbe igbimọ ẹṣọ alabo kalẹ sugbọn oru eni ti won ko jade ni awọn ọgara oloṣa naa tun yoju

Woni eyi tin di lemolemo, to fi mò igbakan ti awọn ole yin bọn fun akẹkọ Awọn akẹkọ na ni ọrọ naa nilo ki awọn ẹṣọ alaabo gbe igbesẹ.

Won fi ẹsùn kàn awon ọlọpa pe gbogbo ìgba ti won ba ke Si won ni won maan pẹ daun.

Kini ọnà abayọ?

Awọn akẹkọ oun ti won gbà ẹnu aare ẹgbẹ awọn akẹkọ soro ọgbẹni Olayemi Oluwasoromidayo pe fún kì awọn àjọ eleto abo paapaajulo awọn ọlọpa lati bẹrẹ ṣiṣe irede kakari gbogbo agbègbe ti awọn akẹkọ n gbe ni tosi fasiti oun bẹrẹ lati ago méfa irọlẹ.

Àjọ ọlọpa ati adari ile ẹko ọun sọrọ lórí iṣẹlẹ awọn ọdanran l'agbegbe ọun

Igbakeji komisana àjọ ọlọpa ni ipinlẹ Ondo Muhammad Rabiu to ba awọn akẹkọ ọun sọrọ ṣeleri ilẹkùn akitiyan àjọ ọlọpa lati dènà ikọlù awọn òdaran lagbegbe wọn.

Oni lati ẹni, awon iko ọlọpa ma bẹrẹ irede kakari gbogbo agbègbe naa

Alága igbimọ ton risi eto abo ni fasiti oun ọjọgbọn kolawole Adegbie ti o ṣoju oga agba ile ẹko FUTA Ọjọgbọn Adenike Oladiji pe fún àláfíà ti osi fi da awon akẹkọ lójú pe awọn adari ile ẹko naa yíò gbe igbesẹ ti o ye